Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti L'edo

She lopo awon eeyan kawo mori nipinle Edo laipe yi nigba ti ileeshe aabo ti otelemuye (DSS) foju awon gendekunrin meji kan ti won ni won ko nishe meji ju jibiti ori ayelujara, iyen Yahoo-Yahoo lo, to si je pe oruko Iyawo Aare orileede yi, Aishat Buhari ati gbakeji Aare, Ojogbon Yemi Oshinbajo ni won fi n lu awon eeyan ni jibiti owo lori ayeluajra.

Awon mejeeji ni Amos Ehis Asuelimen ti won lomo ogbon odun ni, to si tun je akekoo fasiti Ambrose Alli leka eto okoowo (Business Administration ati Kelvin Godwin Ogashi toun je omodun mejidinlogun.

Igbakeji oga agba, Galadima Byange lo foju awon odaran yi han fawon oniroyin l'Ojobo ana nipinle Edo.

A gbo pe ayederu oruko Oshinbajo ati Aishat Buhari lawon mejeeji n lo lori ikanni ayelujara ti Facebook, ti won si lawon fe maa ya awon eeyan lowo, ati pe awon ti won ba fee ran lowo lati ya lowo gbodo koko fi kaadi ipe ibanisoro ranshe, ta a si gbo pe ko din leeyan marun un ti won ti gba owo lowo won.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe awon mejeeji ko ni pe e foju bale ejo.

IKUNLE ABIYAMO O, OWO TE OMO YAHOO MOKANDINLOGBON N'IBADAN

Lojo Weside ana ni ileeshe ajo to n ri shishe owo ilu kumo-kumo, iyen Economic and Financial Crimes Commission, EFCC, eka tiluu Ibadan nipinle Oyo tun kede sita pe ko din ni mokandinlogbon lawon gendekunrin ti won ko nishe meji ju jibiti ori ayelujara towo te lo.

Agbegbe kan ti won pe ni Akoto Estate, Elebu niluu Ibadan lowo palaba won ti segi laaro kutu ana latari olobo ti won lawon kan ti fura si awon eeyan naa ta ileeshe EFCC laipe yii, ta a si gbo pe o niye ojo ti won fi topinpin won, ki won too lo ko won.

Lara awon nnkan ti a gbo pe won gba lowo won ni moto nla boginni mejo otooto, foonu olowo nla lorishirishi ati ero komputa laagbeeka, to fi mo awon ayederu iwe ti won fi n lu jibiti.

A gbo pe ajo naa ti fidi e mule pe ko nii pe tawon eeyan naa yoo fi foju bale ejo, to si shee she kawon ti won ba rii pe won ko mon on nnkankan ninu won gba idalere.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:01:36 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: