Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Wahala Nileewe Giga (University) Obafemi Awolowo Lori Atako Niqab Iboju-eleyinju
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Mujidat Iyanda ati Alade Lawal, Ile-Ife

Wahala Nileewe Giga (University) Obafemi Awolowo Lori Atako Niqab Iboju-eleyinju-ege Awon Omobirin Musulumi

Adura awon babanla wa ninu Islam nile Yoruba ni wipe: Ki Olorun pana adebo re ki O si gbe Sunnah Anabi ga.  Eyi je bee nitori wipe awon eni-esu ti nwon je eni ina yio se wahala lati te esu lorun ti nwon yio fi ba a wona Jahanama to bee gee bi awon ero Alujana naa yio se ko wahala nipase tite Olohun lorun lati wo Ogba-Idera Ogba Alujana. Idije laarin awon ti Olohun ati awon ti esu ti bere ni perewu bayii nileewe giga Obafemi Awolowo.  Ko si Musulumi ti aseju awon osebo ati awon alakatakiti esin Keferi gbogbo fee ba lojoji mo nile Yoruba. Sugbon ni bayi awon ile iwe giga ile Yoruba ni on ti awon ota Islam n gba lati maa dana ote nwon ni jijo woroworo. Asiri awon alabuku Keferi yii ti bere si ni tu.

Nwon tun ti gbe ise won de o. Bi e ba bi wa wipe bawo tun ni o, o to bee.  Paje baleru awon Keferi, iro pata lasan ni!  Bee naa sini gbogbo ariwo "Fir, Fire" awon Keferi alatewo, ara nwon to n gbona ni ina ti n jo woroworo!!  Awon elebo ile Yoruba n daamu pupo ti awon elegbe nwon ninu awon alakatakiti esin Keferi toku nileewe giga Obafemi Awolowo niluu Ile-Ife paapa ko ni isimi lori ati pana Olohun ti i se Islam.  Bee sini Olohun ti se asepe titan Ina-Imole Re ti i se Esin Islam.  Sugbon ko ye awon alaimokan.  Oju ti bere si ni tina osan awon ota Musulumi ni Fasiti Obafemi Awolowo bayii. Gbogbo asiri iro, ote ati tembelekun awon ota Esin Islam Esin Alaafia ni o ti bere si ni tu sita nileewe giga naa bayi nipa iwa aburu ati eleyameya ti die ninu awon asiwaju ileewe giga naa dawole lori oro imura Niqab Iboju-eleyinju-ege fun awon omobirin Musulumi.


Ti o ba je wipe looto ni wipe awon baba wa ni ile Yoruba a maa powe kan pe ofin ti a ba tori omo se, a ko gbodo tori eru yi i pada, ilu ti ko ba si sofin, ese ko si nibe. Idi wo gan wa ni awon osebo ati awon alakatakiti esin nileewe naa fi n dana ote fun awon Musulumi obirin ti nwon n se Esin Islam daradara nileewe naa ti nwon n si n wo Niqab Iboju-eleyinju-ege gege bi Sunnah ati eto ninu ilana Esin Islam? 

Isele ti o sele si awon akeko omobirin ti won je Musulumi to n mura esin Niqab Iboju-eleyinju-ege ni ogba ileewe giga Obafemi Awolowo niluu Ile-Ife yi buru tobee ge ti ninu nwon fi so wipe ayafi ki awon yio bere sini maa ja agbeleebu lorun awon Kiriyo naa kaka ki awon maa mura esin awon mo. Oun to sele ni pe awon Keferi ninu awon alase ati awon akekoo dite bayii pe ko si oun to jo imura Niqab Iboju-eleyinju-ege mo.

Ileewe giga yi koi se aimo foloko ninu akitiyan re lati maa gbese esu laruge ati lati maa tako esin Olohun Islam. Otito ni wipe ni gbogbo orile alowo eeyan dudu ati ni gbogbo agbaiye, ileewe giga Obafemi Awolowo n'Ile-Ife ni asiwaju ninu gbigbe ibose-bope ati bibo orisha laruge. Eyi ti o je pataki julo ni wipe ile iwe giga yi ko je didasile fun awon osebo ati awon alakatakiti esin yoku nikan.  Nigbati awon oponu ninu awon alase ile-iwe yii ba ti fi aaye gba awon osebo ki nwo maa wo aso-ibile ati awon Kiriyo ki nwon maa wo agbeleebu si orun, ko si eto ki awon Musulumi omobirin ti o n mura Niqab Iboju-eleyinju-ege yii maa mura bi esin nwon ti gba ni tiwon.

Iwe Iroyin Yoruba se akiyesi wipe laipe yii ni oro naa tun waye bo ti maa n sele tele, sugbon ti eyi le ju tateyinwa lo, o si ku die ko di wahala nla. Ohun ti akoroyin Yoruba kan so ni wipe ooto ni pe awon alase maa n gba awon Kristeni ati Musulumi laaye lati maa lo awon ibikan ninu ogba naa fun isin won. Won maa n lo gbongan kan ti won n pe ni Cafeteria ninu ile gbigbe awon akekoo ti won n pe ni Fajuyi Hall ati Awolowo Hall nigbakugba, eyi lo si fa bi awon to da wahala yii sile se foju tembelu awon Musulumi ati eto isin nwon. Se eniti a ba sun ti ni a n jarunpa lu! Awon osebo Yoruba feran lati maa jaye familete-n-tuto ninu ile iwe giga yii.

Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi han pe awon ti nwo npe ara nwon ni eso alaabo inu ogba naa ki omobinrin Musulumi kan to n mura Niqab Iboju-eleyinju-ege ninu Esin Islam mole laarin ogba. Bi nown fe fi tipa baa lasepo ni tabi nwon fe fi tipa ri ihoho re, die ninu awon ti isele naa soju ni oro naa ye. Eyi lo mu omokunrin kan, Abdusalam Bushral, ko awon omo Musulumi egbe re jo ti o si funwon niro iwa buruku ti awon eni esu ti nwon n pe ara won ni osise aabo naa n wu si omobirin ti o n mura Niqab Iboju-eleyinju-ege yii.

Ni kese ti awon odo Musulumi egbe Abdusalam gbo isele aburu yii ni nwon mura igbenija fun omobirin amura Iboju-eleyinju-ege yi.  Abdusalam Bushral si ko awon Musulumi akeko egbere leyin lati loo gba omobinrin naa sile lowo awon eni-esu naa. Ohun ti awon Abdusalam so ni pe won ko letoo lati huwa ibaje tabi iwa ifiniwole si omobirin yii.  Ko ju bayen lo.  Ayafi bi awon Keferi yii se fi aake kori ti nwon tu ito soke ti nwo fi oju gba a.  Ti nwon ni o ku ibi ti awon omo Musulumi yio gbe e gba ninu ogba ile iwe giga naa ati wipe eto awon gege bi osise aabo ni lati se ohunkohun ti o ba wu awon si enikeni ninu awon omobirin Muslumi to n mura Niqab Iboju-eleyinju-ege ninu ile iwe giga naa.

Oro yi aboro mii!  Ko pe ko jina ti awon odo Musulumi yi lo jijagbara fun omobirin Musulumi yii ni awon Keferi kora nwon jo ti nwon si bere si ni dana ote.  Oro yii da wahala nla sile nigba tawon ota Olohun yii kora won jo pe ko ye ki awon omorere Musulumi yi se jijagbara fun ara nwon.  Aroye nwon ni wipe ko si nnkan to jo jija fun eto esin tabi imura Iboju-eleyinju-ege esin Islam ninu iwe ti won fi gba won wole. Ninu awawi nwon ni pe awon Alahusa ti a mo si Boko Haraamu le lo eyi lati se ijamba nitori eeyan ko le mo eni to wa ninu aso ti won fi n boju, paapaa pelu ayeye aadota odun ti ileewe naa n se lowo nigba naa, topo eeyan si n ya wo ibe. 

Se ti elebo yio ba kuro gbogbo igba ni eleri Obatala nwon maa nwa ni orun bi ko ba si iledi mo. Sebi araorun ni o ma n wa ninu eku nwon, alaaye si ni awon omo Musulumi tiwa yi nigb gbogbo. Ko sele ri ki awon Boko Haram mura esin Niqab Iboju-eleyinju-ege lati lo se ise tiwon.  Eyi ti o fojuhan gbangba ni wipe awawi lasan ni awon elebo to darapo mo awon Kristeni woyii n wa wi nitori pe awon Boko Haram tabi awon omo Ibo ati awon omo lehin Apanijoga eleyameya Ojukwu ti nwon n da wahala sile ti nwon n pa kukuru ti nwon n pa gigun lati bi aadorin odun ti Naijiria ti darapo kii mura esin lati koju ija si enikeni.  Awon Boko Haram paapa ki i lo imura esin rara lati farapamo. Idi niwipe nwon ko fe ki aawo wa laarin awon ati awon Musulumi agbesinye ati agbesinga kari aiye. Awon Boko Haram ki i se oponu debi wipe won yio gba ona ti oju yio fi tete wa lara nwon fi sise tabi ona ti owo yio fi tete te nwon lori irinsi nwon.  Ko si eniti ko mo wipe ni ile Yoruba loni, oju le tete wa lara eniti o ba mura Niqab Iboju-eleyinju-ege ju eniti o kan mura gege Sade Sandy arinhoho. O ti han gbangba bayi wipe ironu awon Keferi ko to nkan atiwipe lori awon ete nwon ko si arojinle ni be. Ododo ni oro Olohun lori opolo ti o ku die kaato fun nwon - ti nwon ba ni opolo paapa.

Ohun ti akoroyin Yoruba gbo ni pe die lo ku koro naa di ija esin, awon alase ileewe naa lo pana aawo to fee sele ohun. Ni bayi ti oju-ode awon oniro ti da ti opuro nwon si ti mule mofo. Opolopo ninu awon omobirin Musulumi ti koi mura Niqab Iboju-eleyinju-ege tele ni nwon ti n gbero lati maa mura esin bayii.  Pelu eyi, awon alase ti so pe iwe ni gbogbo awon akekoo waa ka, ko si ye ki won maa da ofin elesin-mesin ati eleya-meya ti ara nwon sile nitori ati gbogun ti esin Musulumi tabi nitori ati maa dogbon wu iwa-ibaje loruko awon osise-aabo tabi awon agbofinro inu ile iwe giga naa.

Ninu awon alase naa ti so wipe awon ko ni i gba fun enikeni to ba tapa sofin ati agbekale ileewe naa laaye lati da omi alaafia re ru nipa lilodi si eto awon omobirin elesin Islam tabi fifi nwon wole. Se bi a ti bi eru ni a bi omo.  Ati wipe ojulowo omo Oduduwa ni awon Musulumi Yoruba paapa. Omoluabi ni nwon laarin omo Yoruba ati nibi gbogbo kari aiye. Awon Musulumi ki i se eru rara, ko si to ki enikeni maa bawon lo bi eru tabi fi eto nwon duwon gege bi omo-orile ede yii.  Enikeni ti o ba tapa si eto awom Musulumi n fi owo fa wahala ni. Nigbati eto awon Kiriyo baa ti fi aaye gba nwon ki won maa wo agbeleebu kaakiri tabi ki awon elebo maa wo ounkoun ti nwon ba n wo, aaye gbodo gba awon omobirin Musulumi ti o ba fe lati maa mura Niqab Iboju-eleyinju-ege.

Iwadii awon oniroyin Yoruba tun fi han pe awon alase ati Imaamu agba Obafemi Awolowo ti n gbe igbese lati fopin si iwa ibaje awon osise aabo yii.  Eyi lo fa ti igbese miran fi n waye lat fi opin si eto esu ati iwa ibaje ki awon akekoo obinrin kan maa gbe ninu gbongan ti won ti n kirun ninu ile tawon okunrin n gbe ni Fajuyi ati Awolowo pelu lilo-bibo awon omokurin ti n sise aabo pelu awon ale omobirin nwon to n ri ihoho tabi to n mura aito lati di awon t nwon n kirun lowo.

Ohunkohun ti o ba ti gbogbo igbese awon asofin ile iwe giga naa jade, koko ni wipe awon omobirin Musulumi yii ati awon odo Musulumi lokurin bii ajafeto Abdusalam Bushral yii wuyi gan an.  Igbese nwon ati iwa akinkanju yi wu ni lori pupo.  Akin-omo ati olu-omo ni nwon lokunrin ati lobirin.  Awon okurin nwon ko jale ki enikeni fi eto dun awon eniyan nwon lobirin tabi dun mohuni-mohuni mo nwon.  Eto nwon ni gege bi nwon ti ko jale lati maa rinhoho ni ikose opolopo awon egbe nwon ninu awon omo Keferi ti n fedi sile kiri ti nwon si n fi ara nwon se eleya.  Adura opolopo ti o gbo nipa isele yi fun awon omo Musulumi yi ni ki Olohun Oba Oga-Ogo fun won ni opolopo suru, imo ati oye lati maa dajuko gbogbo isoro ati tembelekun ote ti awon Keferi yio ma gbe siwaju nwon ninu ileewe giga Obafemi Awolowo n'Ile-Ife yi ati nibi gbogbo.

Ki Olohun Oba Alase tii se Alaabo-Julo pa ina awon adebo re ki o si gbe Sunna Anabi ga (Amin).  Sunna ni imura Niqab Iboju-eleyinju-ege. Ki awon omobirin waa naa mura sii.  Ki Olohun ti o se wa ni ero-Alujana nipase Islam maa yo ese gbgbo wa kuro lori Esin Islam Esin Asinla ti a wa yii (Amin).
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, January 23 @ 04:36:27 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Wahala Nileewe Giga (University) Obafemi Awolowo Lori Atako Niqab Iboju-eleyinju" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: