Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·It's Haram To Aid, Promote Or Participate In The Oodua Nation Agitation
·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya

Titi dasiko ta a shakojopo iroyin yi tan niku odomokunrin eni odun metadinlogbon kan, Ismaila Ogunshola shi n je kayeefi fawon eeyan, paapaa awon araalu Owode Egba, nijoba ibile Obafemi/Owode, ipinle Ogun lori bi won she so pe ojo idun Ileya to koja yi ni won pe e, to si je pe nigba ti won maa pada ri, oku e ni won ri.

Ki i she pe bi Ismaila ti won loo fi odun meje gbako ko ishe telo she ku lo n je kayeefi fun gbogbo eeyan, paapaa awon ara agbegbe Owode, bi ko she bi won she ba oku e lori igi Mango, ti won tun de e lapa ati ese, ti won si tun sokun mon on lorun gan an lo n je edun okan fawon araalu, paapaa awon ebi re.

Gege bi a she gbo, won ni odun meji seyin ni won so pe Ismaila gba aaye lodo oga re to ko o nishe telo, iyen Ogbeni Sulaimon Abisoye niluu Owode Egba lati fi wa owo ti yoo fi she firidoomu, idi ni yii ti won loo fi wa ibi to ti n shishe logba osin (poultry) kan to wa lagbegbe Malaaka, opopona Adejoin, Owode kan ni nnkan bi oshu mesan seyin.

Won ni latigba ti Ismaila ti de ileeshe nnkan osin naa ni kii tii gba owo oshu re pe, nitori ti won so pe gbogbo igba ni oga won to ni ibe kii fun won lowo ni gbogbo igba, ta a si gbo pe o le lowo oshu meji ti oga naa je Ismaila, ko too ku.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe ose meji seyin ni Ismaila pe ore re kan, to maa n foro lo, to si loun la ala kan pe won fee ya oun ni were ojiji, nitori naa, oun yoo kuro l'ogba nnkan osin toun ti n shishe, paapaa bi iwa oga won tun she ri, ati bi kii she e fun won lowo oshu nigba gbogbo.

Idi ni yii ti won loo fi so pe oun yoo so fun oga oun naa pe ara baba oun ko ya, nitori naa oun ko nii wa fawon asiko kan lati toju baba oun, ati pe oun nilo owo lati fi toju baba oun, ti won ni oga naa so fun un pe ko buru.

Ojo Sande ose to koja yi, to je ojo ti gbogbo awon Musulumi lagbaaye n shayeye odun Ileya, iyen ni nnkan bi aago mejo ku isheju meloo kan la gbo pe oga Ismaila, Ogbeni Shegun Adekoya pe e lori foonu pe ko wa a gba owo e to ku lowo oun, ati pe o lawon ishe kan ti yoo ba oun she.

Ohun ta a gbo ni pe ibi ti Ismaila ti n ran asho to ti gba lowo ni oga re naa ti pe e, ti won ni loju ese lo ti fi asho naa sile, lati lo. Bo she fee jade la gbo pe o so fun baba, iya, egbon re kan, ati ore re ti won ni won jo sunmo ara won pe oga oun pe oun pe koun wa a gba owo kan to je oun, to si pa gbogbo asho to n ran lowo ti, lero wi pe oun ko ni pe e de.

Iyalenu lo je pe titi tile ojo naa fi shu ni won ko fi ri Ismaila ko pada wa sile, to si je pe gbogbo bi won she n pe foonu e ni ko gbe e, igba to ya ni won so pe foonu naa ko lo mo, eyi ni won lo mu ifura dani, nitori ti won so pe Ismaila kii rin irin kurin, kii si i foro e bo fenikeni to ba sunmo on.

Aaro ojo keji tii she Monde ose to koja yi la gbo pe mama Ismaila gbera lati lo sibi ti Ismaila ti n sise, ti won si so pe won ba ore re ti won jo n sise, iyen Sulaimon, toun funra re si so pe looto ni Ismaila wa sinu ogba naa, ko da tawon tun jo dapaara ko too lo sun sinu yara, sugbon iyalenu lo je pe oun ko ri mo nigba to to asiko kan, toun si ro pe boya o ti fo fensi jade sita lai je koun mo.

Igba ti won ni won ko ri Ismaila ni won ni egbon re, Wasiu Ogunshola atawon kan tun gbera lati lo sibe lati lo mo nnkan to n shele, to si je pe nigba ti won maa de be, won ko ri Ismaila, idi ni yii ti won fi gba teshan olopaa Owode lo lati loo foro naa to won leti, ti won si ni iyalenu lo je pe won ti gba oga Ismaila nibe, to ti n ko oro sile.

Loju ese la gbo pe won ti ti oga Ismaila molee ati Sulaimon mole, tawon mejeeji si so pe awon ko mo nnkankan nipa, ti won si lawon olopaa bere igbese lati shewadi. Sugbon iyalenu ni won loo je pe she lawon olopaa Owode tun gbabodi, ti won si fe maa lo ogbon arekereke lati pana oro naa mole, paapaa ti won tun n fesun kan awon molebi Ismaila pe awon ni won gbe omo won pamo lati fi gba owo lowo oga Ismaila, iyen Ogbeni.

Idi ni yii ti won lawon molebi Ismaila fi gba olu ileeshe olopaa to wa ni Eleweran lo lati loo foro naa to won leti lojo Weside, tawon yen si so pe awon bere igbese lojo Toside. Osan ojo Toside la gbo pe awon olopaa lati Eleweran gba ilu Owode lo lati loo shewadi, ti won si wa gbogbo inu ogba osin (poultry) naa ti won loo fi die le ni eeka marun (5 acres) ko too di pe won kofiri enikan lori igi Mango.

She loro di boolo o yago nigba ti eni ti won ba lori igi naa je oku Ismaila. Iyalenu ni won loo je pe won ti sho o lowo ati ese, ko da, ti won tun ba okun lorun e, to ti n jera peluu idin lara. Loju ese ni won ti so oku e kale.

Nigba to n soro, egbon Ismaila, Ogbeni Wasiu Mukaila Ogunshola ''Mi o si nile lojo odun Ileya yen, ojo keji odun ni won pe mi lori foonu pe won ko ri, mo ki mama e lo sibi to ti n shishe, tori pe omo Baba mi ni, iya otoooto lo bi wa. Igba ti won de be, won lawon kan geeti, won ko ri enikankan. Ko pe ni won tun pe mi pe awon ti ri enikan nibe to so pe loooto ni Ismaila wa sinu ogba, sugbon ti won ko mo bo she jade tori pe won maa n ti geeti ogba yen ni.

''Igba ti mo de ni mo gba nomba oga Ismaila, ti mo si pe e lori foonu pe ko je ka pade ni teshan olopaa Owode lati wa Ismaila, to si loun naa ko si nile, nigba ta a fi maa pade, teshan olopaa la ti ba a, to n bawon olopaa soro pe a paro mo oun lati fi aburo wa gba owo lowo oga e. Idi ni yii ta a fi lo si Eleweran lati lo fi to won leti.

''Iyalenu lo je fun wa nigba ti a ri oku aburo mi lori igi Mango, to si loun ko mo nnkankan nipa iku e, ati pe won ni kii seni to le wonu ogba naa, tori pe she ni won she fensi e ga ju nnkan teeyan le pon lai lo akaba. Mo fe kawon omo Naijiria gba wa lo je ka fi to eyin oniroyin leti o.''

Ore Ismaila to sunmo, Obasan Temitope so pe ''Ose meji seyin ni Ismaila pe mi, to so pe oun la ala pe won fee ya oun ni were. O ma n soro e fun mi daadaa, emi naa si ma n so temi fun. O loun fee kuro nibe pe oun fee gba owo oun koun too kuro nibe. Ojo Sande to lo lohun, iyen ojo kerin oshu yi lo so pe oga oun so pe ere ori igi ni oun fee she lati so pe ara baba e ko ya, nitori toun mo pe iro ni Ismaila n so.

''Aago mejo koja isheju meedogun lo pe mi lojo odun Ileya pe oga oun pe oun pe koun wa gba owo, o ma n so pe oga oun ko mo riri nnkan toun n ba a she. Oro naa ko ye mi rara. Kawon omo Naijiria ba wa da si.''

Irole ojo Fraide la gbo pe won pada sin oku Ismaila. Alukoro ileeshe olopaa ipinle Ogun, Abimbola Oyeyemi fidi e mule, to si lawon ti mu awon min in lori ishele.

Laaro oni Monde la tun gbo pe won ti fi oga Ismaila sile lahamo, bee ni Sulaimon shi wa lahamo ni tie, tori ti won loun ni afurasi bayii, sugbon ti iwadii shi n lo lowo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:15:37 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: