Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Mayowa Figbe Bonu, O Ni: Emi Ko Ba Omo Yen Lasepo O, mMo Kan Towo Bo Kinni E Las
 
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Mayowa Figbe Bonu, O Ni: Emi Ko Ba Omo Yen Lasepo O, mMo Kan Towo Bo Kinni E Lasan Ni

“Ki i se pe mo ba omo yen lasepo, mo kan towo bo o nidii lasan ni. Mo ri i ti oun pelu omokunrin kan jo sun lera won lori ninu ile ni mo se kowo bo idi e wo lati mo boya nise ni won bara won sun nibi ti mo ti ri won. Oro rirun to n ti enu okunrin eni odun metalelogun kan, Mayowa Ayoola ti won lo ba omo odun mesan-an lasepo ree, nigba to n wi awijare leyin towo awon agbofinro te e.

Gege b«Iwe Iroyin Yoruba se gbo, inu ile kan naa ni Mayowa renti yara si pelu Iya Toyosi ta a fi ojulowo oruko e bo lasiiri lopopona Okunmade, laduugbo Vetinary, ni Mokola, n«Ibadan. Lojo Eti, Fraide, ojo keeedogbon, osu kin-in-ni, odun yii, la gbo pe okunrin baaba naa ran omoodun mesan-an yii lomi, to si bere si i fowo ra a lara nile idana tiyen ti waa ba a.A gbo pe nigba to ka Mayowa lara tan lo ba kuku mu omo naa wo yara e lo, to si ba a lasepo titi ti itan omo naa fi ye, ti irin re ko si ja gaara mo.

Itan ti Toyosi ke dele niya e ri to fi bi i leere oun to se e, tiyen naa si ko alaye pale fun un.

Eyi lo mu kobinrin naa foro ohun to awon agbofinro tesan Mokola, n«Ibadan, leti ti won si mu Mayowa bo tile je pe o ti tako esun ti won fi kan an yii fun iya omo ki oro too di tolopaa.

Leyin iwadii ranpe tawon olopaa Mokola se lori oro yii ni won gbe okunrin afurasi odaran naa lo si eka ileese olopaa to n sewadii esun odaran, iyen CSID, Iyaganku, fun iwadii siwaju.

Sugbon oro Mayowa ko yipada, o ni oun ko ba omodebinrin naa sun bi ko se pe oun kan ye abe e wo lasan ni.

Gege bo se so, Won puro mo mi ni o, mi o ba Toyosi lasepo. Ohun to sele ni pe lojo yen, mo ri oun pelu omokunrin kan ta a jo n gbe inu ile to n je Bosun ti won jo n bara won sun.

Inu yara kan ti ko seni to n gbe ni mo ti ba won ti won sun lori ara won. Inu ile wa naa ni yara yen wa, awon to n gbebe ti ko jade ni, won ko si ti i gba elomi-in si i. Emi n dana ounje lowo ni ileedana ni nigba yen. Bi mo se yo si won lojiji, aya won ja, won ta giri, n ni Toyosi ba sare wo pata.

Mo waa pe Toyosi pe ki le n danwo yen, o ni Bosun ni. Bi mo se ni Bosun n gbo, lo ba sare dobale, o n be mi pe ki n ma je ki awon iya awon gbo. Mo saa fi won sile, mo si pada sibi ti mo ti n dana.

Bi omo yen se koja legbee mi nileedana ni mo sakiyesi pe nise lo n ga idi rin, ko le rin daadaa. Ni mo ba so funra mi pe je ki n wo o na boya Bosun ti ba omo yii lasepo. Mo waa fa a mora, mo ti ika bo o labe ki n le mo boya ma a ri nnkan omokunrin loju ara e lati le fidi e mule sugbon owo mi ko ri nnkan kan.

Bi mo se ye ara e wo tan ni mo fi awon mejeeji sile pe ki won maa lo. Afi bo se di ojo keji tawon iya won waa ba mi. Iya Bosun ni ki lemi se fun Toyosi.

Mo si salaye ohun to sele fun won. Mo ni omo yin ni mo ba lori e lanaa ninu yara nibe yen.

Iya Toyosi ni iro ni mo n pa. O ni ki won wo bi mo se yaa sare yi oro naa, to je pe omo awon ti salaye gbogbo bo se je fawon pe emi ni mo n towo bo oun labe.

Mo ni ki i se pe mo mo-on-mo towo bo o nidii, mo kan wo o boya omo yen ba a lasepo ni.

Won saa soro naa di ariwo. Won ni a ni lati lo sileewosan loo sayewo. Dokita ni oun ko le se nnkan kan afi ta a ba san egberun meta naira na. Won ni ki n mowo wa, mo ni mi o lowo lowo.

Okunrin eni odun metalelogun naa salaye siwaju pe, A ti koko lo sileewosan kan tele ti dokita ti sayewo tan to so pe oun ko ri apeere pe won ba omo yii sun. Egbon e kan lo sanwo ti won pada fi se e nibi ta a lo sikeji. Won waa ni ma a da egberun marun-un naira ta a na nileewosan mejeeji pada, mo ni ko si wahala.

O waa ya mi lenu bi iya omo yen se mu awon olopaa waa ka mi mole laaaro kutu ojo keji ti won so pe mo ba omo awon sun. Bawo ni mo se le ba omo to kekere to bee yen lasepo ti abe e ko ni i faya.

Sa, igbakeji oga agba awon olopaa nipinle Oyo, Ogbeni Clement Adoda ti fidi isele yii mule, o nileese olopaa yoo gbe Mayowa lo sile-ejo bo tile je pe iwadii si n lo lowo lori isele naa.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, March 20 @ 04:07:43 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Mayowa Figbe Bonu, O Ni: Emi Ko Ba Omo Yen Lasepo O, mMo Kan Towo Bo Kinni E Las" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: