Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
[ Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu ]

·Iwosi Yii Si Ti N Po Ju Fun Yoruba, Ibi Ti Won Ba Wa De Ree O
·Bo Se Daa Niyen... Sugbon Kan Naa Lo Wa Nibe
·Bi Iro Ba Lo Logun Odun...
·Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
·Won Ni Alaga PDP Ku Sori Asewo N'Ipokia
·Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
·E Gbo! Kin Ni Fayose Wa Lo Si China?
·E Ko Sekeseke Si Won Lowo Jare
·Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ni 1978, Emo N Lo, Afe N Lo, Azikiwe Nikan Ni Ko Ti i Mo Ibi To Fee Gba Lo
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise Ni 1978, Emo N Lo, Afe N Lo, Azikiwe Nikan Ni Ko Ti i Mo Ibi To Fee Gba Lo

Titi di ipari osu kewaa, odun 1978, egbe oselu kan soso to wa ti ko loluwa ni egbe NPP. Ki i se pe ko loluwa bee naa, ko kan ni asaaju kan ti gbogbo won jo fowo si ni. Ati nitori eyi, isoro inu egbe naa ju ti egbe yoowu lo. Gbogbo eeyan lo ti gbo oruko egbe Unity Party of Nigerian (UPN), ti won si mo asaaju won pe Obafemi Awolowo ni. Bakan naa ni won mo oruko egbe National Party of Nigeria (NPN), ti won si mo alaga egbe naa pe Alaaji Aliyu Makama Bida ni. Bakan naa ni won mo oruko egbe Movement of the People (MOP), ti won si mo pe Fela Anikulapo Kuti ni olori egbe naa. Won tun mo egbe National Advance Party (NAP), ati pe Tunji Braithwaite lolori won nibe. Bee naa ni won si mo People Redemption Party ati pe olori won ni Aminu Kano. Koda, awon egbe keekeeke to ku paapaa ni olori won, gbogbo aye lo si mo won.

Sugbon ko seni to mo olori egbe NPN tabi eni ti yoo du ipo aare loruko won, bo tile je pe awon oloselu nla nla ni won wa nibe, awon oloselu gidi, awon olowo ati awon eni ti won mo lawujo. Awon bii Adeniran Ogunsanya, Kola Balogun, ati opolopo awon ti won je omoleyin Azikiwe ninu egbe NCNC lasiko ijoba awon oloselu atijo. Eyi ni awon eeyan kan se n so pe Azikiwe lolori egbe naa, ti won si ni oun naa ni won fee lo lati du ipo aare loruko egbe won. Awon oloselu inu egbe naa ti won mo eyi ko sise feni meji ju Azikiwe lo, bo tile je pe eni kan ti wa ninu egbe naa to n nawo gidi ju awon to ku lo. Okunrin oloselu kan toun naa ti se oselu daadaa, to si se minisita laye awon oloselu akoko ni, leyin to si kuro nidii oselu, ibon lo n ta, bee lo n ta etu, ati awon ota ibon, eyi si je ki owo re ya mura lasiko ogun abele. Waziri Ibrahim loruko re. Alaaji ni.

Isoro to wa ninu egbe NPP yii ni pe opolopo awon egbe keekeeke ni won parapo ti won di egbe yii, ninu won si ni egbe kan to n je National Unity Council, egbe yii ni egbe Waziri Ibrahim, oun si ni olori egbe won nibe. Sugbon awon egbe mi-in naa wa nibe, ti awon naa si je egbe gidi, ninu won si ni egbe awon omo Eko, ati awon egbe mi-in bee, paapaa lati ile Ibo. Nigba to si je oju ona kan naa ti won fi da egbe NCNC sile lodun 1944 ree, awon eeyan ri owo Oloye Nnamdi Azikiwe nidii egbe tuntun yii naa, won si ni baba naa lo wa nidii e, oun lolori won. Awon ti won je omo Azikiwe ninu egbe yii o yee so fawon eeyan pe Azikiwe lawon n sise fun, oun ni yoo di olori awon. Oro yii n dun Waziri Ibrahim ati awon ti won n tele e, won ni bawo ni eni ti ko se nidii pepe yoo se waa je nidii pepe, bawo ni Azikiwe ti ko ba won da si egbe yoo se waa du ipo aare loruko egbe won.

Lojo kan ni Waziri kuku la oro naa mole, o ni egbe awon, NPP, ko ti i ni olori kankan. O lo di igba ti awon ba se ipade gbogbogboo egbe naa ti alakooko, nigba naa ni awon yoo mo eni ti yoo je olori egbe ohun. O ni loooto lawon eeyan n pe oun ni olori egbe yii, sugbon iyen ko ti i see fi gbogbo enu so, afi nigba ti awon ba pade, ti gbogbo egbe ba fowo si i. N'Ibadan lo ti so bee, nigba ti won n ko egbe NPP yii jade ni ipinle Oyo. Ojo Satide, ojo kokanlelogun, osu kewaa, odun 1978 ni. Bee bi a ba si fee so tooto, Waziri ni gbogbo eeyan n ri kaakiri o, nitori ko si ibi ti won yoo ti ko egbe NPP jade ti ko ti ni i si nibe, ko si si owo kan ti yoo jade ti ko ni i je oun ni yoo seto lati na an. Opo awon omo egbe naa, paapaa awon ti won wa lati ile Hausa ko tile gba pe egbe ohun tun ni olori mi-in ju okunrin yii lo, won si ti mu un bii asaaju won.

Oro to so ni Ibadan yii ko dun mo awon mi-in ninu sa, iyen awon ti won ti n seto labele lati gbe Azikiwe jade bii iyawo tuntun. Awon yii ni awon ti soro yii tele laarin ara awon, awon ti won je asaaju egbe si ti mo pe bo pe bo ya, Azikiwe lawon yoo gbe jade, ki waa ni Waziri n loo so iru oro yii nita gbangba si, se ki won le mo pe awon o ti i mu olori awon jade ni, abi ti kin ni! Awon eeyan yii o si deede maa so bayii naa, awon naa kuku n lo si odo Azikiwe, won si n ba a sepade, o si jo pe oro ti won ti so laarin ara won ni pe baba naa yoo jade bo ba ya, sugbon Azikiwe ko ti i fe ki enikeni mo pe oun yoo jade, boya ko si ti i mo inu egbe ti yoo wa ni, nitori pupo ninu awon omoleyin re naa ti gba inu egbe NPN lo. Nibi ti won si ti n soro yii, kinni kan sele to ko royiroyi ba gbogbo eeyan, ati awon ti won n woran oselu ohun loookan, ati awon ti won n se e.

Awon egbe NPN ni won fee ko egbe won jade ni agbegbe Onitsha, iyen adugbo ti Azikiwe ti wa, ni won ba pe baba naa sibe, won ni ko waa se alaga ipade awon. Okan ninu awon omoleyin re to je asaaju egbe yii nile Ibo, Chuba Okadigbo, lo pe e. Oun ati Uwafor Orizu ni won pe. Okunrin Nwafor Orizu yii, okan ninu awon omo egbe NCNC, okan ninu awon omo eyin Azikiwe nigba ti won n se oselu akoko ni. Koda, nigba ti ara Azikiwe ko ya nipari odun 1965, to fee lo siluu oyinbo lati gba itoju, Orizu ni Azikiwe gbe ipo aare fun, to ni ko maa se ipo naa lo titi ti oun yoo fi de. Sugbon Azikiwe ko de titi ti awon soja fi gbajoba ni ojo keeedogun, osu kin-in-ni, odun 1966, bee lo se je pe Nwafor Orizu yii lawon soja gbajoba Naijiria lowo re leyin ti won ti pa Balewa ti i se olori ijoba. Oun lawon soja pase fun ko gbejoba fawon nitori pe ilu o fara ro, ti ko si si Azikiwe nile. Oun naa si se bee.

Eyi yoo fihan, ibi ti ajose okurin naa ati Azikiwe de duro nigba atijo, to je pe won jo n je, won jo n mu ni. Nigba ti eto oselu awon Obasanjo yii si bere, awon NPN ro pe ti awon ba ri Azikiwe ati Orizu mu, abuse ti buse, a je pe gbogbo ile Ibo ni yoo dibo fun egbe naa niyen. Sugbon leyin ti awon olori egbe naa ti gbiyanju titi ti won ko mo eyi ti awon agba mejeeji yii n se, won da a bii ogbon, won ni ki awon ti won wa lati agbegbe re pe won sipade, awon fee mo boya won yoo wa tabi won ko ni i wa. Won ni bi won ba fi ti le wa si ipade won, a je pe won ti gba lati di omo egbe NPN, okan awon yoo si bale, nitori bi won ko ba fee je omo egbe naa ni, won o ni i wa sipade awon. N lawon Okadigbo atawon mi-in ba kowe si Azikiwe pelu Orizu lodo won.

Azikiwe gba leta tire loooto, nigba to si di ojo ketadinlogun, osu kewaa, ni 1978, o da esi iwe naa pada fun won. Ohun ti baba naa si ko sinu leta re si won niyi o: "Inu mi dun lati ri iwe ti e ko ranse si mi lojo ketala, osu kewaa, odun 1978, eyi ti e fi pe mi si ipade yin, iyen ipade egbe NPN ti agbegbe Onitsha. Ni asiko ti a wa yii, oju ti opolopo eeyan fi n wo mi ni oju 'Baba orile-ede', iyen ni pe emi ni baba gbogbo Naijiria, gege bii aare ile wa, ati eni ti ko gbodo ni ikunsinu, tabi ikannu si enikeni. Nitori bee, ojuse kan soso naa ti mo ni lasiko yii ni lati ri i pe awon omo mi ko ja, won ko si ba ara won fa ifakufa ti yoo tun mu wahala kankan wa si ile wa. Iyen ni pe ipo baba ni mo fee wa, ki n le maa to awon omo mi sona bi won ba fee se asise, tabi nibikibi ti won ba ti fee maa ba ara won ja. Mo gbadura pe ipade NPN ekun Onitsha yii yoo mu eso rere jade o."

Bayii ni Oloye Azikiwe ko sinu leta re, oro naa si lu kii kii lokan awon ololufe ati awon omoleyin re, nitori ohun to fenu ara re so yii ni pe oun ko ni i se oselu, oun ko si ni i ba won du ipo kankan. Oro naa ya awon omoleyin re ti won ti n loo ba a lati ojo yii ti won si ti jo n sepade lenu, abi kin ni oga tun n so yii, ohun ti won n beere laarin ara won niyi. Sugbon oro naa dun mo awon eeyan Waziri Ibrahim ninu ni tiwon, won loun ti awon fe gan-an ree, ibi gereje la a ba agba, ipo agba ni Azikiwe wa, ipo agba naa si lo ye ki won maa ba a. Awon wonyi ni ohun kan soso ti yoo so Azikiwe di eni aponle ree, nitori bi baba naa ba tun ko ewu oselu sorun bayii, to n ba awon omode fa ipo aare ati ipo mi-in ninu egbe NPP, arifin ni yoo je, nitori awon omode naa ko ni i fun un ni owo to ba to si i. Sugbon won gba pe pelu eyi ti Azikiwe se yii, baba naa ti di baba gbogbo awon.

Sugbon oro naa ko tan sibe rara, nitori awon kan taku ninu egbe NPP, won ni nigba ti awon omoleyin Sardauna aye ojosi ko ara won jo po sibi kan, ti awon omoleyin Awolowo naa ko ara won jo po sibi kan, ti Awolowo funra re saaju won, bi awon omo Azikiwe naa ba ko ara won jo ti ko ba si Azikiwe nitosi lati saaju awon, awon yoo kan da bii omo ti ko ni baba ni, won ni eyi ti baba naa so yii, apo ara re lo so o si, awon yoo fa a jade dandan. Ohun ti ko waa si eni to mo tabi to le so pato ni pe boya eto ni kinni naa laarin awon asaaju NPP ti won fe Azikiwe gege bii olori awon ati Azikiwe funra re, tabi ko je awon omoleyin re yii ni won kan n fee fi ipa wo baba naa lati waa se ohun ti ko fee se. Awon oloselu ti won mo Azikiwe daadaa fi ogun re gbari saa, won ni baba naa yoo jade, o kan n dibon ni, ko fee wo egbe NPN lo se ko leta bee si won.

Bee ni gbogbo bi awon ti n se yii, awon egbe NPN ni tiwon naa ko duro mo, ona ti won yoo fi tete fi eni ti yoo du ipo aare loruko egbe won han ni won n se. N ni won ba fi ojo ipade gbogbogboo akoko ti egbe naa yoo se si ojo keeedogbon, osu kokanla, odun 1978, won ni lojo naa lawon eeyan yoo ri awon wo bii iran. Alaaji Aliyu Makama Bida ti i se alaga egbe yii lo kede bee, o ni Eko yoo gbalejo awon, won yoo si ri iran gidi wo, nitori lojo naa lawon yoo yan gbogbo awon ti won yoo du ipo kan tabi omi-in, ninu ibo maraarun ti won fee di ni Naijiria nigba naa. O ni gbogbo bi awon ti dake jee ti awon ko soro, iyen ki i se pe awon ko se nnkan kan, o ni eto gidi n lo, eto naa si ni pe awon o fe ohun ti yoo fa ija ninu egbe, tabi laarin awon omo egbe awon, iyen lawon se n yanju gbogbo ikunsinu keekeekee to wa, ki won le jade pelu gbogbo agbara won.

Alaaji Makama ni gbogbo awon ti won n soro pe eru n ba awon lati se ipade gbogbogboo egbe awon, pe ko ma je ojo naa ni egbe awon yoo tuka pata, ko mo ohun ti won n so ni, o ni awon n se eto tawon ni ona ti eto ijoba tiwa-n-tiwa, iyen demokiresi gba ni. Alaaji naa ni awon eeyan nla nla ti won lopolo gan-an ni won po ninu egbe awon, won si letoo lati du ipo yoowu ti won ba fe, awon si gbodo se e ni ona to je awon omo egbe funra won ni won yoo fa eni to ba wu won kale lati du ipo, ti ko ni i je enikan lo gbe eni kan le won lori bi awon egbe kan oke-ohun ti n se. Nigba ti won beere pe awon egbe wo waa ni egbe kan oke-ohun to n wi yii, erin lo bu si, o ni awon oniroyin naa mo awon ti won n wi funra won, to je eni kan naa lo n pase, ohun to ba si ti wi lawon to ku gbodo tele, ti ko seni to gbodo jiyan, oun funra e lo n fi awon to ba fe kale, o lawon yen loun n so.

Nigba ti yoo ba oro je, ti yoo si tu asiri ara re fawon eeyan lati mo ibi ti o n juko oro si, o ni gbogbo ara ti egbe UPN n da tawon eeyan ro pe won n dara gidi kan yen, lojo ti awon ba jade sita yii lawon yoo ba won, ti awon yoo si fi won sile, to je won ko ni i le ta putu mo nigbakigba ti won ba gbohun awon nigboro. Makama Bida ni ohun kan ni egbe awon ko ni i se, iyen naa ni ki awon maa bu awon egbe oselu egbe awon, tabi ki awon maa soro kobakungbe si won. O ni oselu asiko yii ti yato si tatijo, oselu ti ko ni i ba oruko enikeni je lawon fee se, eyi si lo fi je pe ko si egbe meji to dara lasiko naa ju egbe NPN lo. "E wo o, loooto lawon UPN ti saaju wa ninu eto ati ipolongo won, sugbon mo fee so fun yin pe ki i se pe a oo ba won nikan o, a oo la won, a oo ya won sile kia, eyin naa yoo ri gbogbo eyi nigba ti a ba kede eto wa, awon eto iderun gidi fun gbogbo araalu, oju yin yii naa ni yoo se."

Boya ni ko je oro yii lo dun awon UPN, n lawon naa ba sare jade, won ni eni to ba moju NPN ko kilo fun won o, ki won ma ji awon wo ninu eto, ki won ma kopi awon, nitori onikopikopi ni won. Okan ninu awon asaaju egbe naa, Alfred Rewane, lo sare so bee ni ilu Warri. O ni gbogbo ileri ti oun n gbo yii, ati ihale ti awon NPN n se yii, eru n ba oun o, eru to si n ba oun naa ni pe awon egbe naa fee ji egbe awon wo ni, nitori won le de bayii ko je ohun ti awon ti ni awon fee se lawon naa yoo jade wa ti won yoo ni awon fee se, nitori ko jo pe awon eeyan naa ni eto gidi kan fun awon araalu, ko si jo pe won mo ohun ti won n fe gan-an. O ni ki i se pe egbe awon, iyen UPN, kan deede ji lojo kan lawon gbe eto kale, tabi ti awon kede pe bayii lawon fee se fomo Naijiria, o ni ohun ti awon ti n pete-pero le lori lati ojo to pe ni. Nitori bee lo se ni ki NPN tete fi tiwon se tiwon.

Awon soja ti won gbe eto idibo yii kale ko mo pe bi yoo ti ri ree, won ko mo pe awon oloselu atijo yii naa ni won yoo tun gba oju opon eto naa kankan, o fere je gbogbo igba ni Ogagun agba Olusegun Obasanjo n sepade pelu awon omoose re bii Ogagun Shehu Musa Yaradua, Ogagun T.Y. Danjuma, awon bii Ibrahim Babangida, James Oluleye, Alani Akinrinade, Muhammadu Buhari ati awon soja to ku gbogbo. Ohun ti won n fe ni bi eto idibo ti won dana re naa ko se ni i ku sona lojiji, won n wa awon eeyan ti won le fi ropo awon oloselu atijo yii, sugbon ko jo pe kinni naa see se. Egbe meta naa lo fese mule ju, ti won si loruko ju, NPP, NPN ati UPN ni. Bee, awon oloselu atijo lo kun inu won fofoofo!
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, September 12 @ 07:07:31 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Ni 1978, Emo N Lo, Afe N Lo, Azikiwe Nikan Ni Ko Ti i Mo Ibi To Fee Gba Lo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: