Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
[ Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin ]

·Gbogbo Musulumi Jakejado Orileede Naijiriya Ni Babayemi Gba Niyanju Lati Se Awok
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji) Attack: Awon Omo Naijiria Ti Yari Pe Awon Naa Yo Gbes
·Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
·Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
·Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
·Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun
·Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Gbogbo Omo Yoruba Lo Sedaro Oba Asiru Tadese, Oluwoo Tile Iwo To Waja
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Gbogbo Omo Yoruba Lo Sedaro Oba Asiru Tadese, Oluwoo Tile Iwo To Waja

Eseko gbero lojo Isegun, Tusde, ojo kokandinlogun, osu yii ti won sinku Oba Tadese si oju orori awon baba-nla e ninu aafin Oluwoo. Opo awon eeyan pataki niluu naa ni won peju pese sibe lati waa bu eye ikeyin fun Oluwoo tilu Iwo, Oba Tadese to waja. Sheik Mustapha Arowosafe ti i se aare egbe awon lemoomu jakejado ile Yoruba, to fi mo ipinle Edo ati Delta lo saaju awon aafaa nla nla mi-in nibi eto isinku ohun.Ko si beeyan se le wo ilu Iwo lojo Isegun, Tusde, ose to koja ti ko ni i fura pe o see se ko je Oba ilu naa lo waja pelu bi idakeroro ti ko legbe se gba ilu ohun kan, ti tomode tagba n sedaro baba won to lo, ti gbogbo igboro ilu yii si da bii ilu ti won ti kede konile-o-gbele tabi asiko ti eto imototo ayika olosoosu n lo lowo.

Gbogbo awon ontaja ilu pata ni won pa ka-ra-ka-ta ti, gbogbo oja to wa nigboro ni won pati nitori ipapoda Oba won. Oro ko si yato lawon agbegbe bii Ode Oba lo sona Oke Odo, Oja Ale lo sona Oke Bode, to fi mo oja nla kan ti won n pe ni Jankara Opopo Araromi. Gbogbo awon adugbo to maa n gba yunun fun ero nigba gbogbo yii ni won da paroparo.O tojo meta kan ti ojojo ti n sogun Oba Asiru Olatubosun Tadese, Ariwajoye Kin-in-ni ti i se Oluwoo tilu Iwo. Baba naa ko si fi ara re dagunla, bo se n gba itoju nile yii lo n te oko leti lo soke okun lo fun iwosan.
Sugbon aisan ko lo n se baba yii, aisan ogbo ponbele ni, bee, aisan lasan la a wo, ko seni to ri tolojo se. Lojo Aje, Monde, ojo kejidinlogun, osu keji, odun yii, l’Oba nla naa waja, o loo darapo mo awon baba-nla re lalakeji. Sugbon iba eeyan lo mo lojo naa pe opo nla ti ye laafin, nitori ni nnkan bii aago meje aabo ale ni erin wo, afi laaaro kutu ojo keji, iyen ni Tusde, ojo kokandinlogun, osu keji yii, nigba tiroyin naa tan kaakiri agbaye lo too de etiigbo awon eeyan. Ojo Aje, Monde, ojo kokanla, osu keji, odun yii, ni Oba Olatubosun de lati India to ti loo gbatoju. Papako-ofurufu Muritala Muhammed to wa n’Ikeja, l’Ekoo, lo ba pada wo Naijiria. Eko ni baba sun lojo yii, ojo keji lo si pada saafin. Ko si lo ju ose kan lo nile to fi mi imi ikeyin. Afon Oba Tadese gbo die ko too wo. Ojo kefa, osu kefa, odun 1936, ni gbogbo aye gba pe won bi i. Abule kan bayii ti won n pe ni Aba Abimbola, niluu Iwo ni won bi i si. Omo atapata dide ni i se.

Yato si pe awon obi e ko lagbara lati to o niwee, ko wule si ninu ipinnu won pe ki omodekunrin naa di alakowe lojo iwaju. Iba si ti lanfaani lati mo on ko, mo on ka bi ko se ti ore baba re kan ti Olorun lo fun un. Okunrin yii to n je Aremu Oyewusi lo yi awon obi e lokan pada lati je ko kawe. Oyewusi ri jaje die nitori pataki loun ninu awon agbe onikoko Iwo nigba naa. Baba yii lo ni ki Baba Asiru yonda re foun. Bee ni won ran kaki sokoto ati ewu penpe fun un, toun naa si se bee di omo sukuu. Odo baba onikoko yii lomo to mu oriade waye yii gbe titi to fi pari gbogbo iwe e, to si fi bere ise olukoni lodun 1966.Leyin naa lo lo sile-eko onipoketa, eyi to fun un lanfaani lati di ojulowo olukoni ati akose-mose olukoni.

Sugbon bi Omooba Tadese se nifee ise yii to, to si n fi tokan tara se e naa lo nifee oselu. Ko si ti i sise olukoni pe to fi darapo megbe oselu.

Won dibo yan an gege bii kanselo to soju agbegbe re lodun 1976. O si wa lara awon ti won tun fipo nla da lola ninu awon kanselo pelu bi won se yan an gege bii alakooso fun eto eko nijoba ibile Iwo, iyen lodun 1978.Saa ijoba yii ko ti i pari ti Ogbeni Eniola Atanda Olawale ti i se alaga ijoba ibile Iwo nigba naa fi ku, n ni gbogbo awon omo igbimo alase ijoba ibile Iwo ba fori kori, ni won ba ni Tadese lawon fe ko maa dari awon lo. Bee lokunrin oniwa irele naa di alaga kansu laidibo. Bo se lo saa yen pari ni won tun dibo yan an pada sipo alaga lodun 1979. N lo ba tun lo saa odidi kan si i nile ijoba. Bee ni Onarebu Tadese se alaga ijoba ibile Iwo laarin odun 1979 si 1982. Ni 1980 ni ipo oba si sile, o si wa lalaga nigba yen. Nigba to kuro lalaga, oun naa wa lara awon ti idile won fa kale lati joba. Won bere si i du u ti Olorun fi ni ko bo si won lowo. Sugbon kinni kan ti Tadese fi yato si opo awon oselu iwoyi ni bi owo ilu ko se wo o loju. Bi okunrin naa se pe nile ijoba to, ko-lako-sagbe naa lo si wa sibe titi. Bo si tile je pe idile oba lo ti wa, iba ti lanfaani ati gori ite awon baba re nitori oun pelu olowo kan ni won jo dupo naa, olowo bii okunrin naa si sowon niluu Iwo ati agbegbe re. Won dupo yii mora won lowo titi ti won fi wo ara won dele-ejo.

Sugbon eelo ni Tadese ni lowo ti yoo fi sejo, tisa to ti feyinti lenu ise lasanlasan, eni towo ifeyinti to n gba losu ko ju eedegbeta naira lo. Ko rowo sejo bii baba olowo sugbon eyin re ni gbogbo ilu wa.Ife tawon afobaje, awon ijoye ati gbogbo ilu ni si i nitori iwa rere re lo je kipo naa ja mo on lowo. Idi ree ti won fi so o ni Ariwajoye, to si di Oba Asiru Olatubosun Tadese, Ariwajoye Kin-in-ni. Lojo kokandinlogun, osu keje, odun 1992, ni won jawe oye le e lori gege bii Oluwoo tilu Iwo. Oun si ni ori-ade keeedogun to je. Nigba to n ba Iwe Iroyin Yoruba soro, akobi Oba to waja yii, Omooba Segun Olatubosun so pe iku baba naa dun oun nitori asiko toun atawon aburo oun nilo e julo lo dagbere faye.

Gege bo se so, ‘’Gbogbo igba ni won maa n ba emi atawon aburo mi damoran lori bi aye wa se maa dara. Mo le sapejuwe Oba Olatubosun Tadese gege bii eeyan takuntakun to nifee araalu, to si niteriba. Inu aafin nibi ni won dake si lojo ketadinlogun, osu yii, ni nnkan bii aago meje aabo ale. “Igba ti ara won ko ti ya lati bii odun meta o le die la ti n gbe won lo sileewosan Onward, to wa niluu Osogbo, won loo gba itoju lorile-ede South Africa, won si sese de lati India ni. Nigba to n toka sipo ti idile Tadese wa ninu awon idile to n joba n’Iwoo, Omooba naa so pe, “Tadese lakoko ninu omo meta ti Parin Olumade to te Iwo tuntun yii do bi. Ile-Ife ni Iwo ti se wa, oba meta lo si ti je nigba ti won n bo lati Ife. Omo keji ni Olayilumi, eketa ni Oladunmoye.

“O da bii eni pe Olorun ti fi asiko ti baba mi maa ku han won. Nigba ti won gbe won de lati India ni Monde, ohun ti won koko so ni pe gbogbo awon aburo re nko o, ibo ni won wa (Eko ni won ti n so iyen ko too di pe won wale o). Mo ni alaafia ni gbogbo won wa. “Won ni ki n yaa mojuto won daadaa nitori tawon ba ti dele lawon maa bere irinajo kan. Pelu oro yen, o da bii pe Olorun ti fi iku han won ki olojo too de. Titi ta a fi pari akojopo iroyin yii ni gbogbo omo ilu Iwo n ya ketiketi lo saafin Oluwoo lati ba awon olori, omooba ati ebi oloogbe sedaro Oba rere to lo. Won n sadura pe ki Olorun fi alujanna ta Kabiyesi to waja naa lore. Emo ku oju opo di, aferemojo ku enu isa n sofo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, April 13 @ 03:58:19 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Gbogbo Omo Yoruba Lo Sedaro Oba Asiru Tadese, Oluwoo Tile Iwo To Waja" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: