Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
[ Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu ]

·Iwosi Yii Si Ti N Po Ju Fun Yoruba, Ibi Ti Won Ba Wa De Ree O
·Bo Se Daa Niyen... Sugbon Kan Naa Lo Wa Nibe
·Bi Iro Ba Lo Logun Odun...
·Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
·Won Ni Alaga PDP Ku Sori Asewo N'Ipokia
·Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
·E Gbo! Kin Ni Fayose Wa Lo Si China?
·E Ko Sekeseke Si Won Lowo Jare
·Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nnkan De! Nitori Wahala To Sele Laarin Ofa Ati Erin-Ile, Ijoba Jawe Gbele-e Fawo
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

Nnkan De! Nitori Wahala To Sele Laarin Ofa Ati Erin-Ile, Ijoba Jawe Gbele-e Fawon Alaga Kansu Won

Oro aala ile to fa wahala nipinle Kwara laarin ilu Ofa ati Erin-Ile lose to koja ti gbona mi-in yo pelu bi ijoba se jawe gbele-e fawon alaga ijoba ibile tawon ilu mejeeji wa labe won ni ojo Aje, Monde ana. Esun ti won fi kan won ni pe apa won ko ka awon eeyan ilu ti won n sakoso le lori, eyi ti won ko fi le fopin si wahala to sele niluu naa lose to koja.

Gege bi akowe ijoba ipinle Kwara, Alaaji Isiaka Gold to kede oro naa ni lanaa se so, Ogbeni Saheed Popoola ti Ofa, ati Ibrahim Omoniyi ti Oyun ni won ti jawee gbele-e fun. Ni bayii, ijoba ti yan awon alaamojuto ti yoo maa dari awon ijoba ibile mejeeji.Awon naa ni: Ibrahim Omoniyi fun Ofa nigba ti G.B.O Bello je alaamojuto fun Oyun. Bakan naa ni ijoba gbe igbimo oluwadii dide lati sewadii wahala naa eyi ti Onorebu Sikiru Oyinloye je alaga won. Ose mefa pere ni won fun won lati jabo iwadii won fun ijoba.
Te o ba gbagbe, ose to koja ni wahala nla be sile laarin awon eeyan ilu Ofa ati Erin-Ile, leyii ti eeyan bii mewaa padanu emi won, ti opo dukia si baje. Titi di ba a se n so yii, awon soja lo n so Ilu Ofa ati Erin-Ile, nipinle Kwara nitori wahala ija aala ile to ti wa laarin won fojo pipe. Lote yii, ija naa gbona girigiri laarin ojo die ti won bere, eeyan to le ni mewaa lo si ti ku bo tile je pe eeyan meta pere lawon olopaa so pe o ba isele naa rin. Opo eeyan fara gbota ibon, eyi lo mu kijoba pase eto konile-gbele oniwakati merinlelogun gbako.

Ninu oro alukoro awon olopaa, Ogbeni Femi Fabode, awon mejo lowo won ti te niluu mejeeji. O so pe opo nnkan ija oloro bii ibon, ada ati bee bee lo lawon ri gba lowo won, bee lawon ti tun ko awon olopaa ko-gberegbe lo siluu mejeeji si i.

Ninu wahala yii ni won ti pa okunrin kan to ni ile itura Central Hotel, niluu Ofa, iyen Alaaji Bukola Lawal, eni to n lo sile itura e ni deede aago mewaa owuro Ojobo, Wesde, to koja yii nigba ti won pa a. Nise ni won ge ori e ti won si sa ara e yooku sakasaka; ko seni to ri oku baba naa tomi ko bo loju e nitori iku oro ti won fi pa a.

Enikan lo loo ra taisi (tiles), iyen ohun eelo oso ile ti won fee fi se ile to sese n ko niluu Erin Ile. Won so fokunrin ohun pe ko loo ra a niluu Osogbo, sugbon Ofa lo ti loo ra a. Bo se ko o deluu Erin-Ile lawon omo ilu naa to mo pe moto Ofa ni won fi keru naa fo gilaasi moto ohun, won si ba a je. Eyi lawon eeyan ilu Ofa gbo ti won fi gba taksi kan ti won mo pe omo Erin-Ile lo ni in, nise ni won ba a je lati gbesan, eyi lo fa wahala tuntun laarin ilu mejeeji.

Ohun to han gbangba laarin ilu mejeeji ni pe o pe tija ile ti wa laarin won, o si ti le logbon odun daadaa ti won ti n bara won fa a, koda won ni oro ija naa ti wa lataye Olofa to waja, iyen Oba Mustapha Olawoore Olanipekun. A gbo pe idi niyi tijoba se pin ilu mejeeji niya nipa fifun won nijoba ibile otooto> Ofa wa nijoba ibile Ofa, ohun si ni olu ilu ijoba ibile naa; Erin-Ile wa nijoba ibile Oyun, olu ilu e je Ilemona.

Bee awon ilu mejeeji yii ni won je ilu isembaye to ti pe ti won ti da a sile. Nibi tawon oba ilu mejeeji lagbara de, oba onipo kin-in-ni ni won, o si ti pe ti won ti wa. Lati ilu Erin-Ile, opo awon ilu lo ti loo tedo sibomi-in. Awon ni bii Erin-Osun, Erinmope ati Erin-Ijesa.

Ilu Ofa naa ni olu ilu fawon Ibolo, bee lo je pe Ofa lawon ilu bii Ofatedo legbee Ibadan, Ofa Eesun nitosi Ofa, Ilofa ati bee bee lo ti jade. Eyi fi han pe ilu mejeeji lo se pataki, lati Oyo Ile lawon mejeeji ti wa, omo Oodua kan naa ni won, ija lo de lorin dowe.

Awon nnkan keekeeke lawon ilu mejeeji naa maa n fi kewo lati bara won ja. Fun apeere, ija ti won ja saaju, tawon eeyan ku ninu e, oro pe moto kan kero lo siluu Ofa lati Erin-Ile ni won fi kewo. Ohun ti gbogbo eeyan si n pariwo ni pe ija awon onimoto ko lo waye, won kan fiyen kewo nigba naa ni. Ni kia ni alaga awon awako NURTW ni Kwara, Alaaji Issa Ore, so pe ija to wa laarin Ofa ati Erin-Ile lo n fa wahala won, nitori naa kenikeni ma ti oro naa mo awon lorun, awon ki i se adaluru.

Ninu ija ti ote yii, awon toro naa soju won so pe eeyan mewaa lo ku, bo tile je pe meta pere lawon olopaa pe awon eeyan to ku.

Ki i kuku se pe ijoba naa kawo gbera, ni kia ni won ti ko awon olopaa ko-gberegbe lo sibe lati petu sija naa. Saaju akoko yii nijoba ti gbe opopona nla gba agbegbe ibi tile ti won n ja le lori wa, won so o di tijoba, won si faala ibi tile ilu kookan de han won. Leyin igbese ijoba yii, ilu Erin-Ile ti se ikowojo idagbasoke ilu won, awon ara Ofa si kopa nibe. Bee la gbo pe awon eeyan ilu Erin-Ile naa o gbeyin niluu Ofa nigba ti won fi oba tuntun, iyen Oba Mufutau Gbadamosi Esuwoye keji je. Sugbon eni to ba mo itan ilu mejeeji naa daadaa yoo mo pe oro ija naa kan role ni, ko pari rara nigba naa ati pe awon onwoye n so pe o se e se koro naa pada ru lojo kan, ko too di pe ti aipe yii bere ni pereu.

Sugbon okunrin kan to n je Saliu lati ilu Ofa so pe ijoba n gbe leyin ilu Erin-Ile nitori pe egbe ACN lo po ju niluu awon ni. Esun to fi kan won yii ni Ogbeni Bode lati ilu Erin-Ile tako pe ija awon ti bere kijoba yii too de aleefa, awon ara Ofa lo kan fee gba ile ti ki i se tiwon.

Pelu ija ti won n bara won ja yii, eto oro-aje ilu mejeeji lo ti denukole. Fun apeere, awon awako ilu mejeeji ki i dodo ara won, awon araalu mejeeji ki i bara won raja, bee lo je pe ileewe Poli Ofa lawon mejeeji fi n se aala, ibe gan-an lawon awako won ti n pada siluu koowa won.

Sa o, awon oba ilu mejeeji ti soro. Olofa tilu Ofa, Oba Mufutau Gbadamosi, so pe ninu alaafia ni idagbasoke ti le waye. O ni alaafia loun n fe, o si ro awon ilu mejeeji lati je ki alaafia joba.

Bakan naa ni Elerin tiluu Erin-Ile, Oba Ajibola Olusookun, naa so ninu oro e pe alaafia loun n ro awon araalu mejeeji lati gba laaye, ki won rira won bii omo iya, ki won si je ki alaafia joba.

Pelu boro se ri yii lo mu ki ijoba Kwara ninu iwe ti akowe agba fun ijoba, Alaaji Isiaka Gold, gbe jade pase konile-gbele, eyi teeyan atoko o gbodo rin niluu mejeeji rara. Ni kia si lawon soja ti lo siluu mejeeji lati dawo ija naa duro.

Ninu oro Gomina Kwara, Alaaji Abdulfatah Ahmed, eyi ti akowe eto iroyin, Alaaji Wahaab Oba, fowo si, o kilo fawon oba ilu mejeeji lati tete gbe igbese alaafia lori ilu won. O ni aije bee, won yoo ri pipon oju ijoba nitori ninu alaafia ni idagbasoke wa.

Saaju akoko yii ni Seneto Bukola Saraki naa ti pe fun alaafia laarin ilu mejeeji, o ni ibi ti alaafia ba wa nijoba ti le sise idagbasoke.

Ni bayii, ija naa ti n role nitori awon soja to wa nibe, bee ni won ti din ofin konile-gbele ti won fi si ilu naa ku, sugbon ohun tawon araalu n so ni pe ijoba ni lati wa ona tija naa yoo fi pari patapata.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, March 20 @ 03:39:39 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Nnkan De! Nitori Wahala To Sele Laarin Ofa Ati Erin-Ile, Ijoba Jawe Gbele-e Fawo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: