Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.
Onka Ni Oju-Agbo
Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi
E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi
Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran
E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:
Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.
Ona Igba Wole Si Agbo
Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.
Lojoru Weside to koja yi ni ese ko gbero nile ejo giga kan to fikale sagbegbe Ikoyi niluu Ekoo lati wo oju baba agba kan to je Purofeso ni fasiti Obafemi Awolowo to wa n'Ile-Ife, eni ti won loo lu jibiti owo oni aimoye milionu naira.
A gbo pe ajo kan ti Purofeso naa, Charles Jide-Oni da sile, eyi ti won lo fi n gba owo lona aito lowo awon onibaara re ki asiri re too pada tu.
Lara awon ti Charles lu ni jibiti la gbo pe won gbe ejo re lo siwaju awon ajo EFCC, ko too di pe awon yen bere ise iwadii won, ti won si ri i pe loooto ni, paapaa nigba ti won tun ni ko le dahun awon ibeere kookan ti won n bii.
Yato si Jide-Oni, a gbo pe awon ajo EFCC naa tun foju awon min in naa bale ejo latari esun jibiti ti won fi kan won niwaju Onidajo Nicholas Oweibo tile ejo ekun ile Yoruba.
Awon min in ti won tun foju won bale ejo naa peluu ni; Olaleye Kolapo, Madukife Ifeanyi Azuka, Fatanmi Yinka Sunday, Adebayo Bolaji Adeyinka, Adeleke Peter ati Adebowale Fadairo.
Awon yooku ni; Oyewunmi Tolulope Michael, Bello Ayoade Jalal Arikalam, Owolabi Toheeb Tolulope, Abdullahi Abdulazeez Oluwatobi, Temitope Fatolu ati Adesina Adewale.
O MA SHE O, AWON OMO EGBE OKUNKUN YINBON PA AKEKOO, LASIKO TO PARI IDANWO ASHEKAGBA
Bo tile je pe a ko tii le fidi ishele naa mule lori idi ti won lawon omo egbe okunkun kan she yinbon pa akekoo kan ti won ni idanwo ashekagba e lo sheshe pari, ki won too ran an nishe de toru-toru.
A gbo pe ile eko fasiti ti kan nipinle Cross River, iyen Cross River University of Technology ni akekoo ti ko ti i mo oruko e dasiko yi n lo. Won ni bo she n jade ninu yara idanwo ni nnkan bi aago mokanla aabo aaro onii ni won loo pade e peluu ibon.
Won i bi won she soro die ni won yinbon mon on nikun, to si shubu lule loju ese, tawon yen naa si na papa bora.
Iwadii shi n lo lowo lori awon to pa odomokunrin naa.
E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti L'edo
E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti L'edo
She lopo awon eeyan kawo mori nipinle Edo laipe yi nigba ti ileeshe aabo ti otelemuye (DSS) foju awon gendekunrin meji kan ti won ni won ko nishe meji ju jibiti ori ayelujara, iyen Yahoo-Yahoo lo, to si je pe oruko Iyawo Aare orileede yi, Aishat Buhari ati gbakeji Aare, Ojogbon Yemi Oshinbajo ni won fi n lu awon eeyan ni jibiti owo lori ayeluajra.
Awon mejeeji ni Amos Ehis Asuelimen ti won lomo ogbon odun ni, to si tun je akekoo fasiti Ambrose Alli leka eto okoowo (Business Administration ati Kelvin Godwin Ogashi toun je omodun mejidinlogun.
Igbakeji oga agba, Galadima Byange lo foju awon odaran yi han fawon oniroyin l'Ojobo ana nipinle Edo.
A gbo pe ayederu oruko Oshinbajo ati Aishat Buhari lawon mejeeji n lo lori ikanni ayelujara ti Facebook, ti won si lawon fe maa ya awon eeyan lowo, ati pe awon ti won ba fee ran lowo lati ya lowo gbodo koko fi kaadi ipe ibanisoro ranshe, ta a si gbo pe ko din leeyan marun un ti won ti gba owo lowo won.
Iwe Irohin Yoruba gbo pe awon mejeeji ko ni pe e foju bale ejo.
Posted By
Ifiranse Eleyi Je Thursday, September 12 @ 06:37:10 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.