Gbagede Yoruba
 



O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: Bako Ku Sori Obinrin Ninu Oteeli l’Ondo

Afi bii adie tojo pa niyawo ile kan se n ka; siosio laipe yii niluu Ofa, nigba ti oko e, Ogbeni Muili Adelowo, da eru e sita, o ni o lo oogun ki omu re tobi ju bo se wa tele lo.

Okunrin naa ni o ti n sise asewo nitori oun tun ka kondoomu monu baagi e.



Nise ni Adelowo le iyawo ile e to ti bimo meji fun un sita, esun to si fi kan an ni pe o lo oogun to n mu omu obinrin wu nilopo meta ju bo se wa tele lo.

O salaye pe oun tie so fun iyawo oun pe kawon lo si osibitu tabi odo awon onisegun ibile lati mo boya aisan kan ti won n pe ni somu-roro to maa n da awon obinrin laamu lo n se e, tabi kokoro kan, eyi to nilo itoju.

O so pe o ya oun lenu nigba toun bere si i wadii, ti ore e kan si so foun pe oogun ki omu le yo sita niyawo oun Baale ile yii ni obinrin naa, tawon eeyan mo si iya Nimota ti bimo meji foun, sugbon iwa e kan deede yipada, to si je pe oun ko jerii e mo rara. O ni ore e yii lo so foun pe laarin awon merin tawon jo n rin, awon meji lo lo oogun ki omu won le yo jade daadaa.

Sugbon nigba ti a beere oro lowo iyawo e, o so pe nigba toun ba oko oun jise-jiya tan, taye e waa fee maa daa lo fee le oun jade. Ohun to fi pari oro e ni pe Olorun yoo da a fun un.

Bako Ku Sori Obinrin Ninu Oteeli l’Ondo -- Lati Owo Solomon Adewoye, Akure

Inu ibanuje nla lawon molebi arakunrin kan ti won pe oruko e ni Bako, to n sise lagbegbe O·ka, niluu Ondo gege bi agegedu wa bayii pelu bi okunrin naa se ba iku ojiji pade lose to koja lakooko to n ba omodebinrin kan lajosepo lowo ninu ile-itura kan niluu naa.
 
O·gbeni Bako, gege bi awon eeyan ti mo oruko e si ko ti i ju omo ogoji odun lo. Nise lokunrin naa fee se faaji aye ara re pelu arewa omodebinrin kan ti ko seni to mo oruko re, ile-itura kan to wa lagbegbe Surulere, niluu Ondo lo gbe omodebinrin naa lo fun igbadun sugbon iku loro naa ja si fun un.

Gege bi iwadii se so, okunrin naa ni iyawo nile, a gbo pe lojo keji ti awon osise ile itura naa ko ri i ki okunrin naa jade sita ni won lo si yara re, sugbon oku re ni won ba. Ko seni to mo akoko ti omobinrin naa sa kuro ninu ogba ile-itura naa, bee ni won ko si mo odomodebinrin naa ri rara.

Isele yii lo mu ki awon molebi arakunrin naa yo lo si ile-itura ohun, ti won si fee jo o, opelope awon olopaa agbegbe Yaba to tete de sibi isele naa. Awon lo pada gbe oku Bako lo si mosuari to wa niluu Ondo fun iwadii to peye, bee lo je pe ko seni to mo iru iku to pa okunrin naa.

Awon kan so pe o se e se ko je pe magun lo lu lara obinrin to ba sun naa, bee lawon mi-in so pe ki i se akoko niyi ti iru nnkan bee yoo sele nile itura naa, won ni o ti to igba meta tisele bee ti waye nibe lodun yii.

O·ga olopaa Yaba niluu Ondo, O·gbeni Mike Okoh, so pe loooto ni isele naa sele, ati pe iwadi ti bere ni pereu lori re.

 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, October 09 @ 23:46:42 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 4.5
Awon Ibo Ni Oniyi: 2


Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga



"O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com