Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Deji Binu Si Titi Afesona Re, Lo Ba Dana Sun Eeyan Mesan Mole L'Ondo
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu Deji Binu Si Titi Afesona Re, Lo Ba Dana Sun Eeyan Mesan Mole L'Ondo

Ileese olopaa ipinle Ondo ti n wa omokunrin kan, Deji Adenuga lori esun pe o dana sun awon molebi orebinrin re, Tutu Sanumi nitori pe iyen so fun un pe oun o se mo.

Deji, eni ti a gbo pe o ti sewon ri ni wahala be sile laarin oun ati Titi, eni ti won ti jo n ba ere aniyan bo lati odun merin seyin, koda, oro naa le debii wi pe won ko ara won lo si agoo olopa, sugbon pabo lo ja si.

Bi Titi se so fun Deji pe o to gee bayii la gbo pe o ti kuro niluu Ondo laije ki Deji mo. Pelu ibinu ni Deji fi lo sile awon Titi to wa loju-ona Igbokoda lojo Tusde, o gbe keegi epo petiroolu lowo, o si dogbon si windo ile naa laarin oru.

O da petiroolu sinu ile, o si ju isana si i, loju ese ni meji ninu awon molebi Titi ku, nigba tawon meje to ku dake nileewosan Trauma Center niluu Ondo.

Awon eeyan ilu Moro ati Yakoyo koju ija si ara won nitori idajo ile

Ara ko rokun, ara o ro adiye lowolowo bayii nilu Moro ati Yakooyo nijoba ibile Ariwa Ife.

Koda, Iroyin kan ti a ko le fidi re mule bayii so pe eeyan meta lo ti jepe Olorun, nigba ti opolopo si farapa yannayanna.

Lakolako ni ibon n dun, ti ko si si ifokanbale fun enikeni. Idajo kan la gbo pe awon eeyan ilu Yakoyo gba nile ejo giga ilu Ife laarin ose yii.

Idajo yii lo fun won lase lati lo gba awon ile won tawon eeyan ilu Moro ti gbese le.

A gbo pe won lo ba DPO ileese olopa ilu Moro lati fun won lolopa kawon le samuse idajo kootu naa, sugbon iyen so fun won pe komisanna olopa lo lagbara lati se bee.

Laaro oni, lawon eeyan ilu Yakoyo bo sita pelu atileyin baba oloselu kan nilu naa, gege bii aheso ti a gbo, baba yii lo fun won ni soja kan to n tele won kaakiri awon agbegbe ti ilu Moro ti tase agere wonu ile won.

Awon eeyan ilu Moro pe won nija lori nnkan ti won n se, a gbo pe inu bi soja naa, o si sina ibon bole, bayii ni wahala bere lati aaro.

Alukoro ileese olopa ipinle Osun fidi isele naa mule, sugbon won ko le so boya enikeni gbemi mi ninu isele naa.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, October 12 @ 14:24:14 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Deji Binu Si Titi Afesona Re, Lo Ba Dana Sun Eeyan Mesan Mole L'Ondo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: