Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Taye To Gun Olokada Obe Lorun L’Omu-Aran Ti N Kawo Ponyin Rojo
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

Taye To Gun Olokada Oobe Lorun L’Omu-Aran Ti N Kawo Ponyin Rojo

Iwaju adajo kan niluu Omu-Aran ni ogbologbo adigunjale kan, Ogbeni Taye Adeoye, to gun olokada kan, Biodun Babalola lobe lorun, to si gbowo nla lowo e ti n kawo ponyin rojo bayii, o si daju pe bi ejo ohun se n lo yii, yoo sewon.

Ninu iwadii akoroyin wa la ti gbo pe opopona ilu Etan si ilu Omu-Aran lokunrin ole yii ati ekeji e toruko re n je Femi Adegbite, eni to ti sa lo bayii ti pe okunrin olokada yii pe ko gbe awon de ilu Otun-Ekiti.Olokada yii so pe oun yoo gba egberin naira lowo won, sugbon awon mejeeji so pe egbeta naira lawon yoo san fun un, niyen ba gbe won. Bi won se n lo loju ona, lawon mejeeji fa obe yo si olokada yii ti won si so fun un pe ko ya sinu igbo. Lakooko naa ni won gun un lobe lorun, won gba egberun marun-un naira lowo e, leyin e ni won sa wonu igbo lo. Sugbon ko pe towo fi te Taye, eni to daruko ekeji e ti won jo n sise ibi naa. Leyin eyi ni won wo Taye lo si ile-ejo kan to wa niluu Omu-Aran, to si n kawo ponyin rojo niwaju adajo.
Lakooko igbejo ni Ogbeni Biodun to je olokada naa so fun ile-ejo pe nise lawon eeyan naa fee pa oun patapata, sugbon bi won se ri egberun marun-un fa yo lapo oun lo mu ki won fi oun sile, ti won si sa lo ko too di pe owo te Taye.

Nigba ti Adajo Abolade Banigbe ti kootu ohun yoo soro, o ni iwadii si n te siwaju lori esun naa, o waa pase pe ki won ju adigunjale naa satimole ogba ewon titi di igba ti won yoo pari iwadii lori esun naa, tigbejo yoo si te siwaju.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, January 23 @ 03:29:57 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Taye To Gun Olokada Obe Lorun L’Omu-Aran Ti N Kawo Ponyin Rojo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: