Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
[ Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise ]

·Ni Ti Ooni, Alaafin Ati Aare Ona Kakanfo
·Sugbon Ta La Ri Ba Wi, Bi Ko Je Baba To Fi Omo Re Foko L'oru
·Ni 1978, Emo N Lo, Afe N Lo, Azikiwe Nikan Ni Ko Ti i Mo Ibi To Fee Gba Lo
·Leyin Odun Mokanla, Bose Fee Ko Oko Re Sile l'Abeokuta: Nitori Orekunrin Re
·Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
·Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
·Iyaale Ile To Fi Kokeeni Soyun Ti n Ka Boroboro
·Lati Ekiti Ni Wasiu Atawon Ore Re Ti Waa Fi Owo Ayederu Raja n'Ilorin
·Onisowo Ibadan Bo Lowo Awon Ajinigbe Leyin Ojo Marun-un Ninu Ahamo Won

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ni Kwara, Awon Omo Ilu Ora Sedaro Kamaldeen Mohammed To Ku Sinu Ijamba Eronpilee
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Idris Aloma, Ilorin

Ni Kwara, Awon Omo Ilu Ora Sedaro Kamaldeen Mohammed To Ku Sinu Ijamba Eronpileeni Ni Balyesa

Ni Kwara, awon omo ilu Ora sedaro Kamaldeen Mohammed to ku sinu ijamba eronpileeni ni Balyesa Afi bii eni pe aare orile-ede lo ku ni ariwo ati jinni jinni se gbale niluu Ora, nijoba ibile Ifelodun, nipinle Kwara, laipe yii, nigba ti won gbokuu eso Ogagun Andrew Azazi, Ogagun Kamaldeen Mohammmed wolu. Nibi oku baba Oronto Douglas to je oludamoran lori eto aabo fun Aare Jonathan tele ti won loo se nipinle Bayelsa laipe yii ni won ti padanu emi won ninu ijamba baalu. Awon araalu naa ko le gbagbe isele naa laelae.

Bawon obinrin se n sunkun kikoro lawon okunrin to lokan fajuro. Ojo buruku gbaa lojo naa niluu Ora, bo tile je pe oruko okunrin ogagun ohun ko se bee han sawon eeyan, koda ko seni to mo pe omo ilu naa ni nigba aye e.Sugbon gege bii owe awon agba to so pe eni to kan lo mo, bee gege loro naa ri fawon araalu Ora. Awon ni won mo pe ofo nla lo se awon nitori nise ni gbogbo ilu naa kan gbinrin gbinrin, ko si soro lati mo pe nnkan ibanuje kan sele nibe. Saaju ki won too gbe oku yii wolu lawon omo ilu naa ti pe wamu, nise ni gbogbo won naro kaakiri, paapaa nile awon Ogagun Kamaldeen, nigba tawon eso ologun (soja) ti wa nibe lati aaro kutu hai nibi iboji ti won yoo sin in si.

Leyin eyi ni won gbe oku naa lo sile baba e tawon aafaa si sadura si i. Won seto isinku, Imaamu ilu Ora, Alaaji Abdul Ganiyu Jimo, lo kirun si i lara, o si se waasi pe ki koowa se daadaa nitori iku o se e ye, ati pe ohun lopin eda. O ni loooto niku naa je ofo ati ibanuje, sugbon keeyan ku lomode ko ye ni, o san ju ka dagba lai ni adie irana lo. Bakan naa ni Imaamu yii so pe ki i se oro ipo Oba ilu lo fa iku ojiji okunrin soja ohun.

Enikan to ba wa soro lori isele ohun to ni ka foruko bo oun lasiiri so pe opolopo awuyewuye lo ti n lo niluu naa tele pe nitori oro oye oba ilu naa ni iku okunrin naa se waye, nitori o leni ti won lero pe o faramo lakooko oro naa, ki won too fi Oba Bayo Kolade to je osise-feyinti nibi ise to n ri si wole-wode awon ajoji lorile-ede yii joba naa.

Sugbon baba kan toruko e n je Abimbola so pe oro naa ko ri bee rara. O ni fun eni to ba je musulumi tabi onigbagbo ododo, yoo gba pe ko seeyan kan to le pa elomi-in bi akoko Olorun ko ba ti i de. Okunrin naa salaye pe awa eda ki i ranti iku, bee ni iru iku ti yoo pa onikaluku yato sira won. Akoole ti duro lori gbogbo eda.

Saaju akoko yii lawon ologun egbe e ti yinbon leralera lati daro eni won to lo, bee ni won tun yan gege bii ise won. Leyin eyi ni won feeru feeru, ti won si ferupe ferupe. Akobi oloogbe naa lo koko bu erupe si i loju, ki awon omo to ku naa too se bee.

Leyin ti won sin in tan lawon ologun ko fila, bata ati asia orile-ede yii le akobi e lowo, eyi to fi han pe okunrin naa ti kuro laarin awon, ati pe ibi to fadagba aye ro si, omo e ni yoo lo iyoku. Awon ologun tun yan, won ko sinu moto won, won si ba tiwon lo. Awon araalu sunkun kikoro, bee lawon molebi n yi nile, o daju pe oku ofo gbaa loku Ogagun Mohammed Kamaldeen Omooba Odesile.

Te o ba gbagbe, lojo keeedogun, osu kejila, odun 2012, lokunrin ologun yii ku ninu baalu pelu awon marun-un mi-in, nigba ti won n bo lati ibi isinku baba okan lara awon Oludamoran Aare Goodluck Jonathan tele lori eto aabo, iyen Oronto Douglas.

Ninu baalu to ja nipinle Bayelsa ti i se ipinle abinibi Aare Jonathan la ti ri Gomina ipinle Kaduna, Oloye Patrick Yakowa, Ogagun Andrew Azazi, Mohammed Kamaldeen ti i se eso Azazi, eni to je okan lara awon owo omo ogun kokanlelogorin, eka otelemuye awon omo ogun ori ile.

Lara awon to tun ba isele naa rin ni eso Gomina Yakowa, eni to n wa baalu naa ati oluranlowo e.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, January 23 @ 03:03:51 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Ni Kwara, Awon Omo Ilu Ora Sedaro Kamaldeen Mohammed To Ku Sinu Ijamba Eronpilee" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: