Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
[ Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin ]

·Gbogbo Musulumi Jakejado Orileede Naijiriya Ni Babayemi Gba Niyanju Lati Se Awok
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji) Attack: Awon Omo Naijiria Ti Yari Pe Awon Naa Yo Gbes
·Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
·Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
·Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
·Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun
·Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ope O, Gomina Ipinle Oyo Fun Onibapon Ti Ibapon Lopaa Ase
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Abayomi Akanni, Ogbomoso

Ope O, Gomina Ipinle Oyo Fun Onibapon Ti Ibapon Lopaa Ase

Gbogbo ona lo ja si gbongan Lagbami Osekun to wa ninu Sekiteriati ijoba ibile Guusu Ogbomoso, pelu bi ijoba ipinle Oyo se fun Alaaji Oloye Abdul Wahab Akanji Asifatu Onibapon ti Ibapon lopa ase ti won ti n poungbe fun lati ojo pipe wa, koro naa too waa ri bee lojo Eti, ojo kerindinlogbon, osu kerin, odun ti a wa yii.

Nigba ti Gomina ipinle Oyo, Seneto Abiola Ajimobi, eni ti Komisanna feto ijoba ibile ati eto oye jije, Onarebu Isaac Ajiboye Omodewu, soju fun n gbe opa ase le Oba yii lowo, o ro o lati lo gbogbo ohun to wa ni ikawo re lati fi ran awon eeyan to n dari lowo. Bee lo ni ki oluaye yii mu agbega ba ipo oriade nipinle Oyo.Gomina Abiola Ajimobi lo asiko naa lati ki gbogbo awon omo Ibapon nile ati loko, pataki julo Oba naa to je, to si gbadura pe Olorun yoo fun un ni ogbon ti yoo maa fi dari ilu ati emi gigun, ti ayipada rere yoo si de ba eto isakoso re lori oye. Igba odun, odun kan ni.

Lati ipinle Sokoto, lapa oke-oya ni Alagba Suaib to je olori ebi gbogbo omo Ibapon ti se wa ni nnkan bi irinwo odun seyin, eni to je omo Shieki Uthman Dan Foddio, eni to kuro ni agbegbe oke-oya, to si wa si apa agbegbe Guusu ni orile-ede Naijiria fun igbe aye irorun.

Si iyalenu, Alagba yii tedo si agbegbe kan ti won n pe ni Lagate, nibi to ti lo opolopo odun ko too di pe o waa tedo si Ikoyi-Ile. Nitori agbara to ni ati bo se je eni to see fokan tan ati oloooto ni Oba Olukoyi igba naa fi fi i je Bobajiroro (gege bii Alfa oba). Siwaju si i, nigba ti Oba Onpetu Asamu loo sabewo si Olukoyi laafin re to wa n«Ikoyi-Ile, nibi to ti ri baba nla won Suaib, to si so fun un pe ko maa ko bo wa sodo oun nitori ise Alaafaa to yan laayo to si mo dunju. Ise naa te Oba Onpetu igba naa lorun, eyi lo fa a to fi fun un ni omo re obinrin, Olanike, lati fi saya pelu opolopo ile lati fi riri ohun ti okunrin naa se fun Oba yii han. Leyin eyi ni Alagba Suaib yi esin Olanike pada si musulumi, to si so oruko re ni Kosenatu.

Igbeyawo laarin Suaib ati Olanike so eso rere, Olorun fun won ni omokunrin kan toruko re n je Ismaheela. Leyin eyi ni Oba Onpetu ran awon omobinrin ti yoo maa je iranse fun won lati maa ba won gbe omo tuntun jojolo naa, pipon ti awon omobinrin ohun maa n pon omode ohun kiri adugbo naa lo je kawon eeyan maa pe abule naa ni ∆Abule Alaagbapon«, ibi yii si ni won ti mu oruko Ibapon jade.

Si iyalenu, leyin iku Alagba Suaib ti i se Baba Ismaheela, Oba Onpetu igba naa fi omo naa je Baale akoko ni Ibapon, oun lo si je Baale akoko ni Ibapon Orile. Omo meji ni Ismaheela bi, oruko won ni: Muhammed Sufa ati Alhaji Ajani. Leyin iku e ni Muhammed Sufa di Baale keji n«Ibapon, aburo re lo si gba ipo Baale leyin igba toun ku. Eyin e ni Sheikh Sanusi omo Muhammed Sufa gba ipo Alaaji Ajani. Yakubu omo Ajani lo je leyin eyi, ti Alaaji Lawani je tie, nigba ti Garuba Ajao je Baale Ibapon leyin eleyii naa. Alaaji Buhari Akande gbapo leyin Garuba Ajao, leyin iku Buhari ni omo Alhaji Abdul-Raheem Atanda di Baale Ibapon.

Leyin oreyin, Oba Onibapon ti Ibapon, Alaaji Abdul Wahab Akanji Asifatu gori ite baba re leyin ti Alaaji Abdul Raheem Buhari ti gbese.

Alaaji Abdul-Wahab Akanji Asifatu ni omo oloogbe Alaaji Asifatu ti i se obakan Alaaji Buhari Akande. A bi i ni odun 1956 sinu agboole Baale Ibapon.

Ni odun 1964-1972 ni o lo sile-eko alakoobere ti A.U.D to wa ni Masifa. Nigba to pari nibe, o lo sileewe eko larubawa Arabic / Islamic Institute of Nigeria, Elekuro, n«Ibadan, ni odun 1973-1975. Leyin eyi lo lo sileewe Adeleke Progressive Evening College laarin odun 1976 ¬1978. Leyin oreyin lo lo sileewe olukoni agba to wa l«Offa, iyen Offa Teachers« College, lodun 1983- 1986, ko too tun lo si St. Andrews College, Oyo, lodun 1991-1995.

Alaaji Abdul Wahab Akanji Asifatu, Baale Ibapon ti sise oluko fun opolopo odun to si je akowe ninu agboole Ibapon bere lati odun 1974 titi di asiko tiku pa oju Alaaji Abdul- Raheem Atanda Aaro, Baale Ibapon to gbese de.

Yoruba bo won ni inu eni ki i dun ka pa a mora, eyi lo mu Oba Abdlwahab Akanji Asifatu Onibapon ti Ibapon fi idunnu han, to si nawo idupe ati imoore re si Gomina Abiola Ajimobi, bee lo femi imoore han si Komisanna naa atawon Kabiyesi to waa ye e si pelu awon alaga ijoba ibile ati bee bee lo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 02:44:53 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Ope O, Gomina Ipinle Oyo Fun Onibapon Ti Ibapon Lopaa Ase" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: