Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Pako Ni Adekola La Mo Johnson Lori Lojo Keresimesi, Niyen Ba Ku Patapata
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Pako Ni Adekola La Mo Johnson Lori Lojo Keresimesi, Niyen Ba Ku Patapata

Bi gbogbo awon eeyan se se ayeye odun Keresimesi ati odun tuntun to koja lo yii pelu idunnu ati ayo, inu ibanuje ati ekun lawon molebi omodekunrin kan ti se tiwon niluu Osogbo ti i se olu ilu ipinle Osun. Idi ni pe ojo yii gan-an ni eni kan da emi okan lara awon omo won, Johnson Michael, to je eni odun mejilelogun legbodo.

Sebi ise ki i pa ni, ayo lo maa n pa ni lawon agbalagba maa n wi, ayeye Keresimesi lawon odo adugbo Ekotedo, niluu Osogbo, korajo lati se, ti oro naa si yiwo laarin oru.Gege bi a se gbo, won ti bere ayeye naa lojumomo ti ko si wahala kankan titi di nnkan bii aago kan oru ti ede aiyede be sile laarin won. Bayii ni won ni omokunrin kan, Adekola Adelugba, loo gbe pako nla kan, to si jan an mo Johnson niwaju ori, Nise niyen subu lule, to si daku lo rangbandan. Ki won too mo nnkan to n sele, Johnson ti koja sajule orun.

Se koju ma ribi, gbogbo ara loogun re, kia ni pati ti daru, ti onikaluku awon odo yii si bese won soro, sugbon ko pe ti owo fi te Adekola ti won fesun kan, ti won si fi pamo si akolo awon olopaa.

Lose to koja ti won mu Adekola, omo ogun odun yii wa si kootu majisreeti tilu Osogbo, esun meji otooto to ni i se pelu idite ati ipaniyan ni won fi kan an. Gege bi agbejoro fun ileese olopaa lori oro naa, Inspekito Meret Wilson se wi, awon ese ti Adekola se lodi, o si nijiya nla labe ofin iwa odaran tipinle Osun.

Gbogbo akitiyan agbejoro fun olujejo, Ogbeni Abimbola Ige, lati wi awijare fun onibaara re ni ko so eso rere latari iru esun ti won fi kan an, bee ni ile-ejo ko faaye kankan sile fun un lati wi awijare kankan rara.

Ninu idajo re, Olusola Aluko, pase pe ki won loo fi Adekola pamo sogba ewon nla ti ilu Ilesa titi digba ti imoran yoo fi wa lori esun ti won fi kan an lati odo adari eka to n ri si idajo awon araalu, iyen Director of Public Prosecution (DPP).

Leyin naa ni Aluko waa sun igbejo lori esun naa siwaju di ojo kerinlelogun, osu kin-in-ni, odun yii.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, January 23 @ 03:22:15 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Pako Ni Adekola La Mo Johnson Lori Lojo Keresimesi, Niyen Ba Ku Patapata" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: