Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi

O fere je pe ko si kinni kan ti awon oloselu Naijiria ko ni i fi owo ibaje kan. Eyi to si buru to je yoo pada waa kan gbogbo eeyan ile yii naa ni ti etoidajo. Won ti so awon adajo wa di nnkan mi-in, iba die, iyen to ba tilewa rara, lo ku to n dajo ododo.

Bee ni orile-ede ti ko ba ti si idajo ododo, ibe yoo segbe, ki Olorun ma je ki Naijiria segbe ni. Ohun to ba foju han, ti gbogbo aye ri, ti won si mo pe eleyii ni ododo, awon adajo wa yoo jokoo, leyin tiwon ba ti gbowo lowo awon oloselu tan, tabi ti awon ti won n sejoba ba ti hale mo won, won yoo ni kinni naa ki i se ododo, nitori lasiko to sele, elerii to soro yen ko letoo lati soro.

Ki i se pe won ni elerii yen ko so ododo o,sugbon pe ko letoo lati soro ni. Iyen ni won yoo se pale ododo mo, ti won yoo si fi iro ropo re. Ibo ti gbogbo awon ara Kogi ri, ti won si fi tokan-tara won dibo fun Dino Melaye, awon igbimo ti won gbe dide nibe lati sedajo ni ibo naa ni ko daa, Dino ko lo wole.

Gbogbo aye mogbon won, ona lati di Dino Melaye lowo ko ma le dupo gomina tofee du ni, ati ona lati ja a kule pata ko ma je nnkan kan mo. O see se kiDino Melaye ma daa, ko je alariwo ati alafeyeye kan ti ko tile ye ko sunmo ile ijoba.

Sugbon elenu-rirun lo ni amu iya re, bi awon araalu re atiagbegbe re ba so pe eni ti awon n fe ko waa loo se oju awon nibikibi ree, gege bii eto ijoba demokiresi ti a n se yii, ko senikan to letoo labeofin lati di i lowo, nitori ki i se awon ni won yan an, awon araalu re ni.

Sugbon igba tawon adajo ba ti je ijekuje, isokuso lo ku ti won yoo maaso, idajo ododo yoo si sonu mo won lagbari, iro ni yoo ku nibe, wonyoo si maa si gbogbo wa lona kaakiri. O digba ti awon adajo wa ba laya lati se idajo ododo, ti won ko si gbowo eyin, ti won n dajo are fun olododo, ti won si n da ebi fun alaisododo, nigba naa ni orile-ede yii yoo dara gan-an.

Bi Naijiria ba dara, awon adajo yii ni ki e ki, bi Naijiriaba si baje, awon adajo yii naa ni ki e mu o.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, September 12 @ 07:03:26 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: