Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
[ Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu ]

·Deji Binu Si Titi Afesona Re, Lo Ba Dana Sun Eeyan Mesan Mole L'Ondo
·Victoria Fi Obe Gun Oko Re Pa; Ladajo Ba Ni Ki Won Loo Yegi Fun Un
·Awon Olopaa Fee Mu Baba Atiya Ti Won Lu Omo Won Pa L'Akure
·O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
·Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
·Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
·Nibi Ti Sunkanmi Ti N Gbeja Iya Re Lo Ti Gun Ojo Nigo Pa l'Ondo
·Tope To Pa Lanloodu e L'Ondo Ti Wa Lewon
·N'Igbokoda, Tegbon-taburo Ri Ore Meji Mole Laaye Nitori Ti Won Ji Iya Won L

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ija Yii Ko Ti I Tan O: Awon Omo Obasanjo So Pe Apa Paraku Ni Jonathan
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Ademola Adejare

Ija Yii Ko Ti I Tan O: Awon Omo Obasanjo So Pe Apa Paraku Ni Jonathan

Nijeta ode yii, iyen lojo Aiku ti i se Sannde, gbogbo awon ara Aso Rock, nile ijoba, l’Abuja, ni enu ya, enu ya won nigba ti won ri awon moto bii merin ti won to tele ara won, ti won si wole sinu ogba soosi to wa nibe, nigba ti won si n wo olola to n bo naa, eni ti won yoo ri to bo sile ninu oko, tawon ero si n wo tele e leyin, Olusegun Obasanjo ni. Oun naa ko si duro, nise lo n lo leleele, inu soosi lo gba lo. Bee lawon eeyan bere si i bi ara won jiyan, Obasanjo ni, Obasanjo ko, oro naa si da isin to n lo lowo ru, afi nigba ti baba naa wole ti gbogbo awon ti won wa ni soosi ri i pe eye meji ki i j’asaa, Obasanjo gan-an ni. Ati pe eni ba ti roju Jonathan to bu erin seeke, yoo ti mo pe inu re dun pe Baba naa waa ba oun ni soosi oun.

Kia ni won ti gbe gbohun-gbohun le Obasanjo lowo, ti won ni ko maa sadura fun Jonathan atawon ti won wa nibe, leyin ti won si setan ni soosi ni won gba ile Jonathan lo, ti won loo ba ara won soro, nitori lati bii ojo meloo kan ni wahala gidi ti wa laarin won. Bo tile je pe won ko je kawon oniroyin gbo oro yii, enikan to ba Iwe Iroyin Yorubasoro so pe ko sohun to lo laarin awon mejeeji ju pe Obasanjo so ohun ti Jonathan gbodo se fun un lo.Nigba ti a wadii pe se oro ti Boko Haraamu yii naa ni ati bi Naijiria yoo se lo siwaju, eni naa so fun wa pe iyen nikan ko o, awon oro mi-in wa to gbona ju bee lo. Won ni oro Femi Otedola wa ninu oro yii, sugbon eyi to se pataki ju ni ti gbogbo awon omo Obasanjo ti won ba a sise ti Jonathan pa ti, ti ko wa kinni kan fun won lati se, ti awon yen kan n rin igboro kiri, ti won n fese gbale kiri Abuja.

Iwe Iroyin Yorubagbo pe gbogbo bi Obasanjo se n ka eewo orisiirisii fun Jonathan yii, Yesa, Yesa lo n se, teyii si fi han pe gbogbo ohun ti Baba fe ni yoo se kiakia. Sugbon awon omoose Obasanjo ti won ti mo Jonathan tele ko gba, won ni bi yoo ti maa se, Yesa Yesa bo ba ri Obasanjo niyi, bee idobale ki i sewa, nitori ohun ti yoo se wa ninu re. Won ni gbogbo bo se n ba awon eeyan soro pe Baba oun l’Obasanjo, oun ko le ba a ja laelae, bee lo n wo awon omo re ti won n pe Obasanjo lagbaaya, ti won n bu u pe o ti darugbo ati pe ojo ori n daamu re, nitori nigba mi-in, ki i mo ohun to n so. Won ni bi awon ba fi eleyii wo o, bi Jonathan ko ba ti i bere si i se awon ohun ti Baba so fun un, awon ko ni i jawo nidii a n tu asiri re fun gbogbo aye.

Ninu gbogbo asiri oro tawon eeyan Obasanjo wonyi si n so latojo yii wa, eyi to dun won ju ni ti eyi to sese ti enu obinrin kan to ti je minisita Obasanjo jade. Gbogbo odun mejo t’Obasanjo lo lori oye, gbogbo e lobinrin ti won n pe ni Oby Ezekwezili yii wa, lati ibere titi de opin. Obinrin naa ni won koko fi sileese kan ti won n pe ni Due Process laye Obasanjo, to se pe ko seni ti yoo gbe kontiraati kan jade bi ko ba gba ofiisi obinrin yii koja nibi ti won yoo ti ye e wo finnifinni ki won too pe ki won sanwo e, leyin naa ni won fi i se minisita fun eto eko, bee lo si tun se minisita fun eto awon ohun alumooni ile wa ko too di pe o lo s’Amerika gege bii igbakeji olori banki agbaye. Eeyan bii Ngosi Okonjo Iweala loun naa, oro to ba si so, gbogbo awon orile-ede aye ni i fee feti si i.

Obinrin yii lo jade to ni inakunaa awon Jonathan ti po ju, ati pe ijoba apa nikan lo le maa nawo bi won ti n nawo yen. Ni bii ose meji seyin lo ti koko soro yii, oro naa si jo awon Jonathan lara nitori pelu ododo ati akosile lo fi salaye. O ni nigba t’Obasanjo wa nijoba, gbogbo gbese ti Naijiria je pata lawon san. Leyin tawon san gbese naa tan, awon waa bere si i kowo jo sinu apo banki agbaye, nitori gbogbo orile-ede agbaye lo maa n kowo pamo sibe nitori ojo isoro. O ni awon re owo naa jo titi to fi pe bilionu marundinlaaadota owo dola. Owo nla leleyii jare. O ni yato si pe awon ni owo yen ni ipamo nibe, awon tun kowo mi-in sibe legbee kan, owo to le lori epo bentiroolu tawon ta nigba naa, owo naa si je bilionu mejilelogun owo dola. O ni bayii ni apapo owo tawon ko pamo je bilionu metadinlaaadorin owo dola ($67 billion).

Oby so pe owo tawon ko pamo yii, bi ina n jo, bole n ja, owo ko gbodo kan an, nitori Obasanjo so pe ki i sowo tawon gbodo na, nitori owo ti won n fi pamo fojo ti nnkan ba le gan-an ni.

Sugbon laarin odun merin pere Yar’adua ati Jonathan dedii owo naa, won la a gbe ni. Oby ni owo ti Yar’adua na ninu kinni ohun ko to nnkan nitori aiya-ara re, Jonathan lo na gbogbo owo naa tan pata. Ki i se pe o nawo ohun tan nikan ni o, o ti tun ya bilionu mesan-an owo dola leyin to gbajoba yii o, bee lo si n wa owo ti yoo tun ya si i. Bi Jonathan ti gboro yii lo ka a lara, o si dun un wonu akinyemi ara. Nigba tawon omo re ri i bo se n se, won ni ko ma laagun jinna, awon yoo se sege fun Oby.

Loju-ese ni won ti bere si i pariwo, won si n so orisiirisii ninu iwe iroyin, won ni awon eni-ana lawon omo Obasanjo, won si n soro lati fi ba ijoba Jonathan je ni. Oro naa bi awon omo Obasanjo to ku ninu, Femi Fani-Kayode si da Reuben Abati to koko ju bombu oro bayii lu won lohun pe awon ti gba pe eni-ana lawon o, sugbon ki awon eni-oni paapaa sora nitori awon naa n bo waa di eni-ana o, sugbon oro iyen ko lawon tile n so lowo bayii, bi won se nawo tawon ko sile lawon fe ki won waa so. Reuben Abati ni ki won gbenu sohun-un, o si ni Oby ki i seni ti yoo ko ijoba awon nise awon, nitori nigba ti gbogbo won kori jo seyin Obasanjo, awon ko ri nnkan kan ti won se.

N ni Oby ba so pe oro yii ko le o, kawon omo Jonathan maa bo ni gbangba ki won je kawon jo waa soro lori telifisan nibi ti gbogbo aye yoo ti ri awon, ki awon si soro lori owo to sonu yii o.

Nibi toro wa niyen ko too di pe Obasanjo lo sodo Jonathan, ti won si jo jeun. Sugbon awon omo Obasanjo ko gba, Oby taku, o loun fee ri awon omo Jonathan ni gbangba, bi Jonathan naa ba si le wa funra e, yoo fi dara naa ni, ki awon jo jokoo sibi kan naa ti awon oniroyin agbaye yoo wa, ki awon jo waa soro bi ijoba Jonathan se n nawo, bi gbogbo aye ko ba ni i ri i pe loooto loooto, apa paraku nijoba Jonathan n se. Ako ti i mo boya Jonathan ni yoo wa gbangba tabi awon ore re, abi eni kankan ko tile ni i wa rara, o kan je pe ohun ti a n gbo lati ile ijoba, ko jo pe awon eeyan naa yoo yoju sita, awon omo Obasanjo si ti n korin ote bayii pe, Ole n sa lo, ole n sa lo, duro de mi n bo sokoto o, ole n sa lo!

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, March 20 @ 04:16:06 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Ija Yii Ko Ti I Tan O: Awon Omo Obasanjo So Pe Apa Paraku Ni Jonathan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: