Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi
 
 
Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi

Medinat Adesoye, Osogbo

Adajo kootu kan nilu Osogbo ti pase pe ki won lo fi Abiodun Akeem Oladebo pamo sogba ewon titi ti imoran yoo fi wa lati ileese eto idajo ipinle Osun lori esun ti won fi kan an.

Se lawon olopa so pe Akeem, omo odun mokanlelogoji lo pa iyawo re, Sajenti Opeyemi Ojo lojo keedogbon osu keji odun yii.

Inspekito Tajudeen Mustapha so funle ejo pe se ni Akeem so ori obinrin olopa yi mo ogiri, eleyi to yori si iku ojiji to ku. O ni iwa naa nijiya labe ofin iwa odaran tipinle Osun.

Mrs B Y. Dada to duro fun olujejo ro ile ejo lati je koun gba beeli re sugbon Onidajo Ajanaku ni rara, afi ki won lo fi pamo sogba ewon.

O wa sun igbejo siwaju di ojo kesan osu karun odun yi.

Diran to lu Abiola ni jibiti owo l'Osogbo ti foju bale ejo

Diran Olawale ti won fesun kan pe o lu Abiola Adelakun ni jibiti owo to din die ni milionu kan naira ti foju bale ejo bayii.

Gege bi Sajenti Adewuyi Kehinde se so nile ejo, o ni ni igba kan ninu osu kerin, odun 2011, ni adugbo Olobi, Owoope nilu Osogbo, olujejo gba owo lati ba Ogbeni Abiola Adelakun ra eeka ile marun, eleyii to si pada ja si iro.

Sugbon olujejo so funle ejo pe oun ko jebi gbogbo esun ti won fi kan oun, bee ni agbejoro re ro ile ejo lati fun un ni beeli ti o rorun, o si se ileri pe oniduro gidi ni olujejo naa maa muwa.

Adajo O. A Oloyade fun olujejo naa ni beeli pelu egberun lona eedegbeta naira, oniduro meji ti won gbodo ni iwe eri odun meta ti o fihan pe won san owo ori re.

Adajo waa sun igbejo siwaju di ojo keta osu karun, odun yii.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, October 12 @ 14:15:58 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose:
Iru Pasito Radarada Wo Waa Ni Oluso-Aguntan Oyelami Yii Gbogbo Awon Omobinrin Ij


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose

"Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: