Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Owo Olopaa Te Ramoni Atawon Emewa re, Eyederu Owo Ile Okeere Ni Won N Se Fawon A
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Solomon Adewoye

Owo Olopaa Te Ramoni Atawon Emewa re, Eyederu Owo Ile Okeere Ni Won N Se Fawon Araalu

Sinkun lowo awon olopaa erekusu Eko to wa nile nla ti won n pe ni Lion Building te awon afurasi odaran to maa n gba owo gidi lowo awon to ba fee sewo (paapaa owo ile okeere) ti w on yoo si da ayederu pada fun won laije pe awon iyen fura rara. Abudulrahman Yusuf, eni odun merindinlogota atawon emewa re mefa mi-in, Kunle Adewale, omo odun mejidinlogbon, Nurudeen Akinsanya, eni ogoji odun, Femi Emmanuel to je omo odun mokandinlogoji, Adamu Sanda omo odun merinlelogoji, Akeem Ajenuyi to je ogota odun ati Yusuf Idris toun ko mo ojo ibi re rara ni won ti wa lakolo ijoba bayii.

Se a ki i wa ori ti nile iku, ayederu owo ile okeere si wa lowo awon eeyan yii nigba towo awon olopaa to n sode kiri lopopona Marina, l’Ekoo te won. Koda, egberun mewaa owo dola to je ayederu atawon owo ile Geesi ti won n pe ni Pound Sterling ni won ba lowo won.


Gege bi alaye ti Abdurahmon to je olori iko to n lu awon eeyan ni jibiti owo yii se fawon olopaa nigba towo palaba won segi, o salaye pe ileese tawon ti maa n sewo, Bureau de change’ gege bii awon oloyinbo se n pe e, wa lojule ogun, ikejilelogun ati ikerinlelogun, laduugbo Abibu Oki, eyi to wa l’erekusu Eko nibe.

Okunrin to n dari iko agbaniloju naa te siwaju pe nise lawon maa n fi ogbon gba owo lowo awon onibaara to ba mu owo wa lati se, awon yoo si mu owo naa wo iyewu awon lo pelu ero pe lati se e si tile yii tabi si eyikeyii ti kositoma naa ba fe, sugbon bawon se wole lo yen, nise lawon maa mu ojulowo tawon gba yen pamo, tawon yoo si da ayederu pada fonibaara, bee lawon yoo so fun un pe iye to fee sewo yen ko pe; awon, nitori naa, ko maa mowo re lo.

Ramoni so pe nigba teni to waa sewo ko si le ri iyato kan to fara han ninu owo tie ateyi tawon da pada, nise ni yoo gbe ayederu lo sile lai mo pe kantafiiti owo loun n di meru kiri.

Lorii bi won se n huwa laabi naa ti awon ti won ba lu ni jibiti ko fi wa n ba won ja tabi folopaa mu won, o salaye pe bawon ba ti fa awon eeyan lori tan bee, nise lawon yoo kuro lagbegbe yen fasiko die tawon yoo tun gba ibomi-in lo to fi je pe bi won ba wa gan-an won ko le ba awon nibe.

Ofi kun alaye re pe nigba tawon si kuku ti ni awon alafeyinti to maa n ba awon woju ile nigba tawon ba sise jibiti awon tan, awon iyen yoo ti fun awon lowo, awon ko si ni i yoju sitosi lasiko yen. Bi enikan ba waa mu oloopaa wa, o mu un wa feleda re ni, iyen ko je ki wahala kankan wa fawon, nigba to ba se die lawon yoo tun pade sibe tawon yoo tun maa ba ise lo.

Bakan naa lo salaye pe titi kan papako ofurufu to wa n«Ikeja lawon maa n ko ayederu owo lo ti awon arinrin-ajo yoo si maa faimokan se e lowo awon ti won yoo maa ko o lo sorile- ede Europe.

Baba to ti sun mo ogota odun tan naa tun so o di mimo pe bawon ba gba ojulowo owo tan, nise lawon yoo pin in laarin ara awon, ati pe lojo towo te awon yii gan-an, awon sese fa awon kan lori tan laduugbo Toyin ati Muyi, l’Ekoo ni.

Sa, Abdulrahman ni bijoba ba le tu awon sile nigbekun awon olopaa, awon ko ni i sise jibiti lilu naa mo. Sugbon ipe re yii ko ta leti awon agbonfiro rara, nitori nigba ti Koburu Adeyemi Tunde to n sewadi lori awon eeyan naa pari iwadii re, ile-ejo Majisireeti to wa ladugbo Tinubu, l’Ekoo loro won ja si. Nibe ni agbenuso ijoba lori ejo naa, A.C Orti, ti so pe iwa odaran lawon eeyan naa hu, o si tako abala 409 ati 370 ofin ipinle Eko.

Nigba ti won beere lowo awon afurasi odaran ohun boya won jebi esun ti won fi kan won tabi bee ko, ohun ti won so ni pe awon ko jebi. Eyi lo mu Adajobinrin, Omidan A.OAwogboro fi aaye beeli awon eeyan naa sile pelu owo ti iye re je egberun lona eedegbeta naria (N500,000) ati oniduuro meji ti won ni iru owo bee lowo.

Adajo sun igbejo mi-in si Monde, ojo kefa, osu yii fun itesiwaju, sugbon Abdulrahamon atawon emewa re ko ri anfaani beeli naa je nitori won ko ni oniduuro to ni ohun tile-ejo n fe, awon funra won ko si niru owo bee lakata, n ni won ba ko won lo sogba ewon Ikoyi, nibi ti won yoo gba loo jejo won.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 02:46:17 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Owo Olopaa Te Ramoni Atawon Emewa re, Eyederu Owo Ile Okeere Ni Won N Se Fawon A" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: