Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Abi Ki Lo N Seyawo Jonathan Yii: Kin Ni Won N Wa Kiri - Oun Atawon Minisita Oko
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Adewale Adejare

Abi Ki Lo N Seyawo Jonathan Yii: Kin Ni Won N Wa Kiri - Oun Atawon Minisita Oko Re?

Orisiirisii nnkan lo maa n sele laye yii. Awon eeyan a si maa gbagbe oro kiakia paapaa.

Opolopo awon eeyan ni won ti gbagbe aye Abacha ati ohun to gbeyin okunrin naa pelu awon ti won jo n sejoba. Won ko ranti rara bi Abacha ti se n gbiyanju lati fi aburu bo aburu, to n gbiyanju lati fi aidaa bo aidaa, ati bi igbeyin re ti waa ja si jatijati. Ohun to buru ni pe gbogbo ohun t’Abacha n se tawon eeyan n so pe ko daa, gbogbo e naa lawon ti won wa nijoba yii n se, awon miiran si n seyi to buru ju t’Abacha lo.

Won niyawo Jonathan ati Minisita to n ri soro ilu Abuja so pe awon yoo fi bilionu merin Naira kole igbalejo tiyawo Aare yoo ti maa gba awon alejo re si, ti ko si senikan ti yoo di i lowo. Gbogbo ilu lo binu, gbogbo won lo soro, gbogbo eeyan lo si n so pe lasiko ti a wa yii, ati bi nnkan ti se ri fun Naijiria, kin ni Patience fee file-igbalejo ti won na bii bilionu merin naira ko se.


Awon alejo wo lo fee gba nibe! Beeyan ba tile fee se iru awon nnkan bayii, yoo je nibi ti ko ti si i¯se; ati osi to n ba awon araalu finra, kaluku ni iya n je, awon omo ti won kawe, won ko rise, awon ti won saisan ko le lo si osibitu, nnkan gbogbo si daru kanle kanle. Sugbon ko da bii pe eyi je nnkan babara kan loju awon ti won n sejoba, iyawo Jonathan gbodo kole igbalejo dandan ni. Nigba tawon eeyan waa n pariwo, ti won n so pe ko daa yii, awon kan si tun ko sinu awon araalu, won fi ko awon ero jo siluu Abuja, won ni ki won waa maa gbe iwe pelebe pelebe kiri, ki won si maa fi so pe ile ti won fee ko fun Patience yii, ko sohun to daa to o laye ati lorun.

Bee lawon eeyan naa to wa siluu Abuja, ti won si kowe orisiirisii le won lowo, awon kan si wa nibe ti won n bu Wole Soyinka pe o kan mowe lasan ni, ko mo ogbon itolu. Won bu u daadaa, oun atawon ti won lodi si i pe ki obinrin naa ma fi owo ijoba kole. Beeyan ba ti roju awon eeyan ti won gbe iwe le lowo lori telifisan tabi ninu awon iwe iroyin, yoo ti mo pe awon arebipa kan lawon eeyan naa sa jo, awon ti won ko mo ohun ti won ko sinu iwe ati aso ti won gbe le won lowo.

Lara etan ati iwa ibaje buruku to ba Naijiria debi ta a wa loni-in yii naa ree o, iwa naa ni ko fiwa sile yii, odo awon ti won n sejoba ni kinni ohun ti po si julo. Bawo ni won yoo se se e, ona wo ni won yoo gbe e gba, ko si ki aburu tiwon naa ma ba won.

Kin Ni Won N Wa Kiri O?

Minisita to n ri seto iroyin atawon kan jo gbeto kan dide, won ni won fee maa kaakiri gbogbo ipinle kawon le ye ise tawon ipinle gbogbo n se wo, ati ise ijoba apapo to wa nipinle kookan ati eyi tijoba ipinle naa n se, pelu awon ise ijoba ibile paapaa, kawon le jabo ohun tawon ba ri fun ijoba.

Awon eeyan yii nikan ni irin-ajo ti won n rin yii ye o, ati idi tokunrin naa yoo fi ise to wa niwaju re sile ti yoo maa yido ori kiri. Idi ni pe orisiirisii igbimo lo wa, to je awon ko ni ise meji ju lati maa kiri gbogbo agbegbe ti won ba ti n sise ki won si waa maa fawon ijoba labo lo, ki won wo ise ti won n se ati eyi ti won ko se daadaa, ki won si waa so bi ise naa ba ti se n lo si nile.

Gbogbo eka ijoba lo ni iru awon ileese bayii, eyi to si lagbara ju ni tawon ti won n pe ni Due Process, awon ti won maa n ye ohun gbogbo wo ki won too sanwo kankan sita. Yato si tiwon yii, awon ile igbimo asofin leka kookan lodo won to je pe ohun ti won n se ni lati mojuto ise tijoba apapo ba so pe oun n se, ti won yoo kiri, ti won yoo ye gbogbo ise naa wo, eyi ni won si maa n fi se awon ofin ti won ba fee se.

Ohun ti Makua n wa kiri ni ko ye enikan o. Sugbon bi Makua ba tie waa fee maa kiri bee, sebi owo apo re ni yoo na, abi owo ta lo fee maa na, sebi owo ileese ijoba re ni yoo maa ko kiri. Sugbon okunrin Minisita yii ko se bee, kaka bee, o n kowe sawon Gomina kiri pe ki won seto owo ati nnkan igbalejo fawon bi awon ba ti n kiri. Minisita yii kowe si Gomina ipinle Edo, Adams Oshiomhole, o lawon ogofa (120) eeyan loun n ko bo nipinle re, ko seto ibi ti won yoo gbe ohun ti won yoo je ati moto ti yoo maa gbe won kiri.

Ni inu ba bi iyen, o beere pe ise wo loun ran an, abi ki lo kan oun atijoba oun to fi waa je pe oun loun yoo maa sanwo irin to ba fee rin. O ni bi won ba fee waa ye odo oun wo, nigba to se pe ijoba apapo ni won n sise fun, ki won gbowo lowo awon ti won ran won nise, abi ewo lo kan oun. Ewo lo si kan an loooto, se bi won ti n fowo ilu sofo kiri nu-un ni, ti won yoo maa wa ohun ti ko sonu kiri. Eyi to ye ki won se won ko ni i se e o, won yoo maa se iranu kiri bii eran to se niwo. Bee owo araalu ni won n na danu bayii o, afi k’Olorun gba wa lowo won.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, April 13 @ 04:16:52 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Abi Ki Lo N Seyawo Jonathan Yii: Kin Ni Won N Wa Kiri - Oun Atawon Minisita Oko" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: