Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ile Yidi Ti Won Niyawo Bukola Saraki Ra Ti Di Wahala N’Ilorin
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

Ile Yidi Ti Won Niyawo Bukola Saraki Ra Ti Di Wahala N’Ilorin

O ti to bii ojo meloo kan toro ile ibudo isere fawon araalu to je Yiidi atijo n«Ilorin ti n ja ran-in ran-in nile nipa pe iyawo Gomina ipinle Kwara tele, iyen Arabinrin Toyin Saraki lo rale ohun.

Nibi toro naa lagbara de to si ka awon kan lara de, laipe yii ni won gbejo ohun lo sile-ejo giga ipinle Kwara lati ba won yanju re.

Awon to pejo ohun, eyi ti Amofin Jawondo soju fun ni kootu giga Ilorin ni Dokita Saad Omoiya, Dokita Saliu Ajibola Ajia ati Alaaji Saleh Duro Garba. Nibi ti won mu oro naa lokun-un-kundun de, won tun fiwe kan sita lati fesi soro ti Seneto Bukola so lori pe ki i se iyawo oun lo rale naa.Pelu bi nnkan se n lo yii lo mu ki oniroyin wa se iforowero pelu Dokita Saad Omoiya, ninu eyi to so opolopo oro lori isele naa. Bayii lawon oro to so se lo> Itan oro ile Yiidi atijo n«Ilorin Ibi ti Yiidi Ilorin wa tele lo di ibudo isere (Amusement Park) awon araalu loni-in. Gege bo se je pe latojo pipe la ti mo pe opin ilu ni Yiidi maa n wa, opopo to lo siluu Oyo ti a mo si Oyo Bye Pass ni won n pe e nigba naa.

Tori airi itoju fun agbegbe yii ati bo se je pe ilu ti n tobi si i, ti ero to n kirun ni Yiidi si ti n po ju aaye ibe lo lo mu ki Ogagun Agbasika Innih to je Gomina ologun igba naa lodun 1986 fun won nile mi-in lati maa kirun odun Ileya ati ti Itunu aawe nibe. O si so agbegbe Yiidi tele yii di ibudo isere, o se e¯re ologun sibe ko le rewa. O tun ko awon eranko da sibe, eyi si mu kawon omode ati agbalagba nifee sibe lati maa naju tabi sayeye.Igbese bi ijoba Gomina tele se ta ile naa Lasiko isejoba Seneto Bukola Saraki, nitori pe o ri i pe ile naa bo saarin igboro niyawo e se ra a, eyi ti ko dun mo awa kan ninu. Oro pe ijoba sofin pe o fee gba ile ki i se ajoji sawon eeyan Kwara lakooko isejoba e. Gomina ologun David Bamigboye lo ti koko gbiyanju lati gbale naa pada, sugbon oro yii dija nigba naa ti awon eeyan fi doju ija ko o bii ologun, araalu lo si bori nigba naa. Bi ijoba ba si fee se nnkan kan, won gbodo beere itan, asa ati gbogbo ohun to ro mo on ni.

Ki a le baa mo bi ile ibudo isere yii se lagbara to, ibe lawon Kaba kora won jo si nigba ti won fi pin won mo ipinle Kogi. Gbogbo akitiyan ijoba ologun ti Innih n dari nigba kan lati gba ile naa ni ko se e se fun un.

Ohun ti mo n so ni pe ka ni awon kan ti lo ipo won lati so ile ilu di tiwon, Seneto Bukola gan-an ko ni i ba a nibe debii pe yoo ra a fun iyawo e. A ti gbe oro naa lo si kootu, a si n reti ibi tejo naa yoo fori sole si, sugbon a mo pe araalu ni yoo bori.Eto oro ile KwaraEni ti ko mo itan ile Ilorin nijoba yan sipo tele, sugbon nigba ta a pariwo won sita ni won yan elomi-in to je omo bibi ilu Ilorin sileese oro ile, a si mo pe eyi yoo mu iyato ba ohun gbogbo nitori ife araalu lo se pataki. Ki i si se pe Ilorin go o, a kan n ni suuru ni.

Seneto Bukola Saraki naa ko dake lori oro naa, o gbe igbese tie. Ni kia ni Gomina ana ohun, eni ti akowe eto iroyin e, Akintoba Fatigun, ba fesi oro so pe iyawo oun ko rale Yiidi atijo kankan o, ati pe kawon eeyan ma ko Arabinrin Toyin Saraki mo iru oro rederede bee. O ni nise niyawo oun tun nawo lori ibudo isere naa fun idagbasoke ibe ni.

Bakan naa, Komisanna feto iroyin ni Kwara, Omooba Tunji Moronfoye soro laipe yii lori oro naa.

Lodun 2010 lajo kan lati ilu oyinbo toruko won n je Artee wa si Kwara, ti won si n wa ibi ti won yoo ko soobu igbalode si laarin igboro awon agbegbe ekun mefeefa to wa ni Naijiria, eyi tiluu Ilorin je okan ninu won. Opo awon ibi ni won de niluu Ilorin, bii Flower Garden, ibudo isere ati bee bee lo. Won ni ibudo isere Yiidi yii lo te awon lorun, eyi lo si mu kijoba igba naa lodun 2010 fowo siwee adehun lori ile naa. Bee ibudo isere ni won n lo o fun ni bayii, nitori awon eranko lorisiirisii lo wa nibe, ki i si i se Yiidi ikirun rara. Nitori naa, ko kan iyawo Gomina ana rara, iyen Amofin Toyin Saraki.

Lodun 2004 niyawo Gomina ana yii satunse ibudo naa fun isere awon omode, ko si mowo-mese nipa oro tawon kan n gbe kiri ohun. Awon oloselu kan lo n so isokuso, won kan fee fi si araalu lona ni, sugbon oye ti ye awon araalu ju bee lo.

Sa o, awon eeyan to gbe ejo lo si kootu yii ti ni Seneto Bukola ko lo ye ko we iyawo e mo ninu oro naa, won lawon mi-in lo ye ki won soro, ati pe ko je kawon pade ni kootu, kadajo si gbe idajo e kale.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, April 13 @ 03:52:11 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Ile Yidi Ti Won Niyawo Bukola Saraki Ra Ti Di Wahala N’Ilorin" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: