Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.
Onka Ni Oju-Agbo
Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi
E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi
Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran
E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:
Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.
Ona Igba Wole Si Agbo
Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.
O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L'Abuja
Iroyin ti ko dun mo enikeni ninu bawon ajinigbe se ji okan lara awon osise telifisan African Independent Tlelevision, AIT, iyen Abayomi Adigun, ti won si pa a danu.
Eka ileese naa to wa niluu Ilorin la gbo pe won ti gbe Abayomi kuro laipe yi, lati loo darpo mo awon iko to n seto Kakaaki niluu Abuja.
Ale ojo Sande to koja yi la gbo pe Abayomi gbera nile e lati lo sibise, to si wo oko lagbegbe Kubwa-Aya, nibi to ti ko sowo awon ajinigbe ti won pe ni "One Chance" naa.
Nigba ti won ko tete ri Abayomi lati wo ise lale ojo naa la gbo pe won bere sii pe aago e, sugbon ti enikeni ko gbe e.
Iyalenu lo si je pe nigba ti won maa pada ri Abayomi, oku e ni won ba legbee titi, iyen lopopona Kubwa, ti won ti gun un welewele.
A gbo pe iwadii awon olopaa to bere lori awon to seku pa okunrin naa. Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma Se O, Obirin Ja Ibale Omodun Mejo L'ondo
Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma Se O, Obirin Ja Ibale Omodun Mejo L'ondo
Gbogbo ilu Makurdi, nipinle Benue lo fee le daru laaro oni nigba ti won ba oku omoge arewa kan ta a ko tii mo oruko re dasiko ti a shakojopo iroyin yi tan ninu igbo kan to wa niwaju shooshi ti won pe ni Grace Tower.
Ohun ta a gbo ni pe awon gendekunrin kan ni won fipa wo odomobinrin naa, ti won si ko ibasun fun leyo-kookan, titi to fi jade laye.
Iwe Irohin Yoruba gbo pe she ni won ja omobinrin naa sihoho omolaubi, ti won si fi asho dii lenu pa, ki won too bere sii fi kinni abe won dana si omoge arewa naa labe.
Igba ti won ni agbara omobinrin yi ko fee gbe mo, leyin to ti bebe titi, sugbon ti won ko da a lohun, la gbo pe o gba ekuru je lowo ebora.
Bo tile je pe gbogbo akitiyan lati ba agbenuso fawon olopaa ipinle naa soro titi dasiko ta a shakojopo iroyin yi tan lo ja si pabo, sugbon ti a gbo pe ishe iwadii shi n lo lowo.
Posted By
Ifiranse Eleyi Je Thursday, September 12 @ 06:46:59 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.