Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


N’Ibadan, Owo OPC Te Ganiyu To Maa N Mura Bii Omobinrin To Ba Fee Loo Jale
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

N’Ibadan, Owo OPC Te Ganiyu To Maa N Mura Bii Omobinrin To Ba Fee Loo Jale

Igbe ayo lo gba enu awon olugbe adugbo Omi-Adio, nijoba ibile Ido, nipinle Oyo, nigba towo awon OPC te ogbologboo adigunjale kan to ti n yo awon araadugbo naa atawon agbegbe to yi won ka lenu l«Ojobo, Tosde, to koja.O pe tawon olopaa, awon OPC, atawon alaabo ilu gbogbo ti n wa awon ole to maa n yo awon araadugbo naa lenu nitori won lo ti to osu marun-un tawon eni ibi ohun ti n fi okunkun boju pa awon eeyan lekun, sugbon to je pe gbogbo igbiyanju lati mu awon to wa nidii ise ibi naa lo ja si pabo.

Ase enikan soso lo ti n fooro won to bee latojo yii wa.

Ganiyu Salihu lo n je, won si jo n gbe laduugbo ni, sugbon enikan ko mo on nitori agbara oogun ati ete idigunjale to kun owo e.Iwe Iroyin Yoruba gbo pe bii obinrin ni Ganiyu, eni tawon tie tun mo si Ginniginni yii maa n mura bo ba n loo jale. Nigba mi-in, o le wo aso elehaa, tabi ko lo ibori bii tawon obinrin musulumu to pataki esin re de gongo. Eyi ni ki i je kenikeni le fura si i gege bii onise ibi.Sugbon bi ete to n lo yii ko ba fee sise, to di pe awon agbofinro fee mu un, were ni jagunlabi yoo lo afeeri, ti yoo si poora mo won loju bii ina to ti enu ibon jade. Ninu oro olori awon OPC lo ti ni, Nijeta. Ojobo, Tosde, laduugbo Abanla, Omi-Adio, nijoba ibile Ido, ni nnkan bii aago meta oru lawon lanloodu pariwo, Ole, ole, ole, Ganiyu Salihu lole yen. Okan ninu awon omo egbe wa kan toruko e n je Abiodun Oyan lo pe mi pe oun gburoo pe won n pariwo awon ole. Bi mo se lo sibe niyen.Biodun Oyan lo n le e bo. Bi mo se pade e nileewe St Andrews to n sa bo, mo ni ile mo e lonii, o ni ki i soun Gani. Bo se fi ogede bonu niyen, a si wa a ti lesekese.

Ko too debi to n lo, a ti pade nibe. Enu soobu e to maa n sago si la ti jo pade.Nje bawo le se waa mo pe ibi kan lo lo, okunrin olori awon OPC naa dahun pe, Owo awon baba mi lo ti wa.

Mi o le so pe mo lo ofe. Bo saa se n debe lawa naa debe. O tun fee lo ohun to lo lakooko, sugbon a ti te oju ese re. Ibi to ti waa juwo sile niyen, o gba kamu, a ba mu un pelu ada kekere to wa lowo e ati irin to fi maa n hale mo awon eeyan, atawon ero ibanisoro bii mesan-an.To ba fee jale, sokoto penpe nikan lo maa n wo, igba mi-in, aa lo aso elehaa tabi ko bori bii obinrin musulumi. A ti fa a le awon olopaa Apata lowo. Irin to se bii ibon lo fi maa n hale mo awon eeyan.

Ka ma puro, okunrin yen loogun, teeyan fi le jale fun odidi osu marun-un ti mi o ri i mu.

Sugbon nigba towo ti waa te e bayii, aa ko awon yooku e logbon pe ole ko dara. Awa naa ko si ni i foju awon ole sile niwon igba ta a ba si wa laye.Okunrin tawon eeyan e tun mo si Gani Ginniginni naa salaye pe, Omo Kogi ni mi. Ajara loruko mama mi. Mo ti wa lenu ise yii, o ti to odun meeedogun. Awa marun-un la jo n jale tele l«Ekoo, sugbon owo lo dija sile laarin wa temi fi pinya pelu won, ti mo n da sise. O ni nitori e lawon eeyan se maa n pe oun ni Wan Man Mopol, eyi to tumo si eni bii igba loju ogun. O loun a ji nnkan l«Ekoo, oun a waa ta a n«Ibadan, toun ba jale n«Ibadan, oun a ta a s«Ekoo. Ori a¯ja¯ lo loun maa n gba wole. Bakan naa lo loun loun maa n ja baagi gba ni Soomeeli Abanla ti a maa kan ka too de Omi-Adio.Okunrin to pe ara e leni odun mokandinlogbon yii so pe, O ya mi lenu bi won se mu mi, nitori ise to wa lara mi da mi loju.

Emi ki i se aajo nile yii, Abule Egba ni won ti n sise fun mi. Ile kile ti mo ba de, ti mo ba fi le ka owo atese le ara ogiri ibe, ti ma a fi ko gbogbo awon eru inu ile yen tan, ko seni to maa mo.Latigba ti mo ti wa lomo odun merin ni iya mi ti gbe mi sile. Baba mi ti ku tipe. Odo iyawo baba mi ni mo n gbe ni Omi-Adio ki n too ba ise aje lo s«Ekoo.Mo maa n fi aso elehaa bori kawon eeyan ma baa da mi mo. Ojo kefa, osu yii, ti mo lo, awon ode ti mo ri ni ko je ki n le raaye wole ti mo fi lo.

Ti mo ba wa nibi kan tawon ode ba wa nibe, to ba je ode to le, ara maa fu mi, lesekese si ni mo maa kuro nibe.Awon araadugbo Omi ti won ba Iwe Iroyin Yoruba soro ro awon olopaa lati ma se fi okunrin naa sile lai se pe o jiya ese to se nitori pe o pe to ti n ko awon sinu hilahilo.O ti koko lo saduugbo yen lojo Aiku, Sannde, ojo kefa, osu kin-in-ni, odun yii, lasiko ti won n senawo, sugbon ko ri i wo. O jewo pe oun loun wa nidii gbogbo idigunjale adugbo ohun. Ise DJ ni won lo n se l«Omi Adio.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, February 28 @ 04:56:22 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"N’Ibadan, Owo OPC Te Ganiyu To Maa N Mura Bii Omobinrin To Ba Fee Loo Jale" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: