Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
[ Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu ]

·Deji Binu Si Titi Afesona Re, Lo Ba Dana Sun Eeyan Mesan Mole L'Ondo
·Victoria Fi Obe Gun Oko Re Pa; Ladajo Ba Ni Ki Won Loo Yegi Fun Un
·Awon Olopaa Fee Mu Baba Atiya Ti Won Lu Omo Won Pa L'Akure
·O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
·Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
·Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
·Nibi Ti Sunkanmi Ti N Gbeja Iya Re Lo Ti Gun Ojo Nigo Pa l'Ondo
·Tope To Pa Lanloodu e L'Ondo Ti Wa Lewon
·N'Igbokoda, Tegbon-taburo Ri Ore Meji Mole Laaye Nitori Ti Won Ji Iya Won L

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
 
 
Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara

Ninu isedale ati idasile itan ile Yoruba, okan pataki ni eya Egba je. Eya kan ni to je pe pupo ninu adamo won ko si ninu awon eya to ku nile Yoruba ti Olodumare si fi ebun ife ati isokan jiǹki won.

Yato sa asa ati ise ti a mo won mo, iwa omoluabi, irele ati ikonimora je ki eya yii di ilu-mo-o-ka kaakiri agbanla aye. A ri eleyii nibi eto isejoba, eto oro aje, eto amuluudun, eto oselu, esin ati awon asa miiran ti a fi le gbe oriyin fun omoniyan.

Nibi eto oselu, Egba lo wa loke titi di asiko yii, nitori pe awon bii Oloye Olusegun Obasanjo, Oloye Ernest Sonekan, Oloye Olusegun osoba ni ko see fowo ro ti seyin. Bakan naa nibi eto oro aje, awon bii Oloogbe Moshood Kasimaawo Abiola ni won ń wa loke.

Nibi eto amuluudun, Egba naa le maa ri niwaju nitori pe awon bii Oloogbe Akin ogungbe, Oloogbe Duro Ladiipo atawon miiran ni won so eto amuluudun dirorun. Bee nibi eto eko, ko tii si ilu kan ninu awon eya Yoruba ti won le figagbaga pelu awon omo Egba ti won ti wa loke atawon to sese ń dide bo bii, ojogbon Wole Soyinka ta gba ami eye agbaye, eyi ti enikeni ko tii gba iru e ri nile Yoruba, paapaa lorile-ede Naijiria, Omoba Bola Ajibola to je oludajo agba nile ejo agbaye ti ko tun tii si iru e dasiko yii. ojogbon Akinwunmi Isola, Debo Alebiosu, Alagba J.F Odunjo, Amofin Bola Solańke to je eni to koko gba oye imo ofin lorile-ede Naijiria, Oloogbe Titilayo Ransom Kuti to je obinrin akoko to koko wa oko nile Yoruba ati lorile-ede Naijiria lapapo.

A ko le soro eto amuluudun tan lai menuba awon oǹkorin bii Oloogbe Fela Anikulapo, Oloye Ebenezer Obey, Ayinla Omowura, Yusuf Olatunji, Sina Peters, to fi de ori Alhaji Sefiu Alao won si ń se ise ribiribi lawujo wa di asiko yii.

Bakan naa ninu eto ere idaraya, awon omo Egba ni won ń leke. A o le soro lai menuba awon bii Mudasiru Lawal, Segun Odegbami.

Ninu awon nǹkan to ń mu ki ilu Egba tayo ni ti imugbooro eya naa pelu awon eka maraarun ti awon Oba alade marun-un otooto je olori fun. Awon eka naa ni Egba Ake, Egba owu, Egba Agura, Egba Oke-ona ati Ibara.

Egba Ake to ni awon adugbo bii: Itesi, Ikopa, Ibarapa, Adatan, Asero, Isale-Ake, Ijemo, Itoko, Iporo-Ake, oke Ejigbo, Erunwon, Ijaye, Obańtoko ati bee bee lo ni Oba Alake to tun je olori awon oba patapata ni Ipinle ogun bayii je olori fun. Alake ni won ń pe oruko Oba won.

Awon Oba ti won ti je ni: Oba okukenu to je laaarin odun 1854 si odun 1862; Oba Ademola (I) to je laaarin odun 1869 si odun 1877; Oba Oyekan to je laaarin odun 1879 si odun 1881; Oba Oluwaji to je laaarin odun 1885 si odun 1889; Oba Osokalu to je laaarin odun 1891 si odun 1898; Oba Gbadebo (I) to je laaarin odun 1898 si odun 1920.

Awon miiran ni Oba Ladapo Ademola (II) to je laaarin odun 1920 si odun 1962; Oba Samuel Adesina Gbadebo (II) to je laaarin odun 1963 si odun 1971; Oba Mofolorunso Oyebade Lipede to je laaarin odun 1972 si odun 2005, to fi wa de ori Oba Adedotun Aremu Gbadebo to je lodun 2005 titi di asiko yii.

Egba Owu: Leyin naa ni Egba owu to ni awon adugbo bii: Totoro, Akin-Olugbade, oke Sokori, Ita-Eko ati bee bee lo. Olowu tiluu owu ni won ń pe Kabiyesi won.

Awon Oba ti won ti je ni: Oba Pawu ni Oba to je laaarin odun 1855 si odun 1867, Oba Adefowote to je laaarin odun 1869 si odun 1872, Oba Aderinmoye to je ni odun 1873 si odun 1873 si odun 1890, Oba Owookade to je laaarin odun 1893 si odun 1905, Oba Adesunmbo Dosunmu Amororo (I) to je laaarin 1918 si odun 1924.

Awon miiran ni Adesina to je laaarin 1924 si odun 1936, Oba Adelani gbogboade Otileta (IV) 1938 si 1946, Oba Salami Adewunmi Ajibola Gbadela (II) 1949 si odun 1972, Oba Adewale Oyegbade to je laaarin 1975 si odun 1980 titi to fi de ori Oba Olusanya Adegboyega Dosunmu Amororo (II) to je lodun 2005 titi di oni yii.

Egba Agura: A tun ni Egba Agura toun naa ni awon adugbo bii: oke-Ido, Ago-Ika, Ita-Ika, Ikereku, Adedotun ati bee bee lo. Oruko Oba won ni Egba Gbagura.

Awon oba to ti je ni: Oba Jamolu to je laaarin 1870 si odun 1877, Oba Ijaade to je laaarin odun 1878 si odun 1893, Oba Olubunmi to je laaarin odun 1897 si odun 1910, Oba Abolade to je laaarin odun 1910 si odun 1915, Oba Adeosun (I) to je laaarin 1915 si odun 1936, Oba Bakare Babasola Olaloko Sobekun (I) to je laaarin odun 1937 si odun 1960.

Awon miiran ni Oba Raufu Adeosun (II) to je laaarin odun 1961 si odun 1978, Oba Halidu Adedayo Olaloko Sobekun (II) to je laaarin odun 1980 si odun 2018.

Oba Abdul-Subur Bakare to je lodun 2018 lo wa lori oye bayii.

Oke-Ona tun je ilu miiran lara awon eya Egba. Lara awon adugbo to wa labe oke-ona ni Sapon, Ago-oko, Ijeun-Titun, oke-Ijeun, Isabo, Kuto ati bee bee lo. osile ni oruko Oba won.

Awon oba to ti je ni: Oba Karunwi (I) to je ni odun 1897 si odun 1899, Oba Sanyaolu Adebare (I) to je laaarin 1900 si odun 1902, Oba David Sokunbi Karunwi (II) to je laaarin odun 1904 si odun 1918, Oba Suberu Adedamola (I) to je laaarin odun 1918 si odun 1932, Oba Yesufu Adedotun Idowu to je laaarin 1932 si odun 1934, Oba Emmanuel Sobayo Adebare (II) to je laaarin 1934 si odun 1944, Oba Alimi Adediran Adedamola (II) to je laaarin odun 1951 si odun 1988.

Oba (Dr.) Adedapo Adewale Tejuoso Karunwi (III) lo wa lori oye lowo bayii,

Ibara: Ilu miiran tun ni Ibara je ninu awon ilu to wa labe eya Egba, lara awon adugbo to wa labe ni Omida, oke-Ilewo, Onikoko, Panseke, Olomore ati bee bee lo. Olubara ni oruko Oba alade won.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, October 12 @ 14:34:56 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo:
Yoruba Greetings, (Middle) Names In Yoruba Language With Titles Of Obas (Kings)


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo

"Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: