Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Wahala De! Won Yinbon Pa Beyioku, Igbakeji Alaga Egbe Onimoto N’Ibadan
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Abayomi Akanni, Ogbomoso

Wahala De! Won Yinbon Pa Beyioku, Igbakeji Alaga Egbe Onimoto N’Ibadan

Ajalu nla ti sele si egbe awako, NURTW, eka tipinle Oyo lopin ose to koja nigba ti igbakeji alaga won, Alaaji Kamorudeen Beyioku, ku leyin ojo merin ti awon agbebon kan yinbon fun un. Awon dokita gbiyanju lati gba emi okunrin naa la, sugbon o teriba fun iku lojo Satide to koja nileewosan ekose isegun, UCH, n’Ibadan.

Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi han pe leyin tawon agbebon naa sise owo won tan ti won si gbe Alaaji Beyioku lo sile iwosan, nise lawon olopaa duro ti i ni yara ti won ti n fun alaisan ni itoju to peye to wa.Awon dokita gbiyanju lori re fun ojo merin gbako to fi wa ni ipo naa, sugbon pabo ni wahala won pada ja si.
Nigba to n soro lori isele naa, Alukoro ileese olopaa ipinle Oyo, Ogbeni Ayodele Lanade, so pe awon olopaa naa wa nibe lati daabo to peye bo o, nitori awon onise ibi naa le pada wa.

Te o ba gbagbe, ojo kokanlelogun, osu to koja, ni won se ifilole igbimo ti Alaaji Beyioku wa yii. Won fun un ni ipo igbakeji alaga ohun leyin bii odun meta ti ko si igbimo to n dari egbe awako naa. Pelu nnkan to sele yii, ko seni to mo ohun ti yoo tun be sile ninu egbe awon awako ohun bayii.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, February 28 @ 04:30:36 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Wahala De! Won Yinbon Pa Beyioku, Igbakeji Alaga Egbe Onimoto N’Ibadan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: