Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
[ Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose ]

·Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi
·Eyi Ni Bi Pasito Se Gbe Majele Je Ni Ipinle-Ogun
·Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
·Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
·Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
·Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
·Orekunrin Bukola Fee Fi i Soogun Owo N'Ibadan
·Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo
·Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ope O! Owo olopaa Ti Te Awon To Ge Oori Aliya, Omo Odun Meta N’Ilorin
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

Ope o! Owo olopaa Ti Te Awon To Ge Oori Aliya, Omo Odun Meta N’Ilorin

Owe awon agba to so pe biro ba lo logun odun, ojo kan soso loooto yoo ba a lo se mo awon odaran meji kan lara laipe yii, iyen Ogbeni Abdulrasheed ati Jamiu, ti won so pe won ge ori ati eya ara Aliya omo odun meta soogun owo n«Ilorin. Awon olopaa ti wo won lo si kootu lori esun pe won ba eegun eeyan, igba ose dudu, igba eyin ijapa dudu, oogun abenu gongo ati bee bee lo ninu yara okan ninu won, eyi to fidi e mule pe awon lo sise ibi naa.

Ohun to ya awon eeyan lenu to si mu kawon ero iworan to wa ni kootu majisreeti naa maa so pe aye yii ma le ni pe aburo baba omo ohun ni Abdulrasheed Usman to je okan ninu awon meji ti won mu fesun ipaniyan naa, awon yooku ti won jo sise ibi naa ti sa lo.Sugbon won ni eje eeyan to n daamu awon odaran naa lo tu asiri won towo fi te won. Idi ni pe lojo keji isele naa, iyen ojo kejo, osu kin-in-ni, odun yii lawon eeyan ri Jamiu nibi ti won ju oku omo naa si. Eyin windo ile Abdulrasheed ni won ti ri oku e ti won si ti ge kinni e, ese kan ati apa kan, leyin e ni won tun ko ifun e lo.

A gbo pe dipo ki Abdulrasheed salaye ara e nigba ti won n bi i pe ki lo mo nipa iku Aliya, nise lo n wo boo bii ori eran, eyi lawon eeyan se so pe dajudaju oun lo pa omo egbon e lati soogun owo.

Nigba ti baba omo naa, iyen Ogbeni Tajudeen Usman ri i pe isele naa waye lo ti lo si tesan olopaa iyen C Division to wa n«Ilorin lati foro naa to won leti. O so fun won pe aburo oun, Abdulrasheed to n gbe ni ojule kokandinlogbon, ile Onigbooro, to wa lagbegbe Ita Ogunbo, ati Ogbeni Jamiu to n gbe ile Ayede-Mejiro, to wa niluu Ote, nijoba ibile Asa, loun fura si pe won sise ibi naa. Kia lawon olopaa mu won ti won gbe won ju satimole, lati igba naa ni wahala won pelu awon olopaa ti bere ti won si n foro wa won lenu wo. Ni kootu ohun ni Iwe Iroyin Yoruba ti gbo pe lakooko tawon omo naa n sere leyinkule laburo baba e yii tan an lati loo pa a. Lojo keji, laaaro kutu hai lawon eeyan ri oku omo naa ti won ti ge ori, ese, owo ati kinni e lo. Bakan naa lawon obayeje ohun tun ko ifun omo naa ki won too ju ori e saatan kan to wa leyinkule won ti won si so ara omo naa yooku sinu salanga.

Lara awon molebi ti won jo n wa omo naa kiri ni won ri oku e nibi tawon obayeje yii so o si.

Ninu akosile awon olopaa, a gbo pe Jamiu wa lara awon odaran to n gbeeyan pa lati fi sowo, won si lo mo nipa ise ki won maa ji awon omo kekere gbe lati setutu owo daadaa.

Bakan naa ni won so pe awon mejeeji lawon olopaa ti foro wa lenu wo daadaa ti won si ti n fidi e mule pe won mo nipa iku omode yii.

Olopaa to n soju ijoba ni kootu naa, Ogbeni Nasiru Yusuf so pe esun meji ti won fi kan won ni igbimo-po sise ibi ati ipaniyan, eyi to so pe o tako ofin orile-ede yii. O salaye pe ese nla ni won da, fun idi eyi, ki adajo mase faaye beeli won sile rara nitori o se e se ki won sa lo.

Agbejoro awon olujejo naa, Amofin Ibrahim Shuaib, be adajo lati faaye beeli won sile nitori ofin odun 1999 so pe enikeni ko ti i le peeyan kan lodaran afi tiwadii ba pari lori iru esun bee, ati pe o tun digba tadajo ba gbe idajo e kale. O ro Adajo lati faaye beeli won sile lai foro naa fale rara.

Adajo Ibrahim Mohammed to n gbejo naa so pe ese nla to ga julo ni won fi kan awon eeyan naa, nitori naa, oun ko faaye beeli ti amofin naa beere sile. O ni ki won ko won satimole ogba ewon to wa ni Mandala. O waa sun igbejo mi-in sojo kejila, osu keji odun yii. Te o ba gbagbe, lati ojo kejo, osu kin-in-ni, odun yii, tawon molebi omo odun meta yii, Aliya Usman, ti ri oku e tawon eeyan ju sinu salanga ni won ti bere si i se opolopo adura lati tu asiri eni to pa a. A gbo pe gbogbo mosalasi metadinlogun to wa lagbegbe Ita Ogunbo, tisele naa ti waye n«Ilorin ni won ti n sadura akanse lori iku omo naa.

Bakan naa mi Emir Ilu Ilorin, Alaaji Ibrahim Zulu Gambari, naa ran eeyan wa sagboole naa lati ba won kedun, ti won si tun seto adura mi-in lati tu asiri eni to dan iru iwa naa wo. Eyi lawon eeyan se n so pe Olorun funra e lo tu asiri awon obayeje ohun, ti won si n gbe won sepe pe won o ni i bo ninu e.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, February 28 @ 04:49:24 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Ope O! Owo olopaa Ti Te Awon To Ge Oori Aliya, Omo Odun Meta N’Ilorin" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: