Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijiria Pelu Awon Omo Re To N Sun Segbe Opopona Niluu Oyinbo

Bi e she n ka iroyin yi, awon omo Naijiria ti ko din ni metalelogun lo ti wa lorile-ede yi bayii latari esun gbigbe kokeeni ti won fi kan won lorile-ede Saudi Arabia.

Adeniyi Adebayo Zikri, Tunde Ibrahim, Jimoh Idhola Lawal, Lolo Babatunde, Sulaiman Tunde, Idris Adewunmi Adepoju, Abdul-Raimi Awela Ajibola, Yusuf Makeen Ajiboye, Adam Idris Abubakar, Saka Zakaria, Biola Lawal, Isa Abubakar Adam, Ibrahim Chiroma, Hafis Amosu ati Aliu Muhammad.

Awon to ku ni: Funmilayo Omoyemi Bishi, Mistura Yekini, Amina Ajoke Alobi, Kuburat Ibrahim, Alaja Olufunke Alalaoe Abdulqadir, Fawsat Balogun Alabi, Aisha Muhammad Amira ati Adebayo Zakariya.

Be o ba gbagbe, lai pe yi ni won dajo fun omo Naijiria kan, Kudirat Afolabi lori esun gbigbe kokeeni, to si tun je pe ko pe lowo tun te Saheed Shobade peluu kokeeni ti ko din ni iwon egberun kan (1,183) giraamu niluu Jeddah.

Awon omo Najiria metalelogun yi la gbo pe aarin odun 2016 si odun 2017 lowo te won ni papako ofurufu King Abdul-Aziz to wa ni Jeddah ati papako ofurufu Omoba Muhammad bin Abdu- Aziz to wa ni Madinah.

E WO AREWA IYAALE ILE OMO NAIJIRIA PELUU AWON OMO RE TO N SUN SEGBE OPOPONA NILUU OYINBO

Fonran kan to n lo kaakiri ori ayelujara bayii, ko da a, tawon eeyan shi n soro lori e dasiko yi ni ti iyaale ile kan toun atawon omo re n sun segbe opopona, paapaa ni papako ofurufu Naijiria to wa niluu Berlin, Germany.

Ohun ta a gbo ni pe ilu Munich ni obinrin naa ti wa ni Berlin lati gba iwe irinna e tuntun, eyi ti ojo ti lo lori e.

Won ni nigba ti won ko tete da won lohun, ti ko si sibi ti won fe e lo, lo mu ki won maa sun kaakiri egbe opopona.

Eyi lohun tawon eeyan n so nipa e.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:19:50 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: