Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Segun Ati Ore E Ti Jewo Fawon Olopaa, Won Ni: Nitori Olokada Yen Je Omode La Fi
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
Lati Owo Johnson Akinpelu

Segun Ati Ore E Ti Jewo Fawon Olopaa, Won Ni: Nitori Olokada Yen Je Omode La Fi Gba A Lowo Re, A Ko Ni i Lokan Lati Jale Tele

Pipa ni won fee pa awon omokunrin naa, Segun Afolayan ati Folorunso Owolabi. Awon olokada Orita Challenge, n’Ibadan, ko mu oro naa ni kekere rara, won ni ole lawon omokunrin ti won pe ara won ni mekaniiki ohun, o si di dandan ki awon da seria fun won. Kia ni won ti fi apola igi, irin, okuta atawon ohun ija oloro mi-in de gbogbo eegun ara won tan pata. Leyin naa ni won ja won sihooho, afi bii eni pe iyen ko to gege bi ijiya, n ni won ba pinnu lati dana sun won ki won kuku ku patapata. Bi ki i baa se pawon olopaa tete debe ni, won iba ti dana sun awon eeyan naa bii eran.

Eeyan ko le ri Segun ati Folorunso nibi ti won ti n lu won lalugba ki aanu won ma seeyan, sugbon beeyan ba gbo iroyin itu ti won lawon eeyan yii fi awon ara Orita Challenge pa, bi oluwa re ko ba kiyesara, o le ma mo igba toun paapaa yoo maa ko igi bo won.


Gege b’Iwe Iroyin Yoruba se gbo, jeje ni olokada n sise aje tire laduugbo Orita Challenge, ti awon okunrin yii da a duro ni nnkan bii aago merin irole Ojoru, (Wesde), ojo kerinlelogun, osu kerin, odun yii, won ni ko gbe awon de Idi-Iroko. Nigba ti won de oju olomo-o-to-o, won ni ko duro, okunrin naa si fere ma ti i duro tan ti won ti da aimoye igbaju olooyi bo o, bee ni won re e bo sile lori okada. Won ni bo ba pariwo penken, ibon lawon yoo fi fo ori e danu. Bee ni won fipa ja okunrin naa lole alupupu re ti nomba e je GNN 134 QB.

Ariwo, “E gba mi o, awon ole ni o,’’ ti okunrin olokada naa n pa lawon egbe e ti won wa nitosi gbo ti won fi gba ti Segun ati Folorunso. Bi owo si se ba won ni won bere si i rojo iya le won lori. Won ti n seto lati wa taya moto ati epo bentiroolu ti won yoo fi dana sun won kawon olopaa ti won n paara igboro Ibadan kiri lati ri i pe alaafia joba too de ba won nibe.

Insipekito Usman Dimka la gbo po saaju awon agbofinro ohun, ti won gba awon afurasi ole naa sile lowo iku, ti won si fa won le awon agbofinro tesan Orita Challenge lowo.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe bi won se ko awon okunrin naa de ago yii ni okan ninu awon ti won ti ja lole so fawon olopaa pe ki won mu won daadaa. Okunrin ohun ti won pe ni Akin Folajinmi so pe awon afurasi ole yii ni won fipa gba oko ayokele Toyota Sienna oun ti nomba e je LND 393 AW lowo oun lojo ketalelogun, osu kejila, odun 2012.

Bi awon afurasi adigunjale yii se n pe si i nibi tawon olopaa tesan Challenge ti n sewadii won ni oro ti n foju han pe ogbologboo adigunjale lawon okunrin naa i se. Bi enikan ba de ago olopaa ohun to ba foju kan Segun ati Folorunso, lojiji ni yoo pariwo pe haa, awon to waa ka mi mole ti won ji mi ni moto ree. Bi tohun de, a a ni awon to waa ka mi mo soobu ti won ji mi lowo ati ero ibanisoro ree. Bee lokodoro oro tawon olopaa iba maa fi opolopo asiko sewadii le lori rora n te won lowo were.

Nigba toro ti ri bayii, awon agbofinro naa ko foro fale mo ti won fi gbe won lo si eka ileese olopaa ipinle Oyo to wa ni Iyaganku, n’Ibadan, fun iwadii siwaju.

Okan ninu awon ti won fidi e mule pe ogbologboo ole lawon okunrin meji naa salaye pe, ƒAwon okunrin yii ni won waa ja mi lole ni soobu lojo Satide, ogunjo, osu kerin, odun yii.

Soobu mi ni mo wa lona Asipa, niwaju Orita Challenge, tawon okunrin meta yen gun okada waa ba mi ni nnkan bii aago meje aabo ale. Eni to gun un jokoo sori e nita, awon meji wo soobu waa ba mi.

“Mo ri oju eyi to pera e ni Afolayan yii, o ni oun fee ra ike omi Eva nla. Bi mo se ni ki n si firiiji ki n mu omi bayii, mo gbo, ‘Wo o.’ Bi mo se wo eyin bayii, o kan rora si ewu ankara to wo soke, ni mo ba ri i pe ibon lo fi ha ibi sokoto. Bo se fa ibon yo to na an si mi lorun niyen. O ni to o ba pariwo, ma a yinbon pa e danu.

“Aya mi ja. Awon eeyan wa ni soobu to wa niwaju odo mi sugbon ariwo jenereto ti kaluku tan ko je ki won gbo ohun wa. Won gba baagi owo mi, egberun mejidinlogota naira (ö58,000) lo wa ninu e pelu kaadi ti mo fi maa n gbowo ni banki ati iwe-eri agunbaniro mi. Bee ni won gba ero ibanisoro Blackberry ati Nokia mi lo.

Gbogbo yeti goolu mi ni won ko lo patapata.

“Nigba to ya lo fi igbunwo gun mi leyin, nibi ti mo ti subu lule ni mo ti kolu awon oja ti awon waini kan si re lule ti won fo niyen. Bi won se setan ni won ta le okada, ti won si n yinbon soke bi won se n lo. Asare tele won sugbon a ko ba won.” Okunrin olokada ti awon Segun tun ja lole ki asiri won too tu, Sarafa Jimoh, naa ba akoroyin wa soro, o ni, mole. Bi won se fa ibon yo si mi niyen, won ni awon maa yinbon pa mi ti mo ba pariwo. Bi won se gbe okada mi lo niyen, sugbon mo sare dide, mo si n kigbe ole tele won leyin. Bawon eeyan se ba mi mu won niwaju niyi.≈ Nigba to n ba akoroyin wa soro, okan ninu awon afurasi-adigunjale naa, Segun Afolayan, salaye pe, “Birikila ni mi. Ise kan la fee loo se lojo yen, fandesan ile kan la fee loo gbe tawon olokada fi n le wa loko.

Nigba ta a de ile eni ta a wa lo ti a ko ba a, a be olokada pe ko sowo lowo wa, pe ko gbe wa pada s’Orita Challege sugbon ko gba. Ba a se gba okada re niyen.

“Nibi ta a ti n gun okada yen pada s’Orita Challenge lawon olokada ti di ona mo wa niwaju, bi won se bere si i juko lu wa niyen.” Nje ki ni idi ti won se fipa gba okada lowo eni to gbe won, okunrin eni odun mejidinlogbon naa dahun, o ni, “Nitori pe a ko lowo lowo lati gun okada pada sibi ti a n lo ni, ibe si jinna. Ki i se pe okan mi ni mo fi se ohun ti mo se yen gan-an, nitori pe olokada yen je omo kekere ni mo se se e. Ki i se pe a ti pinnu pe a maa jale tele, nigba ta a debe naa ni ero yen so si wa lokan.’’ “Ako yo ibon tabi obe si eni yen, a gba a leti lasan ni. Baba kan naa ti puro mo wa bee ri, o ni a gba moto lowo oun.

“Awon olokada yen fee pa wa, die lo ku. Igi ni won fi n na wa fun bii odidi wakati kan. Won ja wa sihooho, won fee gbe wa lo sibi ti won ti maa dana sun wa lawon olopaa de.” Ninu oro tie, Folorunso Owolabi, eni ogbon odun toun naa pera e ni birikila so pe, “Esu lo lo wa debe. Igba ta a de ibi ta a ni ki olokada naa gbe wa lo la gba a lowo e. Sugbon nibi ta a ti n sa lo lawon olokada ti mu wa, ti won si bere si i ko igi bo wa kawon olopaa too de.” Nigba to n fidi isele yii mule, agbenuso fun ileese olopaa ipinle Oyo, DSP Olabisi Okuwobi-Ilobanafor, so pe awon afurasi-adigunjale naa yoo foju bale-ejo laipe sugbon won si wa ni Iyaganku, nibi tawon agbofinro ti n te siwaju ninu iwadii won.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 02:47:54 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"Segun Ati Ore E Ti Jewo Fawon Olopaa, Won Ni: Nitori Olokada Yen Je Omode La Fi" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: