Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.
Onka Ni Oju-Agbo
Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi
E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi
Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran
E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:
Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.
Ona Igba Wole Si Agbo
Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.
Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Terin N'isoosi
Oro buruku toun terin, nigba ti won ka Ajihinrere kan ti won pe oruko re ni Akinjide Durojaiye mo ibi to ti n ji foonu lasiko to n waasu ihinrere Jesu pe kawon eeyan yi pada kuro ninu eshe won.
"E she mi jeje, ishe eshu ni, Emi mimo lo ran mi nishe" loro ebe to n tenu Durojaiye jade lasiko towo palaba e segi naa, pelu foonu olowo nla meji otooto to ji gbe lagbegbe Dugbe niluu Ibadan, ipinle Oyo.
Gege bi a she gbo, opin ose to koja yi la gbo pe Durojaiye ti won ni ilu Ilare-Ijesha to wa nipinle Oshun lo ti n shishe ni shooshi kan ti won pe ni Dominion Assembly gba ilu Ibadan lo, to si lo n waasu ihinrere Jesu.
Won ni bi Durojaie, omodun mokandinlaadota naa she de agbegbe Dugbe lojo naa, ni won loo bere sii waasu loirshirishi, tawon eeyan si n wo o bo she n she. Shadede ni won loo wo shoobu kan ti won pe ni Femi Johnson.
Bo she de be la gbo pe o fogbon yo foonu meji ninu awon foonu ti won n ta, ti won si lowo awon foonu naa ko din ni egberun lona aadorin (N70,000) naira, ti ko si mo pe awon eeyan n sho oun.
Iwe Irohin Yoruba gbo pe bo she ji foonu naa lo ba ese re soro, ti won si lee mu. Nibi ti won ti n luu lo ti bere sii ka bi aje boroboro pe ara omo oun to je omodun meje ni ko ya, eyi lo je koun wa ona lati ri owo ji.
Igbe ti won ni okunrin naa n ke lo mu kawon eleyinju aanu baa bebe, ti won si pada fii sile, pe ko maa lo layo ati alaafia.
ORO BURUKU TOUN TERIN: ADIGUNJALE TO LO FO SHOOSHI TUN KO LETA PE KI WON GBADURA F'OUN
She lawon to ri leta ti adigunjale kan to lo fo shooshi lale ojo Aiku, Sande to koja yi tun bere sii wo tiyanu-tiyanu, nigba to tun bere sii bebe pe ki won gbadura foun nitori pe nnkan toun ro ko loun ba pade.
Gege bi a she gbo, adigunjale naa so pe okan lara awon omo shooshi naa lo fun oun lowo pe obitibiti owo wa ninu shooshi naa to wa niluu Engineer, ipinle Nyandarua County, orileede Uganda, to si mu koun loo yee wo lale.
Ole naa so pe nigba toun jawo shooshi naa, toun tu gbogbo inu e finifini, lo je iyalenu foun pe ko si nnkan to jo owo nibe, idi ni yii, toun fi fibanuje jade sita.
Ninu leta naa lo ti so pe eri okan ti ko je koun gbadun lo mu koun ko leta pe ki won gbadura foun, ki won si dariji oun fun nnkan toun she naa.
Pentecostal Evangelistic Fellowship of Africa (PEFA) loruko shooshi naa.
Posted By
Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:24:21 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.