Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
[ Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere ]

·Ijoba Ipinle Osun Ti Ki Oselu Bo Eto-eko O - Awon Eeyan Iwo-Oorun Osun Ke Gbajar
·Awon Aare Agbaye N Se Idaro Iku Robert Mugabe, E Gbo Nnkan Ti Obasanjo So
·Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
·Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
·O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
·Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
·Nitori Bi Won Ko Se Rowo Osu Gba, Awon Osise Di Onibaara Nipinle Oyo
·Nitori Owo Osu, , Edet Be Ori Omo Oga e N'Ijebu Ife
·Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Yoo Soro Lati Mu Eegun To Pa Alfa, Nitori Ara Orun Ni Eyi Ni Awawi Awon Olopaa
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Johnson Akinpelu, Abeokuta

Yoo Soro Lati Mu Eegun To Pa Alfa, Nitori Ara Orun Ni — Eyi Ni Awawi Awon Olopaa

‘Isoro nla ni fun wa lati mu eegun to sokunfa iku Alfa kan ni Ijaye, niluu Abeokuta, lojo Sannde to koja lohun-un nitori ara orun ni.’ OÙgbeni Ikemefuna Okoye to je Komisanna fawon olopaa nipinle Ogun lo salaye oro yii lose to koja nigba to n safihan awon meta towo te lori esun naa. Osalaye pe loooto lawon ti mu awon to wa laye ti won fura si, sugbon eegun gan-an to sokunfa iku Alfa naa lawon ko mo, nitori ko seni to le so pato pe eni bayii lo wa ninu eku naa.

Awon meta towo te lori esun naa ni Alagba Shitu Adeyemi, eni odun mokanlelogota Waidi Babalola, eni odun merinlelogota ati Ajani Olabimtan, eni ogoji odun. Latojo tisele naa ti waye lawon towo te naa ti wa ni Eleweran, nibi ti won ti n fowo-sowo-po pelu awon olopaa.Sugbon titi di akoko yii, ko seni to mobi toro naa yoo yori si nitori pelu gbogbo akitiyan awon olopaa lati pese eto aabo, won lawon musulumi kan si n leri labele lati gbesan ohun to sele naa. Nje bawo gan-an ni wahala naa se bere to fi di pe Eegun pa Alfa? Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi ye wa pe lati bii ojo meloo kan seyin lawon eleegun ti n sodun won ni Ijaye, eyi ti won maa n se lodoodun; ojo metadinlogun ni won si fi n se e. Lojo Aiku to koja lo lohun-un tisele naa waye, eleegun kan ti won n pe ni Leyin Aponle sugbon ti oruko e gan-an n je Kasimu Dada lo jade gege bo se maa n jade lodun meta meta. Iwe Iroyin Yoruba gbo pe bi won se de Ijaye ni won pade awon oloosa obinrin ti won n pe ni Elerinle, eewo si ni ki eleegun ati oloosa pade; n ni won ba n ro awon oloosa naa pe ki won gba ibomi-in ki eleegun le koja. Eyi lo da ede aiyede sile ti won si bere si i yinbon.

Ota ibon yii lo loo ba Alfa ti won pe oruko e ni Lateef Sabiu lori okada to wa to si gbabe ku patapata. Ko seni to le so pato ibi ti ibon naa ti wa nitori lojiji ni won so pe won yin in.

Idi niyi tawon kan fi n so pe eegun lo yinbon naa.

Iwadii tun fi ye wa pe ki i se pe awon eleegun atawon musulumi lagbegbe naa nija ti tele ko too di pe won yinbon mora won. Awon eeyan tie koko ro pe okan lara awon omo eyin eleegun lo ku, sugbon leyin-o-reyin ni won gbo pe Alfa ni onitohun, ati pe awon meta lo wa lori okada lojo naa.

Bile ojo keji ti i se ojo Aje, Monde, se mo lawon odo musulumi kan ti tu sita ti won si n fehonu won han, ojo naa ni won dana sun ile baba omo to gbe eegun naa to wa ni Ijaye. Bi ki i baa se pe won tete da awon olopaa sigboro paapaa, nnkan taa ba maa wi ko la n wi yii pelu bo se je pe awon odo musulumi yari pata, o si ku die ki won so o dija esin.

Titi di akoko ti a n ko iroyin yii lowo, ipade olokan-o-jokan lo si n lo lowo niluu Abeokuta laarin awon olori esin Islam atawon eleegun, eyi ti won ni won n se pupo e lodo Alake tile Egba, Oba Adedotun Gbadebo.

Oniroyin wa ba awon eeyan meta ti won fura si naa soro lori ohun ti won mo nipa isele naa.

Ohun ti onikaluku won so ree: Waidi Babalola Oruko mi ni Oloye Waidi Babalola, emi ni Balogun Oje, Ago Isaga ni mo n gbe niluu Eko, ise dereba ni mo n se. Ojo Eti, Fraide, to koja lohun-un ni mo ti de fun odun naa.

Aaro ojo Aje, Monde, ni Alapinni waa pe mi pe Leyin Aponle tun ti da wahala sile o. Kasimu Dada ni oruko e gan-an, sugbon oruko eegun ile won ni won fi n pe e. Mo da a lohun pe sebi a ti so fun omo naa pe ko ma gbe eegun mo. Alapinni loro naa ko ye oun, o ni awon Alaafa ti n sara won jo o, ajalu si le tibe sele. Ko pe to pe mi ni mo gbo pawon Aafaa naa ti loo sun ile eleegun naa. Loju-ese la ti loo so fun eleegun Egba nitori a ni Alapinni, bee la tun lo sodo Baba Oluwo ni Ibara nitori oun ni Aare gbogbo wa.

Aare waa so pe ka loo so fawon olopaa Oke Itoku, nigba ta a debe ni won tun ni a gbodo de Eleweran, ka kan loo so tenu wa lohun-un ni, sugbon nigba ta a de Eleweran nibi ni won so pe a o le lo sile, won ni die lara awon ti won fura si ni wa.

“Eko ni Kasimu to gbe eegun yen ti maa n wa, nitori wahala e to po la se fofin de e pe ko ma gbe eegun mo. Awa o si nibe, oga e lo le so boro se je nitori o so pe awon elegbe okunkun lo yinbon. E joo, ki won tu wa sile o.’’ Ajani Olabimtan Oruko mi ni Ajani Olabimtan, omo ogoji odun ni mi, mo n gbe ni Ijeun Titun, niluu Abeokuta. Ise dereba ni mo n se. Se e ri eni to gbe eegun lojo naa, omoose mi ni, Kasimu si ni oruko e. Oti pe to ti n sise lodo mi, mi o si gbo pe o daran ri.

Lojo Aiku, Sannde, ti wahala naa be sile, bi a se jade ta a fee de aarin titi Ijaye, a pade awon oloosa. Eewo si ni, eleegun ati oloosa o gbodo pade, idi niyi ta a fi loo mu eegun naa pamo sinu ibi kan. Emi ni mo loo ba awon olorisa naa ti mo n be won pe n ki won loo gba ona Oja Aaro, ki eegun si gbona mi-in ki won ma baa foju rira won. Elerinle ni won pe awon olorisa naa, obinrin ni won, won si gbe eru sori.

Eegun gan-an ko mo nnkan to sele, nitori a mu un pamo ni, bi mo se n bo lati so fawon yooku pe a ti yanju e, lojiji la ri awon omo egbe okunkun kan lori okada ti won ti se okan ninu won lese, boya won loo ja ni ko seni to mo, sugbon bi won se de aarin awa eegun lokan ninu won yo ibon lori okada to si yin in. Nnkan to da mi loju ni, mo da onitohun mo. Bi a se gbo iro ibon ni gbogbo wa tuka atawon eeyan to n wo eegun, emi naa sapamo, nigba ti won lo tan ni mo jade pada, ti mo ri okunrin ti ibon ba naa ko ti i ku rara, mo sare si i, nitori okan lara awon omo eyin wa ni mo pe e, sugbon ko seni to waa ba mi lemi naa fi kuro nibe.

Mo ti so fawon olopaa pe ti won ba le ran mi lowo, a maa ri awon to yinbon naa, omo egbe okunkun ni, mo ti ba a pade ri nibi tawon elegbe okunkun maa n duro si ni Sapon. Emi funra mi ni mo lo si tesan awon olopaa ti mo loo fejo sun lale ojo tisele naa waye, latigba naa ni won ti ti mi mole.

Mo fee so o di mimo pe eleegun ko lo pa Aafaa naa, awon egbe okunkun ni. Kin ni a fee pa a fun nigba ti ki i se pe a n bara wa ja tele.’’ Oloye Shitu Adeyemi Oruko mi ni Oloye Shitu Adeyemi, Alapinni ni mi niluu Ijaye. Eko ati Abeokuta ni mo n gbe papo, idi ni pe osoose ni mo maa n wa fun ipade awon Olojede. Ohun to sele ni pe a ti bere odun eegun logunjo, osu yii, ojo metadinlogun la si fi maa n se e.

Mo sese pari ayeye temi ni, owo si ti tan, ni mo ba so fun iyawo mi pe mo fee d’Ekoo lati loo mu owo. Bi mo se n de Alagbado ni nnkan bii aago meje ku ogun iseju ni Balogun pe mi pe ki n maa bo pada si Abeokuta, wahala ti sele o.

Loju-ese ni mo pada ti mo loo ba Balogun ti a bere igbese lori wahala naa, a fee waa fejo sun ni tesan awon olopaa, lawon olopaa de wa mole pe a wa lara awon ti won fura si. A ko mo nnkan kan nipa e.

Iwe Iroyin Yoruba tun se iwadii nipa odomokunrin Afaa ti won yinbon pa naa, Lateef Sabiu lomo naa n je, eni odun mejilelogun si ni. Omo ijo Nuraindeen Islamic to wa ni Iporo Ake ni won pe e. Adugbo Isale Ijeun ni won lo n gbe.

Gege bi Sheu Ibrahim Eniyo to je oga Lateef se wi, odomokunrin naa je eni to gba esin gbo sugbon won ko je ki ala e se lori gbigbe esin Islam ga. Won ni ile e lo n lo lojo tisele naa waye. Iso Olo ni Ijaye, ni won sinku e si.

Ko ti i seni to mo ibi toro naa yoo ja si nitori awon eleegun n so pe awon ko lawon yibon, bee lawon olopaa n so pe yoo soro lati mu eegun nitori ara orun ni.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, February 28 @ 05:15:58 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Yoo Soro Lati Mu Eegun To Pa Alfa, Nitori Ara Orun Ni Eyi Ni Awawi Awon Olopaa" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: