Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
[ Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin ]

·Gbogbo Musulumi Jakejado Orileede Naijiriya Ni Babayemi Gba Niyanju Lati Se Awok
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji) Attack: Awon Omo Naijiria Ti Yari Pe Awon Naa Yo Gbes
·Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
·Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
·Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
·Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun
·Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


O Sele Nijo Ni Soosi: Ayo Atore Ki Ibukun Mole, Won Ba A Lo Po Karakara N’Ibadan
 
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

O Sele Nijo Ni Soosi: Ayo Atore Ki Ibukun Mole, Won Ba A Lo Po Karakara N’Ibadan

Kayeefi loro naa je fawon omoleyin Jesu ni soosi kan to gbajumo n’Ibadan nigba ti won r i i bi idi arakunrin won kan to n je Ibukun, eni ta a foruko e gan-an bo lasiri se n seje, ti iwadii si fidi e mule pe awon okunrin egbe e ni won fi ibasun se e lese to bee.

L’Ojobo, Tosde, ojo kerinlelogun, osu kin-in-ni, odun yii la gbo pe awon oniranu okunrin naa, Ayo Fatumbi ati eni ti won pe oruko e ni Ade ko ibasun fun Ibukun to bee ti won fi fi kinni fa a nidii ya.Gege bi Iwe Iroyin Yorubase gbo, ile kan naa ni Ibukun ati eni kan to n je Bolaji n gbe. Bolaji yii lo je ore fun Ade ati Fatumbi, oun lawon mejeeji si wa lo sile lojo naa ti won ko ba a ki won too ki Ibukun mole ti won si ba a lopo lona ti Olorun lodi si.

Ise la gbo pe won ran Ibukun lojo isele yii, nje ko loo jabo fun iya e to ran an nise ni Ade ati Fatumbi pade e laarin oode, ni won ba run un mo ara ogiri nibe. Gbogbo igbiyanju Ibukun lati ja ara e gba mo won lowo lo ja si pabo pelu bi won se ni Ade yo obe si i to si leri pe oun yoo dumbu e bi ko ba je kawon se nnkan tawon fee se wooro. Leyin naa ni won wo o lo si yara Bolaji ore won, nibe ni won si ti ko ibasun fun omokunrin naa buruku buruku.

Bo tile je pe kinni ohun ti pa Ibukun lara gidigidi, sibe nise lo n ba irora naa finra lai jewo ohun to sele fun enikeni nitori eru awon eruuku n ba a. Sugbon lojo kerin, iyen lojo Aiku, (Sannde) ojo ketadinlogbon, osu kin-in-ni, odun yii, lasiri tu nigba ti omokunrin naa dide lori aga to jokoo si lasiko ti isin n lo lowo ti oju ibi to ti dide si n rin fun eje.

Iya kan lo sakiyesi eyi to si bi Ibukun leere ohun to n ti ara sokoto to wo jade. Leyin opolopo arowa lomokunrin naa sese royin ohun to sele. Loju-ese ni won gbe e lo sileewosan to wa ni Jericho, n’Ibadan, fun itoju, nibe lawon dokita si ti fidi e mule pe ona meji otooto lawon alakori ti fi kinni won da ogbe si inu iho idi Ibukun.

Leyin naa ni won fi oro to awon agbofinro leti, lojo naa lawon olopaa si ti mu Fatumbi ati Bolaji ti won lo yara e huwa egbin naa bo tile je pe Ade to sikeji nidii oran naa ti na papa bora.

Nigba to n ba Iwe Iroyin Yorubasoro, Fatumbi so pe ore oun lo si oju oun sibi ibalopo okunrin sokunrin bo tile je pe oun ko ba Ibukun sun ni toun, oun kan di mo on lasan ni.

Se tai ri obinrin fe gege bii iyawo lo sun un debi iwa ti Olorun lodi si yii ni tabi bawo, okunrin eni ogbon odun naa dahun pe, “Mo ti niyawo nile, mo si ti bimo meji. Ore mi kan to n je Ade lo ko mi. Nigba to n salaye bi ibasepo oun pelu Bolaji se bere, okunrin olokada yii so pe, “Ojo kesan-an, osu kin-in-ni, odun yii ni mo mo Bolaji nipase ore mi kan to n je Busayo ti mo maa n fi okada mi gbe lofee. Busayo naa lo tun mu mi mo ore e kan to n je Ade, lojo Wesde, ojo ketalelogun, osu kin-in-ni, odun yii. Akure ni Bolaji so fun mi pe Ade n gbe, Ade yen saa gba nomba mi lojo yen, o ni gbogbo igba toun ba ti wa s’Ibadan loun yoo maa pe mi ki n le maa fi okada mi gbe oun jade.” Fatumbi ni tie jewo pe loooto ni Ade ba omokunrin naa sun sugbon oun ko ba won da si i.

Gege bi alaye to se, Laaaro ojo Tosde, ojo kerinlelogun, ni Ade foonu mi pe oun fe ki n gbe oun debi kan. Ko pe sigba naa ni Bolaji naa tun pe mi pe ki n joo ki n loo ba oun gba kokoro toun gbagbe sibi ti mo gbe oun lo lanaa. Mo so fun un pe mi o ba eni yen nibe, o waa ni ki n loo duro de e nile. Nibe ni Ade tun ti pe mi pe ki n waa pade oun ni Sango, ki n le gbe oun lo sibi toun ti maa wo moto Akure, n’Iwo Road. Mo ni ko ni suuru.

“Nigba ti emi ati Ade pade, a koko jo lo sile Bolaji. Iyawo e fun mi ni kokoro yara kan pe ka loo jokoo nibe, a si jokoo sori roogi, mo n saaji foonu mi. Nibe ni Bolaji ti pe mi pe ki n pada loo ba eni toun ni ki n gba kokoro lowo e nitori eni yen so pe oun ti de. Bi mo se loo dagbere fun iyawo Bolaji niyen, nigba ti mo pada de ni mo ba Ade ati omokunrin yen nibi ti won ti n bara won sun.

“O ba mi lojiji. Ade ni se won ko ti i se iru e fun mi ri ni, mo ni rara. Bi mo se fee jade lo ni mi o gbodo lo. O ni ki emi naa maa bo ki n wa se e, mo lemi o le se e o, bo se yobe si mi niyen. O ni oun maa gun mi lobe ti mi o ba se e, ati pe se mi o mo pe omo egbe okunkun loun nileewe poli toun n lo ni. Leyin iyen lo da omo yen dubule lori eni to wa leyin aga ninu yara yen, o si ba a sun. O ni ki emi naa wa se temi, mo si ni mi o se. “Mo kan di mo omo yen lasan ni, mi o le se nnkan kan pelu e. Ade na obe si mi, o ni ti a ba fi le so ohun to sele fun enikeni, awa mejeeji loun maa gun lobe pa. Ani a ko ni i so feni kankan. Leyin iyen lo ni ki n waa gbe oun lo sibi toun n lo.” Ninu oro tie, Bolaji Adedayo, eni ti won lo yara e fun iwa aito yii so pe oun ko si nile lasiko ti isele ohun waye debii ti oun maa ba won kopa ninu e, sugbon iru nnkan bee ki i se tuntun loju oun nitori ere ori igi lasan ni.

Gege bo se so, “Emi naa maa n seru e tele sugbon latigba ti orekunrin mi ti mo n fe nigba yen ti ku lodun to koja ni mi o ti se e mo. Tayo Adedayo loruko re, odun meji lemi pelu e fi jo wa ko too di pe o ku.

Okunrin eni odun mejidinlogoji yii so siwaju pe, “Ore mi kan to n je Gbenga lo ko emi naa nigba ti mo wa nileewe. Emi pelu e la jo n gbe inu ile nigba yen, ti emi ati Gbenga ba di mora wa, o maa di mi mu, yoo si maa fowo pa nnkan omokunrin mi sere titi ara mi fi maa dide.

Bolaji Adedayo to pera e ni baba omo meji yii so pe koda leyin toun feyawo sile tan, oun si maa n ni ibalopo pelu okunrin egbe oun daadaa. Mo n gbiyanju lati jawo ninu e, kinni yen ki i kuro lokan mi bo tile je pe mi o se e bii tigba kan mo. Koda, Pasito wa gan-an mo si i, won si maa n gbadura fun mi ki n le yipada.” Nigba to n fidi isele yii mule, igbakeji oga agba olopaa nipinle Oyo, Ogbeni Clement Adoda so pe ileese olopaa ti gbe oro naa lo sile-ejo nibi tawon afurasi arufin naa ti n jejo iwa ibalopo lona aito ti won hu.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, March 20 @ 04:11:18 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"O Sele Nijo Ni Soosi: Ayo Atore Ki Ibukun Mole, Won Ba A Lo Po Karakara N’Ibadan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: