Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
[ Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere ]

·Ijoba Ipinle Osun Ti Ki Oselu Bo Eto-eko O - Awon Eeyan Iwo-Oorun Osun Ke Gbajar
·Awon Aare Agbaye N Se Idaro Iku Robert Mugabe, E Gbo Nnkan Ti Obasanjo So
·Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
·Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
·O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
·Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
·Nitori Bi Won Ko Se Rowo Osu Gba, Awon Osise Di Onibaara Nipinle Oyo
·Nitori Owo Osu, , Edet Be Ori Omo Oga e N'Ijebu Ife
·Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Oba Alowa Pariwo Ni Kootu: Emi O Fipa Ba Agunbaniro Lo Po, Iyawo Mi Ni, Gbogbo E
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Oba Alowa Pariwo Ni Kootu: Emi O Fipa Ba Agunbaniro Lo Po, Iyawo Mi Ni, Gbogbo Eeyan Lo Si Mo

Oro Alowa tilu Owa, Oba Adebukola Alli, ti won fesun kan pe o fipa ba agunbaniro lo po tun ba ona mi-in yo nile-ejo giga ilu Osogbo lose to koja, nigba ti Kabiyesi so pe ololufe oun ponbele lomobinrin ohun, ati pe oun ko fipa ba a lo po.

Oba naa salaye fun ile-ejo pe o see se ki Owa tile Ijesa, Oba Adekunle Aromolaran lowo n inu wahala iro ti agunbaniro naa pa mo oun latari ija to wa laarin oun ati baba oun nigba aye re.

Yato si Alowa to jerii ni kootu lojo naa, okan lara awon omo re, Seun Alli; okan lara awon omoose Alowa, Ogbeni Ganiyu Babalola ati eni to n dana f’Oba naa (Cook), Esther Patrick, jerii si i pe ibasepo to dan moran wa laarin Alowa ati omobinrin agunbaniro naa ko too di ojo to paro mo on.Gege bi Alowa se wi niwaju Adajo Jide Falola, o ni ki i se igba akoko niyen ti ibalopo yoo waye laarin oun ati agunbaniro omo odun metalelogun ohun, ati pe tojo yen naa ko mu agidi lowo rara, se lomobinrin ohun finu-findo fi ara re sile foun lati ba a lasepo, to si dun mo on.

Oni, “Ololufe mi lomobinrin yen, emi o fipa ba a lo po rara, ki i si i se igba akoko niyen ti ibalopo yoo waye laarin wa. Iyawo mi ni, sugbon o ya mi lenu nigba ti mo de ago olopaa ti won fesun kan mi pe se ni mo fipa ba a lo po, a jo sun lojo keeedogbon mojumo ojo kerindinlogbon, osu keta, odun 2011 yen ni, o si ya mi lenu lati gbo pe o loo paro mo mi lagoo olopaa lojo Monde, ojo kejidinlogbon, osu keta, odun naa. “Lakooko ifinimole ti won maa n se fun awon agunbaniro ni mo ba a pade ni Ibokun, ti a si bere si i fera wa. Lojo keeedogbon, osu keta yen, awa mejeeji kuro ni Ilowa, a koko ya si ojubo Osun, niluu Osogbo, nibi ti a ti damoran lori ona ti a le gba lati je kawon ibudo asa ti won wa niluu di ilu-mo-on-ka.

“Leyin ti a kuro nibe, a koja sile mi niluu Osogbo, nigba to si di nnkan bii aago mewaa aabo si mokanla ale ojo naa, o bo jakeeti ori aso re, o si ni ki n ba oun tu awotele oun lateyin, leyin ti mo ba a tu u tan ni mo ri i pe ko wo beresia.

“Funra re lo bo sikeeti ati pata to wo, a si bere si i sere ife lai mu ariwo lowo rara, bee ni ko mu agidi naa lowo. Nigba tile ojo keji mo, mo gbe e pada si Ilowa.

“Sugbon o ya mi lenu lojo Monde, ojo kejidinlogbon, osu keta, nigba tawon olopaa ranse si mi pe se ni mo fipa ba a lo po. Ko seni ti ko mo on gege bii ololufe mi laafin ati nile mi l’Osogbo. Koda, awon araale mi pelu die lara awon oba alaye mo pe emi ati e jo n fera wa.” Gbaga ni gbogbo awon ti won wa ninu kootu tun lanu nigba t’Alowa dahun ibeere agbejoro re, Taofeek Tewogbade, pe egberun lona irinwo naira lawon olopaa beere lowo oun lati fi pa oro naa mole, nigba ti Pasito ijo ti agunbaniro naa n lo beere milionu kan naira lati le ba omobinrin naa soro lati jawo ninu ejo esun ifipa-bani-lo-po ti won fi kan an.

Oba Adebukola so siwaju pe latigba toro yii ti bere loun ko ti gbadun mo, o loun mo pe, “Osee se ki Owa-Obokun tile Ijesa, Oba Gabriel Adekunle Aromolaran, ko ipa pataki ninu esun ti won fi kan mi yii, nitorii ede aiyede to wa laarin oun ati baba mi.” Omo Alowa, Seun Alli, okan lara awon omoose re, Ogbeni Ganiyu Babalola ati alase re naa jerii nile-ejo lojo naa, gbogbo won si so pe ololufe Kabiyesi ni agunbaniro naa, ati pe gbogbo igba lo maa n be Oba wo laafin.

Adajo Jide Falola sun ejo naa siwaju dojo keeedogun, osu kerin, odun yii, lati gba akosile awon agbejoro ati olupejo wole.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, April 13 @ 03:48:58 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Oba Alowa Pariwo Ni Kootu: Emi O Fipa Ba Agunbaniro Lo Po, Iyawo Mi Ni, Gbogbo E" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: