Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Oro Oba Ataoja: Omooba Adeleke Ni Ayederu Lawon Idile Aderohunmu Ati Olude, Won
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Oro Oba Ataoja: Omooba Adeleke Ni Ayederu Lawon Idile Aderohunmu Ati Olude, Won Ko Si Lara Wa

Wahala olodun meji lori oro oye Ataoja tilu Osogbo tun gbona mi-in yo lose to koja pelu b i okan lara awon idile maraarun ti won n joba niluu naa se so pe gboingboin lawon wa leyin Oba Jimoh Olanipekun to wa lori oye naa lowolowo.

Agbenuso fun awon idile Lajomo, Omooba Adeleke Oduola Ibiloye, so fun Iwe Iroyin Yoruba pe ayederu lawon idile Olude ati Aderohunmu ti won so laipe yii pe awon idile Lajomo ko si leyin Oba Olanipekun.Alhaji Oduola to ti le die ni ogorin odun so pe idile Olude ati Aderohunmu ko si lara awon ile Lajomo rara ati pe ki won fori le ile-ejo ti won ba ni eri lati so pe ara omo Lajomo lawon.

Gege bi baba yii se salaye, ƒOro ti mo n so yii, oro itan ni, to si je pe oro itan yen ni won fi fun wa ni idile oye merin ni 1981, iyen ile Lajomo, Laro, Lahanmi, Oyipi ati Matanmi sugbon loni-in, idile yen ti di marun-un.

Ni 2005 ni won fi ile olomooba ti Sogbo kun wa. Ni 1973 ni gbogbo awa omooba l’Osogbo bere si i kowe ehonu sijoba lori idile oye ti a ni nigba yen ti a n pe ni idile omobinrin ati idile omokunrin, gege bii idajo igbimo Adegbenro tori a fi n yan ara wa je. Iyen la se ni 1976, awa omo Adedunhan si wa ninu awon ti won ko iwe ehonu.

Leyin eyi nijoba gbe igbimo Sotunde sile, iyen Sotunde Enquiry ni 1974, emi ni mo senu fun idile Lajomo. Pelu idi kan to han sijoba igba naa, abo iwadii yen ko jade, a ko gbodo maa menuba iyen nibi. Igba to tun di 1976, ijoba tun gbe igbimo oluwadii mi-in kale, iyen Ademola Adenekan Commission of Enquiry, gbogbo omooba pata to wa l«Osogbo ni won ko iwe lo sibe nigba naa pelu awa naa loruko Lajomo. Titi ti a fi pari iwadii yii, ko seni to gburoo idile Olude ati Aderohunmu, won o yoju.

Igba ti abo iwadii igbimo yii jade gege bi mo se so siwaju, ohun lo se idasile idile olomooba merin. Awon omo Sogbo, iyen Oluawo ati Gbaemu waa lo sile-ejo, ejo naa koko wa niwaju Babalakin niluu Ikirun ni 1992, igba ti Babalakin lo lai se e ni Sijuwade de, oun naa o se e, niAdio waa de, Adio lo waa so pe oun gbodo gbo ohun to ba wa nidii ejo yii. Emi naa ni mo senu fun awa omo Adedunhan loruko Lajomo, odun marun-un la fi ro ejo ti awon omo Sogbo pe.

Igba ti a n ro ejo yii lo ni idile Aderohunmu ati Olude waa darapo. Ako gburoo won nigba ti igbimo oluwadii ti Sotunde, Ademola, ati ti Babalakin, a ko gburoo won pe omo Lajomo ni won; sugbon nigba to debii ti Adio, won waa darapo. Labe ofin, ti eeyan ba ri i pe ejo kan le pa oun lara, bi won o tile pe e lejo, o le darapo mo ejo yen.

An rojo yen lo, looya wa, Oloogbe Adeboye Adejumo, waa beere lowo won pe nibo ni won wa nigba igbimo iwadii Sotunde nigba to je pe omo oba ni won, ti won si wa l«Osogbo, ati nigba ti Ademola. Igba ti won ri i pe ko si ona abayo, won yora won kuro ninu ejo yen, ibe loro yen ku si doni. Ko si akosile kan ninu iwe ilana ti won fi n joye niluu Osogbo to le so pe Aderohunmu ati Olude, eyi ti Liasu Olateju ati Saamotu Olude n senu fun je okan ninu wa.

Sugbon nigba ti Oba Jimoh Olanipekun, Ataoja to wa nibe yii joye, won ko ote jo, awon idile Aderohunmu ati Olude waa loo go sabe awon ti won ko ote jo yii, won waa n so pe awon lojulowo omo ile Lajomo, pe enikeni to ba se ti Ataoja, awon yoo gbe e lo sile-ejo< iyen la fi so pe ile-ejo yen gan-an la n reti ki won lo ki won le ri esin ara won.

Mo fee so fun yin pe Laro lo wa nibe loni-in, yoo gbo, yoo to, to ba kuro nibe, o kan Lahanmi Oyipi, to ba pe pe pe lo kan awa Lajomo. Won o ni eto lati yoju, bi iru wa yii ko si laye mo, awon omo wa kunle lorisiirisii.

Ajagunna to je olori afobaje loni-in gan-an o gbodo so pe won letoo lati debe. Nigba ti won n beere lowo won l«Oke Baale laipe yii nibi igbimo oluwadii ti Aregbesola gbe kale, won ni nitori pe ile mi ni Looya Araoye ti awon gba nigba naa n gbe ni ko je kawon te siwaju ninu ejo ohun nigba naa. Loro kan, ile Olude ati Aderohunmu o ba Lajomo tan, won ki i se iran Lajomo, won o si letoo labe Lajomo lati je oye.

Ai waa mo o, ti won ba ba Sogbo ti won jo n sepade tan, ko si wahala, ti won ba ba Lahanmi tan, wahala tiwon niyen, ti won ba ba Matanmi tan, ko kan wa, ti won ba so pe olomooba lawon, ki won wa idile omooba mi-in ti won yoo darapo mo. Sugbon ni tiwa o, won ki i se omo Lajomo, ko si si akosile kankan to le so ni pato pe omo Lajomo ni won.

Bakan naa ni ko si ijoba to le yi akosile to ti wa nile nipa ilana oye ilu Osogbo, ayafi ti omiin ba fee kun un. Koda bi omo Olude tabi Aderohunmu ba je Gomina Osun, ko le so ile won di omo Lajomo.

Omo iya ati omo baba kan naa ni Lajomo ati Laro, Lajomo lagba, Laro laburo, Ola-Oge ni baba won, Lajomo lo waa bi Adedunhan, oun lo tun bi Sogbo to je baba awon Oluawo ati Gbaemu.

Nipa ohun ti won n so pe eegun lawon iran Olanipekun gbe wa siluu Osogbo, Alhaji Oduola ni, Omo Larooye ponbele ni Oba Jimoh Olanipekun nitori pe Omunmuyiwa ni Aremo Laro, Laro naa lo si bi Lokungboye, oun lo bi Lakanye, oun lo bi Abogbe to je Iya Matanmi. Omo Laro ni Jimoh, bi bee ko, ko le de ibi to de yen, iru wa gan-an o ni i gba, awa ta a je omo Lajomo o ni i gba tori pe Olorun fun wa ni anfaani lati ma se je ko debe. Omunmuyiwa lo se won sile nile Opoole, won kan n pe won ni eleegun ni. Ta ni ko ni orisa to n sin laye ijohun nigba ti ko ti i si esin Imale ati ti Onigbagbo? Enikookan lo ni nnkan ti won fi n gbadura. Nile tiwa, a maa n se ti Sango, ki i se pe a n yo ina lenu o. Nigba ti won bi baba wa Adedunhan bo tile je pe won se wahala ki won too ri oyun re bi, nigba ti won bi i, won ri i pe o di owo mejeeji. Nigba ti won la owo re ni won ba okuta kekere kan nibe, babalawo lo waa difa pe edun aara niyen, Sango ni, okuta yen ni won n fi le awon olori ebi wa lowo bayii.

Ohun tawon Sogbo n fe ni ilana idile omokunrin ati omobinrin, se e mo pe omobinrin ni Oyewale to waja, won fe ko tun kan awon leyin opolopo igbimo iwadii ti a ti se seyin, ko se e se, ko si ogbon ti won le da si i. Won ti ko ejo yen lo sodo Gomina Ajimobi to ba won tan, won ko rogbon da si i. Ejo ti won si n ro ti a le pe lejo gidi ni pe boya ile-ejo so pe ki won ma ti i joye ti Lagunoye fi joye; gbogbo iyoku, otubante ni.≈ Aafin ni won fi ori mi sole si ni 1932, ko si nnkan ti won le mu jade ninu wahala ti won n fa. Leyin Laro, Lahanmi Oyipi lo kan, ko si ogbon ti won le da si i.

Mo waa n fi akoko yii so fun awon Aderohunmu ati Olude pe bi won ba waa ni eri kan lowo pe omo ile Lajomo lawon, awa omo Adedunhan nile Layiokun pe won nija lati mu un jade, ko si nnkan to kan wa pelu awon Sogbo atawon ile olomooba to ku. Won n lo won lati dojuko wa ni, ko si tu irun kankan lara wa.

Ayalegbe lawon Aderohunmu lodo wa, won o lagboole, awon Oluode kan tie jinna si wa gedegbe.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, January 23 @ 03:17:46 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Oro Oba Ataoja: Omooba Adeleke Ni Ayederu Lawon Idile Aderohunmu Ati Olude, Won" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: