Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere

Okun kii ho ruru ka wa ruru! Bayii ni ijoba apapo se n parowa fawon omo Naijiria pe ki won ye kolu awon ileese to je ti orilede South Africa to wa ni Naijiria lati gbesan isekupani awon omo Naijiria lorilede naa.

Ijoba ni kikolu awon ileese orileede South Africa ni Naijiria yoo ni ipa ti ko dara lara omo Naijiria ju South Africa lo.

Minisita fun iroyin ati asa, Alhaji Lai Mohammed so ninu atejade kan pe bawon omo Naijiria kan ti fi ibinu kolu awon ileese to je ti orileede South Africa lojo Isegun ku die kaato.

Lai Mohammed ni awon omo Naijiria ni oludokowo lawon ileese orileede South Africa, nitorinaa fifi owo ara eni sera eni ni kawon omo Nigeria maa ba iru awon ileese bee je.

Bakan naa ni minisita eto iroyin ati asa ni omo Naijiria lo poju ninu awon osise ileese South Africa to wa ni Naijiria.

O fikun oro re pe awon omo Naijiria lo maa fori ko ju, ti awon ileese orileede South Africa ba di titi pa.

Minisita Aare Muhammadu Buhari ti ran awon asoju si aare South Africa lati fi edun okan re han ati lati wa nnkan se si ikolu ati ikoriira awon omo Naijiria to n gbe ni South Africa.

O ni aare ti so fun minisita oro ile okere, Geoffrey Onyeama pe ko ranse pe asoju orileede South Africa ni Naijiria pe ko wa so tenu re, bi o tile je pe asoju South Africa oun ti so pe ohun to n sele kii se ikoriira awon omo Naijiria.

Ewe, egbe oselu alako PDP ti kepe ile igbimo asofin agba l'Abuja lati pe ipade pajawiri lori oro naa.

PDP bu enu ete lu ijoba Aare Buhari pe ko tete ja oro naa kunra, won ni o buru jai pe olu ileese Naijiria to wa nile South Africa tun ko eyin si awon omo Naijiria to sa lo sibi.

Osinbajo, Ekweremadukoro ojú sí ìkolù South Africa

Igbakeji Aare orileede Naijiria ki kesi awon adari lorileede South-Africa pelu ibanuje okan lati dekun ipaniyan nitori eya to n lo lowo lorileede South Africa.

Osinbajo lasiko to n ba awon oniroyin soro ni ipinle Kano, so wi pe o lodi si igbelaruge eto omoniyan ti awon adari ile South Africa ja fun ni igba aye won.

O ni oun to buru jai ni lati koju ija si awon omo Naijiria ti won wa ni South Africa bayii, nitori pe Naijiria pelu awon to ja fun ominiran ile naa lowo awon amuniseru.

Bee lo wa kesi ijoba orileede naa lati dide ati lati wa woroko fi sada lori ipaniyan naa ki oun gbogbo le pada si ipo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, September 12 @ 07:19:36 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: