Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ibrahim Yii Ma Daju O, O Si Ki Abileko To N Sise Jeje Ninu Oko Mole Niluu Ilora,
 
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Ibrahim Yii Ma Daju O, O Si Ki Abileko To N Sise Jeje Ninu Oko Mole Niluu Ilora, Lo Ba Ba A Sun Karakara

Bi obinrin eni odun marundinlaaadota kan, Abileko Peju Adeleke, ti a foruko e gan-an bo lasiiri ba mo pe okunrin kan, Ibrahim Cimeh, ti oun se loore yoo pada waa ja oun lole ara ni, dajudaju, iba ti tete ba ese re soro, sugbon aimo se e, ko si fura titi tokunrin ajeji naa fi ba eyin yo si i, to si ki i mole to fipa ba a lasepo karakara.

Okunrin eni odun marundinlogoji naa to je omo bibi orile-ede Benin lo ka obinrin opo to ti bimo mefa yii mo inu igbo ni nnkan bii aago kan osan ojo Abameta, Satide, ojo kokandinlogun, osu kin-in-ni, odun yii, to si ja a lole ara pelu tipa-tikuuku.Agbe ologbin ewebe ni won pe obinrin yii. Aba ti won n pe ni Oloko lo da oko akuro si, sugbon ilu Ilora lo n gbe, nibe lo si ti maa n loo sise ogbin naa.

Gege b«Iwe Iroyin Yoruba se gbo, nibi ti Abileko Adeleke ti n sise lowo, to ti n bu omi rin oko akuro to gbin efo si ni Cimeh ti ba a, o toro omi mimu lowo e, obinrin naa si juwe odo to ti le romi pon fun un.

O pe tokunrin yii ti lo ko tun too pada wa. Iya arugbo yii tile ti gbagbe pe oun juwe ona odo fenikan. Lojiji ni okunrin omo Benin naa ba eyin yo si i, to si fi okun de e mogi leyin to ti fi lilu de gbogbo ara re ko too di pe o ba a sun ni tipatipa.

Irora nla la gbo pe obinrin opo yii ba lo sabule lati loo fi iroyin isele ohun to awon agba aba leti. Loju-ese lawon yen ti ta awon olopaa tesan Jobele, lolobo, ti won si fi panpe oba gbe omokunrin naa.

Leyin iwadii pajawiri tawon agbofinro yii se ni won gbe e lo si eka ileese olopaa to n sewadii esun odaran gbogbo n«Ibadan fun iwadii ijinle lori isele naa.

Nigba to n royin ohun tokunrin naa foju e ri ninu igbo, Abileko naa salaye pe, Inu oko mi ni mo wa tokunrin yen fi gbona odo mi koja pelu ada ati keegi funfun lowo. O ni ki n fun oun lomi, mo si juwe odo ti yoo ti pon on fun un. Mo kiyesi i pe mi o ri i ko koja pada, mo ro pe boya o ti gbona ibomi-in lo ni. Afi bi mo se ri i nigba ti mo setan ti mo ni ki n loo ponmi lati fi won awon ewebe mi.

Mi o mo pe enikan n tele mi bo leyin. Omi eleekefa ni mo ru to fi yo si mi lojiji. O bu mi so lati eyin, o ni oun maa fi ada yo oju mi setutu ti mo ba fi le jampata pelu oun. Mo be e, mo ni ko saanu mi nitori opo ni mi, mo si ti bimo mefa ki oko mi too ku sugbon ko gbo.

O ti mi lule pelu ike omi lori, mo subu, ike naa si fo. Lo ba bere si i lu mi. O fi ikuuku de gbogbo eegun ara mi, o waa n wo mi tuurutu nile, titi to fi wo mi deti odo. Mi o lagbara lati jampata mo nitori o ti re mi. Nigba to ya lo fi okun de mi lowo mo igi, o bo aso lara mi, bee lo tun fi sikeeti mi di mi loju, o si ba mi lasepo.

Nigba to da nnkan si mi lara tan to dide lo beere lowo mi pe se mo mo oun, mo ni mi o mo on. Nigba naa lo too tu mi sile to si ba tire lo.«« Obinrin yii te siwaju pe, Nigba to lo tan ni mo tu aso to fi bo mi loju kuro, ti mo si ra pala lo sinu abule, nibi ti mo ti fisele naa to awon agba leti. Won ni se mo da a mo, mo ni mo da a mo ti mo ba ri i, o n tiro ese rin bayii, ki i si i se omo ile yii.

Mo ro pe won ti mo on pelu apejuwe ti mo se yen. Won ba ni ki n ma wule mura pe mo n pada s«Iloraa, ki n kuku sun sabule lojo yen nitori ko bojumu ki n se bee pada pelu gbogbo oju mi to wu ati bo se wo mi nile to je pe gbogbo ara mi lo ti bo felefele.

Leyin e ni won ran awon omo won kan lati loo mu olopaa wa ti won si loo mu un nibi to n gbe l«Aba Oloko lojo keji. Bo tile je pe Ibrahim ti koko se kanle pe oun ko ba obinrin opo naa lasepo, o papa jewo nigba tawon olopaa yii mu un nibi ti ko ti le bo mo won lowo.

Nigba to n fidi isele ohun mule f«Iwe Iroyin Yoruba, okunrin eni odun marundinlogoji naa so pe loooto loun fipa ba iya olomo mefa naa sun sugbon ki i kuku se pe oun gbadun kinni ohun gan-an da bii alara. O ni oyin loun maa n ko kiri inu igbo ati pe ise yii loun n se lowo toun fi ri obinrin ohun nibi to ti n bu omi rin ogba ewebe re.

Gege bo se so, Oyin ni mo maa n ko kiri inu igbo ni temi. Nibi ti mo ti n wa oyin kiri ni mo ti ri i. Mo beere omi lowo e, o si juwee odo fun mi. Nigba ti mo mumi tan, mo jokoo, mo sinmi die. Leyin naa ni mo dide ti mo loo pade e lona ibi to ti n ponmi. Mo taari ike omi ori e danu, o bere si i be mi pe ki n saanu oun sugbon mi o da a lohun. Mo tu aso lara e, mo si bo awotele sokoto to wo sidii. Ni mo ba yo kinni mi jade ninu sokoto penpe ti mo wo sugbon ko le daadaa, n ni mo ba lo Tramol (oogun amarale) sugbon kinni mi ko le daadaa naa sibe.

Owo ni mo saa fi run kinni mi mo on labe. Mi o fi bee gbadun e sugbon mo da ato si i lara ki n too dide lori e.

Nje se loooto lo so obinrin yen mole ko too ba a sun, Cimeh dahun pe, Mi o de e lokun mole o, emi to je pe ese n dun mi, mi o lagbara iyen. Mo kan di i mu lasan ni, mo si ki kinni mi si i labe sugbon mi o da ato si i lara to bee ti mo fi dide lori e. Omo ilu Bembreke, lorile-ede Benin ni mi. O pe die ti mo ti de Naijiria, mi o ju omoodun meeedogun lo nigba naa. Mo ti gbe orisiirisii awon ilu bii Ogbomoso, Kisi, Igboho ati IlesaBaruba ati ilu Oyo ko too di pe mo renti yara kan si Abule Oloko.

Ibrahim salaye ara e siwaju pe, Omo marun-un niyaa mi bi, sugbon omo ti baba mi bi po nitori iyawo meta ni won fe, metalelogun ni gbogbo omo won lapapo. Baba mi ti ku, iya mi si wa laye sugbon won ti dagba. Emi nikan lokunrin ninu awon omo iya mi Nigba to n fidi isele yii mule, igbakeji oga agba awon olopaa nipinle Oyo, Ogbeni Clement Adoda, so pe okunrin afurasi odaran naa si n wulo fawon ninu iwadii awon, ati pe ni kete tawon ba pari re lawon yoo pe e lejo si kootu.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, February 28 @ 05:18:37 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Ibrahim Yii Ma Daju O, O Si Ki Abileko To N Sise Jeje Ninu Oko Mole Niluu Ilora," | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: