Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L'Abuja

Iroyin ti ko dun mo enikeni ninu bawon ajinigbe se ji okan lara awon osise telifisan African Independent Tlelevision, AIT, iyen Abayomi Adigun, ti won si pa a danu.

Eka ileese naa to wa niluu Ilorin la gbo pe won ti gbe Abayomi kuro laipe yi, lati loo darpo mo awon iko to n seto Kakaaki niluu Abuja.

Ale ojo Sande to koja yi la gbo pe Abayomi gbera nile e lati lo sibise, to si wo oko lagbegbe Kubwa-Aya, nibi to ti ko sowo awon ajinigbe ti won pe ni "One Chance" naa.

Nigba ti won ko tete ri Abayomi lati wo ise lale ojo naa la gbo pe won bere sii pe aago e, sugbon ti enikeni ko gbe e.

Iyalenu lo si je pe nigba ti won maa pada ri Abayomi, oku e ni won ba legbee titi, iyen lopopona Kubwa, ti won ti gun un welewele.

A gbo pe iwadii awon olopaa to bere lori awon to seku pa okunrin naa.
Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma Se O, Obirin Ja Ibale Omodun Mejo L'ondo

Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma Se O, Obirin Ja Ibale Omodun Mejo L'ondo

Gbogbo ilu Makurdi, nipinle Benue lo fee le daru laaro oni nigba ti won ba oku omoge arewa kan ta a ko tii mo oruko re dasiko ti a shakojopo iroyin yi tan ninu igbo kan to wa niwaju shooshi ti won pe ni Grace Tower.

Ohun ta a gbo ni pe awon gendekunrin kan ni won fipa wo odomobinrin naa, ti won si ko ibasun fun leyo-kookan, titi to fi jade laye.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe she ni won ja omobinrin naa sihoho omolaubi, ti won si fi asho dii lenu pa, ki won too bere sii fi kinni abe won dana si omoge arewa naa labe.

Igba ti won ni agbara omobinrin yi ko fee gbe mo, leyin to ti bebe titi, sugbon ti won ko da a lohun, la gbo pe o gba ekuru je lowo ebora.

Bo tile je pe gbogbo akitiyan lati ba agbenuso fawon olopaa ipinle naa soro titi dasiko ta a shakojopo iroyin yi tan lo ja si pabo, sugbon ti a gbo pe ishe iwadii shi n lo lowo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, September 12 @ 06:46:59 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: