Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Idaraya

Bi ki i ba a she opelope awon eleyinju aanu kan ni, boya won ki ba ti dana sun odomobinrin arewa kan, ti won pe oruko re ni Laurenta, eni ti won loo wo oteeli lo, to si lo o ji okan lara awon amohunmaworan, iyen telifishan ti won lo n lo nibe.

Oteeli kan ti won pe ni Kevleyn, eyi to wa nipinle Delta la gbo pe Laurenta loo ji gbe, ati pe oun peluu orekunrin re kan, tiyen ti na papa bora ni won jo gbimo papo ji telifishan naa gbe.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe ose kan gbako ni Laurenta ati orekunrin re fi n gbe ni oteeli naa, latari owo ti won san sibe, ti won si n gbadun ara won daadaa.

Won ni inu baagi nla kan ti won n pe ni ''Ghana Must Go'' ni Laurenta gbe telifishan naa pamo si, asiko to si n gbe e jade ni lawon esho daa duro lati beere nnkan to wa ninu baagi naa, to si lawon eru tawon gbe debe ni.

Bi won she gba baagi naa lowo e ni tipatipa lo ba bere sii bebe pe ki won she oun jeje. Awon eleyinju aanu la gbo pe won gba won nimonran lati fa Laurenta le awon olopaa lowo.

A ti e gbo pe orekunrin Laurenta naa ti ji asho inura, agboorun (umbrella) ati kokoro to je ti oteeli naa salo peluu etanje wi pe oun fee lo ran nnkan nita. Leyin wakati keta la gbo pe Laurenta naa gbe telifishan, sugbon ti ashiri re pada tu sita.

Bee lawon kan ti e tun so pe Laurenta ti ji milionu kan naira din legberun lona igba (800,000) naira lowo okunrin kan ti won jo sun laipe yi.

WON JI IYAALE ILE GBE NIBI TO TI N ShE ERE IDARAYA

Bi e she n ka iroyin yi lowo ni won ko tii ri iyaale ile kan ti won pe oruko re ni Gbemisola Alabi, eni ti won loo jade nile laaro ojo Aiku tii she ijeta lati she ere idaraya (exercise) die, to si je pe latigba to ti jade ni ko ti i rii titi dasiko ti a ko iroyin yi tan.

Gbajugbaja oniroyin kan niluu Ekoo, Soni Irabor lo gbe iroyin naa sita lori ikanni ayelujara ti Facebook re lati fi to gbogbo agbaye leti, bo ya o she e she ki won ba won ri i, tabi mo ibi to wa.

Ohun ta a gbo ni pe opopona Monastery nitosi Novare mall – shoprite to wa lagbegbe Shangotedo niluu Ajah ni Gbemisola ti looshe ere idaraya naa.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:10:00 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: