Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
 
 
Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo Baba Ti Omo Rẹ̀ Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa

Baba Ti Omo Rẹ̀ Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa

Arakunrin omo odun metalelogun, ti o n je Basty Abass, ti wa ni atimole fun ogun odun ni Nkwanta south ti Oti region, ni orile-ede Ghana, ti a gbo pe baba re ti mole nitori o ni warapa.

A gbo lati oju feresi nikan ni Abass ti ma n fi oju kan ina, o ma n se igbonse,o ma n to, o ma n jeun, o si ma n sun sinu yara naa, ti won fi agadagodo to tobi ti pa ki o ba ma le jade.

Baba re, Mallam Abass Abdulai, so fun MyJoyOnline, idi ti o se ti omo naa pa, o ni omo naa ni warapa, ko le da ronu funra re, ti e ba si salaye bi o se le toju ara re fun, ko le ye.

Mallam Abass ni omo oun ma n yagbe kaakiri ile, pe oun si ro pe nnkan to da ju lati se ni ki oun ti i pa mo yara fun ogun odun. O ni nigba ti o wa ni omo osu mejidinlogun ni iya re ti gbe sile ti ko si boju weyin lati igba naa. Iya iya re lo to ti oun naa ti je olorun nipe.

iyawo akorin Timi Dakolo, Busola Dakolo ti shalaye pe Pasitọ̀ kan fi ipa ba oun lopọ̀

Iyawo akorin Timi Dakolo, Busola Dakolo ti salaye pe Pasito Biodun Fatoyinbo ti COZA fi ipa ba oun lo po ni opolopo igba nigba ti oun wa ni omo odun metadinlogun.

Busola ni, oun o ti mo okunrin nigba ti pasito naa fi ipa ba oun lopo ni omo odun matadinlogun. O ni leyin ti Pasito naa fi ipa ba oun lo po ninu palo mama oun, Pasito Biodun naa so fun oun pe o ye ki inu oun maa dun nitori eniyan olorun lo gba ibale oun.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:25:54 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo:
Yoruba Greetings, (Middle) Names In Yoruba Language With Titles Of Obas (Kings)


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo

"Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: