Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Kayeefi Ma Loro Adeola Yii O, Omo To Bi Ninu Ara Re Lo Ri Mole Laaye L’Osogbo
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Kayeefi Ma Loro Adeola Yii O, Omo To Bi Ninu Ara Re Lo Ri Mole Laaye L’Osogbo

Otooto loju tawon eeyan agbegbe Oke-Ijetu, niluu Osogbo, fi wo ohun ti omodebinrin eni odun mejidinlogun kan se lose to koja pelu bo se sin omo bibi inu re laaye, to si sa lo. Bawon kan se n so pe eedi loro re, bee lawon kan n so pe eje ta si omobinrin naa lopolo ni, nigba tawon mi-in n so pe ohun asiri ikoko kan lo n je edun okan fun un.

Ni nnkan bii aago meta osan ojo kejidinlogun, osu keji, odun yii ni Adeola Joseph to n gbe ni ojule kerinlelaaadorin, OkeIJetu, niluu Osogbo gbe omo re, Fatia Nafiu lo sile akoku kan nitosi ile ti won n gbe, o gbe ile looro, o jin die, o si ti ori omo naa wonu re, o da yeepe bo o mole, leyin naa lo gbe bulooku meta le e lori ki ekun omo naa ma baa goke titi ti yoo fi ku.

Leyin to se ise ibi yii tan lo sa lo raurau kuro laduugbo lojo naa, sugbon awon ti won ti n so irin ese re laarin adugbo ti won si mo oniruuru igbese to ti n gbe tele lati gbemi omo odun meji yii yara lo sinu ile alapa ti Adeola ti jade, won si ri omo naa nibi to sin in si.Won gbe omo naa lo si eka itoju awon omo alainiyaa nileewosan St Francis, lagbegbe Jaleyemi, niluu Osogbo. Laaaro ojo keji lowo te Adeola lakooko to wa sinu ile. Awon ara adugbo beere ibi ti omo re wa, o si da won lohun pe inu yara lo wa, bayii ni won fa a le awon olopaa lowo, to si foju bale-ejo logunjo, osu keji, odun yii.

Pako ni Adeola n seju niwaju Adajo Majisreeti ilu Osogbo lakooko ti agbejoro fun ileese olopaa, Inspekito Solomon Oladele, n salaye nipa iwa odaju to hu ati ijiya to ni labe ofin.

Oladele so fun ile-ejo pe opelope wolii obinrin kan toruko re n je Tunrayo Akinwande to ri omo naa nibi ti iya re sin in si, to si pe gbogbo awon ara adugbo ti won fi gbe e lo sileewosan.

Esun meta otooto to ni i se pelu igbiyanju lati paniyan, didite se nnkan buburu ati hihu iwa to le da omi alaafia ilu ru ni won fi kan omobinrin yii, eleyii ti won ni o ni ijiya nla labe ofin iwa odaran ipinle Osun, kia naa lo si so pe oun jebi awon esun naa.

O waa rawo ebe sile-ejo lati siju aanu wo oun, o ni nnkan to sun oun debi igbese naa ni pe inu awon obi oun ko dun si igbeyawo laarin oun ateni toun bimo fun ati pe oun nikan loun n da gbo bukaata omo naa. O ni oun ri omo naa gege bii idena si erongba oun lati wa ise lo siluu Eko, idi niyen toun fi pinnu lati gbemi e nitori ko si bi oun se le da gbo bukaata re toun ba lo s’Ekoo.

Nigba to n gbe idajo re kale, Adajo Olusola Aluko so pe ko ye ki omobinrin naa maa gbe laarin awon eeyan nitori odaju pata gbaa ni, o si se e se ko ma yipada kuro ninu iwa naa.

Leyin naa lo waa dajo pe ki Adeola loo lo odun mefa gbako logba ewon pelu ise asekara lai faaye faini kankan sile fun un.

Nitori bii oro naa se ri ni Iwe Iroyin Yoruba se loo se iwadii lori isele naa lagbegbe ti Adeola n gbe. Enikan to ni ka foruko bo oun lasiiri lo koko salaye pe aimoye igba ni Adeola ti fi oogun eku sinu ounje fun omo re yii, sugbon ti Olorun ko je ko ku.

Yato si eleyii, laaaro ojo kejidinlogun, osu yii, tisele naa sele, won ni Adeola ti koko gbe omo naa lo sodo Osun pelu erongba lati ju omo naa sodo, sugbon o ba awon eeyan ti won n foso nibe, ko si le ju u sodo.

Iwe Iroyin Yoruba ba oko Adeola to je Baba Fatia soro. Ayoku Nafiu to ti le lomo ogbon odun salaye pe oun ti koko niyawo kan nile tele tiyen si ti bimo meji foun ko too di pe oun salaabapade Adeola lodun meta seyin lakooko to n ba iya re kiri eja.

O ni ife wa laarin awon mejeeji nigba to loyun, oun si seleri fawon obi re pe iya ko ni i je omo won ati pe oun setan lati maa gbo bukaata re.

Ayoku ni, “Mo so fun awon iya re pe ko wa maa gbe odo mi, sugbon iya re so pe omo kan soso toun bi niyen, oun ko le je ko maa gbe odo mi. Gbogbo igba ni mo maa n lo sibe, nigba to bimo ninu osu karun-un odun 2011, mo sanwo osibitu, mo si ra oriisirisii nnkan fun un.

Ile iya re la ti sekomo nitori iya re ko je ki n ko omo lo sile ti mo n gbe ni Arogunmasaa, niluu Osogbo. Losoose ni mo maa n loo fun un lowo, igba mi-in egberun kan naira, igba mi-in eedegbeta naira; to ba pe mi pe omo n saisan, ma a ra oogun lo fun un.

“Ohun ti mo kan sakiyesi ni pe latigba to ti bimo, ti mo ba ti lo sodo re bayii, ija ni. O so fawon araale won pe inu maa n bi oun toun ba ti ri mi ni, mo si maa n so fun un pe to ba ni nnkan ti mo se fun un, ko so fun mi, ki n le be e nitori pe emi ko feran ija rara.

“O waa ya mi lenu nigba ti won pe mi lati ago olopaa lanaa pe ki n wa, mo koko loo gbe mama mi nitori n ko de ago olopaa ri laye mi, nigba ti a debe, won so nnkan ti Deola se fun mi, o ya mi lenu nitori mo si loo fun un lowo lose meji seyin, n ko le so pe nnkan to sun un debe niyi.” Iwe Iroyin Yoruba yoju si ileewosan Our Lady of Fatimoh Catholic Hospital, Jaleyemi, Osogbo, nibi tawon ara adugbo gbe Fatia lo. A ba Iya Deola nibe, ohun ti obinrin naa si so ni pe oro omo oun ki i se oju lasan rara.

Arabinrin Funke Olusola Amos to je mama re salaye pe, “Omo odun merin ni Deola wa nigba ti baba re ku, Akure la n gbe nigba yen sugbon nigba ti wahala po ti n ko ri oluranlowo ni mo gbe e wa si Ilesa lodo aburo baba mi tawon naa ti ku bayii, odun merin seyin naa ni mo salaabapade oko ti mo wa lodo re bayii.

“Won mu Deola bii omo, ko seni to mo bi ki i baa se bo se ko wa sita bii omo ojo mejo yii.

Nigba ti mo mo pe Deola loyun, mo ranse pe Dadi wa loko ti won wa, won wale, a pe omokunrin yii to fun un loyun, o ti niyawo kan tele, se niyawo re bu sekun pe oun gan-an ko ti i yo to tun fi loo fun elomi-in loyun.

“Bayii lawon ara adugbo pe mi ki n mu omo mi sodo, Dadi wa naa si so pe ka maa mu omo wa lo nitori omo po lowo wa. Awon mu un lo soko, emi wa l’Osogbo, mo n ta eja, Dadi wa maa n gbe e wa nigbakuugba to ba to asiko lati lo si osibitu nitori pe Ibala ni oko ti won wa, o si jinna, won a tun gbe e pada titi to fi bimo were si Onireke ti omokunrin yen mu un lo.

“Niwaju Olorun ati eeyan, ohun tawon molebi Ayoku se fun omo mi ko te mi lorun, eba ni won te waa fun un lojo to bimo, o dun mi, mo ni ki won gbe omo won kemi naa mu temi tori o po lowo mi. Nigba ti Dadi wa de, a mu un lo soko, a n toju re, nigba to se die ni okunrin yen atawon ore re waa bebe pe oun fee renti ile fun un.

“Awon araale wa tun gba mi niyanju pe Deola o ti i le da gbele, pe ki n mu un sodo nitori okunrin yen ti niyawo kan tele. Bayii ni mo n toju re ati omo, mo n fun un lowo, oogun, aso ati bee bee lo. Nigba tomo re to odun kan to ti n rin, a beere lowo re pe ise wo lo fee ko, o si so pe oun ko lo ileewe mo pe oun yoo ko ise aserun-losoo legbee ile wa.

“Ohun to se yii ko ye mi rara nitori emi Deola ni Fatia omo re yii, ko le fi sile fun iseju kan.

Mo gba pe oro yii ki i se oju lasan, ko wu oun naa, ko ni i lokan lati pa omo re. Se e mo pe won ni tawon olopaa ba n na eeyan, ohun ti ko se, o le so pe oun se e, bee loro oogun eku ti won ni Deola n fun omo re je tele yen, awon dokita gan-an si so bee.” Iwe Iroyin Yoruba tun ba Reverend Sister Mary Elizabeth Akinlotan to je alaamojuto awon omo ti ko niya tabi ti won gbe sonu nileewosan Jaleyemi l’Osogbo soro. Obinrin naa so pe, “Ni nnkan bii aago meta osan ana ni won gbe omodebinrin yii wa sibi, awa si ti fun omo yii loruko nigba ti won gbe e de gege bi a se maa n se nigbakuugba ti won ba ti gbe omo wa sibi, yala eyi tiyaa re gbe sonu ni tabi lona mi-in. Mary Peter la fun omo yii nitori Peter ni apata. Nnkan temi ri ni pe loooto ni ohun tiyaa omo yii se ko dara, sugbon mo waa ro o pe ki lo fa a to fi huwa ti ko dara bee fun omo to bi ninu to si ti dagba.

“Mo ri i pe ogbe okan wa ninu igbe aye omo yii, o sese wo ileewe giga lo loyun, a gbo pe eni to loyun fun maa n loo wo o, o maa n fun lowo leekan lose, o le fun un ni eedegbeta naira, o le fun un ni egberun kan naira, sugbon gbogbo igba tokunrin yii ba ti de lobinrin yen maa n ba a ja gege bi awon eeyan se so.

“Leyin igba yen naa, ko ti i gba pe boya ki won tun jo ni ajosepo kankan, dajudaju mo ri i pe o n kabamo pe oun bimo, o de n toju omo yen daadaa. Sugbon o da bii eni pe ibanuje okan yen ti fee di aisan si i lara to fi je pe okan re poruuru to fi loo se iru ise buruku bayii fun omo, kawon ara adugbo too gbemi omo yii la.

“Nnkan temi mo ni pe ta a ba wo baba to bi Deola, o ti ku, mama re naa wa lodo oko mi-in to n toju re to si mu un bii omo, a ko mo iru ibanuje to kun okan omo yii. Nnkan temi le gba awon olopaa niyanju ni pe ki won je ki omo yii lo si LAUTECH ko loo ri dokita to maa ye e wo boya o ni aisan okan kan to n da a laamu ti okan re ko fi bale.

“O siwa yen hu, ko daa, oun naa mo pe ko dara lo se sa lo leyin to se e tan. Emi o nigbagbo pe ki won loo ti i mole lo maa so o di oloriire, o tun maa baje si i logba ewon ni, sugbon ti won ba n soro isiti fun un lona tutu, ka wo iru aisan to ni, iyen lo le da a pada si rere to fi le gbe igbe aye to nitumo, ti yoo si le se iya omo e lona to to.

Ju gbogbo re lo, Adeola ti wa logba ewon ilu Ilesa bayii, odun mefa gbako ni yoo si lo nibe gege bii idajo ile-ejo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, April 13 @ 04:16:45 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Kayeefi Ma Loro Adeola Yii O, Omo To Bi Ninu Ara Re Lo Ri Mole Laaye L’Osogbo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: