Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunkun Yinbon Pa Akekoo, Lasiko To Pari Idanwon Asekagb

She loro di boolo o yago lojo Aiku, Sande ana nigba ti won lawon Hausa ati Yoruba koju ija sira won, ti won bere sii she ara won bashubashu, ko da, ti opo dukia shofo danu, tawon eeyan si farapa yannayanna.

Agbegbe oja nla kan to wa ni Oke-Odo nipinle Eko, loju ona Ekoo si Abeokuta nija nla naa ti waye, to si je pe fun bi i wakati merin lagbegbe naa fi pa loolo.

Die re e lara awon foto ishele naa.

O MA SHE O, AWON OMO EGBE OKUNKUN YINBON PA AKEKOO, LASIKO TO PARI IDANWO ASHEKAGBA

Bo tile je pe a ko tii le fidi ishele naa mule lori idi ti won lawon omo egbe okunkun kan she yinbon pa akekoo kan ti won ni idanwo ashekagba e lo sheshe pari, ki won too ran an nishe de toru-toru.

A gbo pe ile eko fasiti ti kan nipinle Cross River, iyen Cross River University of Technology ni akekoo ti ko ti i mo oruko e dasiko yi n lo. Won ni bo she n jade ninu yara idanwo ni nnkan bi aago mokanla aabo aaro onii ni won loo pade e peluu ibon.

Won i bi won she soro die ni won yinbon mon on nikun, to si shubu lule loju ese, tawon yen naa si na papa bora.

Iwadii shi n lo lowo lori awon to pa odomokunrin naa. 
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:12:51 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: