Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lorun Pa Nile Itura

Bo tile je pe a ko ti mo nnkan to shele laarin baba ati omo re, omodun meta, to mu ki baba naa daa dubule, to si ko patie bo o bii maalu to gbojo iku.

Ilu Ogbomosho nipinle Oyo nishele naa ti waye lojo Satide to koja yi.

A gbo pe baba naa ati iyawo to sheshe fe ni won jo dawo bo omodun meta naa, to si je pe awon eleyinju aanu ni won gba omo naa sile.

Foto omo naa le n wo yii.

WON FUN IYAALE ILE LORUN PA NILE ITURA

Bo tile je pe iwadii awon olopaa shi n lo lowo titi dasiko yi, sugbon sibe, iyalenu loro iku iyaale ile kan ti won pe oruko re ni Maureen Ewuru shi n je fun opo awon eeyan kaakiri agbaye, paapaa awon ara agbegbe D'Line nipinle Port Harcourt.

Ohun ti a gbo ni pe Maureen ti won lo n tomo kan shosho lowo ni okunrin gbe lo si ile itura lati jo jegbadun ara won, paapaa bi won tun she so pe obinrin naa n shishe ashewo lati fi toju ara re ati omo kan shosho to bi sile.

Bo tile je pe orishirishi iroyin lo n kaakiri ori ayelujara nipa iku Maureen ti a ko si tii le fidi otito mule, sibe Iwe Irohin Yoruba gbo pe ale ijeta ni loun ati okunrin kan tenikeni ko mo dasiko yi jo lo si ile igbafe naa, ti won si wo yara lati gbadun ara won.

Won ni bi won she ba ara won sun tan, ti won gbadun ara won debi to ni apeere ni won so pe aawo be sile laarin won, to si mu ki okunrin naa ki asho mole, to si fun un lorun titi to fi ku.

She ni okunrin naa tete ba ese re soro nigba to rii pe oun ti pa a danu ki ashiri ma baa tu sita. A gbo pe nigba tawon to ni ile itura naa rii pe enikeni ko tii jade ninu yara naa laaro ana, lo mu ki won fi tipa wole, to si je pe oku Maureen ni won ba lori beedi.

Loju ese ni won ti figbe ta sita, ko too di pe won sare loo foro naa to awon olopaa leti koro naa ma ba a yiwo mo won lowo.

Ohun tawon eeyan n so bayii ni pe lara iwadii to ye kawon olopaa she ni pe ki won ye gbogbo ipe to wole sori foonu Maureen wo lati mo eni to shishe naa.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:14:05 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: