Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
 
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa Da Ayey Ojoobi E Ru - Bee Loun Naa Ti Salo

Lana-an gan-an ni omokuinrin kan ti oruko e n je Idris Okuneye, eni tawon eeyan tun mo si Bobrsiky pe eni odun mejidinlogon, sugbon dipo ayajo ayeye ohun, nise lawon olopaa kolu ileetura to fe lo, ti oro si di bo o lo o yago.

Oga gba nileese ijoba to n ri si Asa ati isese, Otunba Olusegun Runsewe ni okunrin to n se bii obinrin yii, Bobrisky yaju si, ki oloju si too se e, nise ni nnkan daru mo on lowo, toro si di bi bami-in mo on lowo bayii.

Ohun ta a gbo ni pe, lana-an gan-an ni Bobrisky loun yoo pate ariya nla, nibi to ti fe ko awon tie jo lati sayeye ojoobi, sugbon bo ti se n pete ariya yii lowo, bee lawon olopaa n so, bo si ti se ku dede ki won bere inawo ohun lawon agbofinro yade, bi won se le awon alabase e danu niyen o, ti won ni Bobrisky paapaa na papa bora, tawon eeyan ko si mo ibi to gba lo.

Se ko too di asiko yii lokunrin yii ti fenuko, nibi to ti n hale wi pe ko si ohun kan bayii ti Otunba Olusegun Runsewe le se fun oun, nitori pe awon to ju u lo daadaa lenu ise ijoba loun n ba tayo, ti oro ba di pe eeyan n mo eeyan lawujo.

Ninu iwe iroyin oloyinbo kan, iyen Vanguard ni Otunba Runsewe ti bu enu ate lu iwa ati isesi Bobrisky. O ni, asiko ti to bayii fun ijoba lati tako iwa idojutini ti Bobrisky n ko ba awujo wa.

O ni, "Bobrisky ti e n wo yen, idojuti nla gbaa lo je fun orile-ede wa. Ohun ti awon eeyan mo on mo tele ni pe, awon ipara gbigbona tawon eeyan fi n bora lo koko fi bere, nigba to ya lo di pe, oun naa wa ogbon da si aya e, ti oun naa deni to ni omu, bee lo tun yo idi bombo bii obinrin, to n wa fi osi se ayo kiri.
"Ti Bobrisky ba n se iru iwa idojuti yii lawujo, to fi n pawo, bawo la se le ba awon odo orile-ede yii soro lati ma se tele irufe iwa bee.? Loooto ni Bobrisky ni eto, sugbon iriu eto yii ki i se ohun to ba oju mu lawujo Nigeria.

"Ki i se oun nikan lo n hu iru wa yii, iru e po daadaa, sugbon ki i se orile-ede yii ni won wa, kaakiri lawon orile-ede mi-in niru won wa. Ti a ba si ko, ti a ko gbe igbese to nipon lori oro Bobrisky, ko sigba ti ko ni ko awon eeyan kan jo, ti won a maa je iru aye ijekuje yii kiri, eyi to see se ko gbile ju bi a se lero lo.

"Ibanuje nla ni abajde iru iwa idojuti yii yoo si je, abi nigba ti awon obi ba n pokunso, ti won n gbe majele je nigba ti omo ti won fi gbogbo ojo aye toju ba n se bii Bobrisky, ti okunrin n se bii obinrin kaakiri.

"Ohun to wa nile yii, ki i se ere tabi awada, ohun aburu gbaa ni Bobrisky fe bere lorile-ede yii, bee la gbodo gbogun ti i, ko too dohun ti apa ko ni i ka mo, ki a le ni ojo ola to dara.

"Ise ti mo gba ni, lati mojuto igbelaruge asa wa ati ise omoluabi lorile-ede yii. Bee ni yoo je ohun to bu ni ku, ti mo ba dake lai fohun si osi ti okunrin yii n se, to so pe oun n yo kiri. Ati pe ta o ba tete gbe igbese, ko sigba ti awon omokunrin naa ko ni i maa gbe igba asewo legbee titi.

"Laipe yii ni omo orile-ede yii kan; gbajumo nla leni ti mo n yii, o sabewo si omo e niluu oyinbo, iyanu nla lo je fun un nigba to ri i pe ibasepo okunrin si okunrin lomo oun n se niluu oyinbo. Isele to ri yii ba a lojiji, lojuese lasian kolu u, ori keke ni won gbe e si pada si Nigeria nibi.

"Gege bi ipo mi lorile-ede yii, awon eri kan wa daadaa ti mo ni, eyi to fihan wi pe awon omo kekeeke metaleIogun kan ti wa, to je pe nise ni won n se bii Bobrisky, eyi bani ninu je pupo, bee la setan lati fopin siru awon iwa odaran yii."

Bi Otunba Olusegun Runsewe ti soro yii tan ni Bobrisky naa da a lohun, ohun to si so ree; "Mo gbo pe enikan to wa ninu ijoba n so nipa mi, e ba mi so fun un daadaa wi pe mo n duro de o, o maa too ye e wi pe, awon to ju u lo daadaa ni mo maa n ba se lagbo ijoba. Ki i se iru oun yen, o kere. O jo pe eni yen gan-an ko mo ohun to ku mo, pelu gbogbo ohun to n sele ni Nigeria yii, oro emi Bobrisky lo wa ku fun un lati te lewo bii igba, ko si wahala o, mo tun fi n loruko si i ni."
Te o ba gbagbe, lana-an ode yii ni Bobrisky di eni odun mejidinlogbon, ariwo to si n pa ni pe, ana Satide ojo Abameta yen, ilu Eko maa mi titi, nise loun yoo fi ayeye nla ti oun fe se mi Eko titi.

Bo tile je pe ileri nla ti Bobrisky se niyen o, sugbon nise lawon olopaa ya lu ibi to ti fe se inawo e, ti won si le kaluku danu, bee ni won loun paapaa fese fe e.

Lojuese ti isele ohun ti waye lawon eeyan e ti so pe nise lokunrin naa fenu ko, won ni Otunba Runsewe ti o gbe enu e ni igbekugbe si yen gan-an lo jewo ara e han an. Bee la gbo pe, pelu igbese yii, o see se ki opin deba gbogbo iwa ti okunrin to n se bii obinrin yii n hu kaakiri ilu.

Agbenuso fun ileese olopaa, Bala Elkana, ti soro o, alaye to si se nipa bi won se gbe ibi ayeye Bobrisky tipa ni pe, olobo kan lo ta awon wi pe, o see se ki wahala be sile nibi ti won ti fe se ayeye ohun, ati pe ileese olopaa ko nivi faaye gba ohunkohun to le koba alaafia ilu.

Ile igbafe kan ti won n pe ni Pearls Gardens ni Lekki Phase 1 ni iba ti waye lana-an, nigba ti omi-in iba tun waye ni Paradise Boat Club, ni Victoria Island loni-in.

O MA SHE O, OBINRIN JA IBALE OMODUN MEJO L'ONDO

Titi dasiko ti e n ka iroyin yi lawon olopaa ipinle Ondo shi n wa obinrin kan ti won fesun kan pe o fipa fi owo e ja ibale omodun mejo kan niluu Irele, ipinle naa.

Bo tile je pe iroyin to lo kaakiri igboro tele ni pe okunrin kan tenikeni ko mo fipa ba omo naa sun mo inu shoobu, to si salo, sugbon iya omo naa ti wa a je ko di mimo bayii pe kii she okunrin lo ja ibale omo oun, bi ko she obinrin.

Obinrin naa lo shalaye boro she je fun okan lara awon oniroyin to ba soro lori foonu, to si ni awon olopaa ti bere iwadii lati mu eni naa, tori pe o ti na papa bora.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, September 12 @ 07:00:36 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: