Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Abiru Omokomo Wo Ni Yemi Yii! O Si Gba Tisa To N Ko O Nileewe Lesee Loju L’Ekiti
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Stephen Ajagbe,Ado-Ekiti

Abiru Omokomo Wo Ni Yemi Yii! O Si Gba Tisa To N Ko O Nileewe Lesee Loju L’Ekiti

Omoleewe girama Ado-Ekiti Grammar School, Adeyanju Adeyemi, ti n jejo bayii lori esun kiko oju ija si okan lara awon agunbaniro to je tisa nileewe naa, Daniyan Raphael, ese lo gba a loju nitori ti iyen fee gba foonu to mu wa sileewe eyi to lodi sofin.

Isele to fa wahala naa waye logba ileewe ohun lojo kokandinlogbon, osu kin-in-in, odun yii. Iwe Iroyin Yorubagbo pe foonu ti agunbaniro naa to je omo ipinle Kogi ri lowo Yemi, ti eyi si lodi sofin ileewe won lo gbiyanju lati gba ki akekoo ohun to wa nipele to keyin nileewe girama, SSS3, too koju ija si i.Yemi gba oga e lesee loju, oju naa si beje, ki won si too mo ohun to n sele, o ti wu gidigidi.Loju-ese ni won ti sare gbe Raphael lo sileewosan ekose isegun oyinbo to wa l«Ekiti, EKSUTH, nibi to ti n gba itoju titi di akoko ti a n ko iroyin yii jo.Gege bi oga-agba ileewe naa, Ogbeni John Afe, se so fun akoroyin wa, o ni nigba tisele ohun sele, awon fa omoleewe naa le awon olopaa Odo-Ado lowo, awon si ti gbejo e siwaju awon igbimo to n ba awon omoleewe wi.

Awon olopaa ti wo Yemi lo sile-ejo, won si ti gba beeli e, igbejo mi-in yoo waye lojo kejo, osu keta, odun yii.Bakan naa lo lawon ti fi isele naa to alakooso awon agunbaniro nipinle Ekiti, Ogbeni Tunde Baba-Ahmed leti, iyen si loun ti ko leta sowo si Gomina lori e.Afe so pe ajo NYSC ipinle Ekiti ati eka to n ri seto eko ti gbiyanju lati ri i pe agunbaniro naa ri itoju to peye, bee ni won si sabewo si i ni gbogbo asiko to wa nileewosan.Gbogbo akitiyan akoroyin wa lati ba Oga-agba ajo NYSC ipinle Ekiti soro lo ja si pabo, se ni foonu re n dun sugbon ko gbe e.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, April 13 @ 02:28:05 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Abiru Omokomo Wo Ni Yemi Yii! O Si Gba Tisa To N Ko O Nileewe Lesee Loju L’Ekiti" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: