Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ipo Oba Di Wahala L’Akure, Deji Atawon Oba Fee Gbena Woju Ara Won
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Solomon Adewoye, Akure

Ipo Oba Di Wahala L’Akure, Deji Atawon Oba Fee Gbena Woju Ara Won

Tijobako ba tete da soro to n ja rain-rain nile niluu Akure bayii lori oro awon oloye ti won ni ki won fipo won sile, afaimo ko ma yori si wahala laarin awon agbegbe to yi ilu naa ka. Idi ni pe awon oba alaye to wa lagbegbe Akure ti yari mo Deji ilu Akure, Oba Adebiyi Adesida Afunbiowo keji, lowo lori ta ni ipo oba to si ati eni to ye lati je oye laarin ilu naa.

Latigba atijo ni Deji ti joba le gbogbo awon ilu to wa lagbegbe re pata lori. Ede kan naa si ni won jo n so. Bee niwadii fi han pe gbogbo awon ilu to yi Akure ka patapata lo maa n bu ola ati eye fun un, sugbon ni bayii, olaju ti de, bee lofin si ti wo o pelu. Eyi gan-an ni ko je kawon eeyan mo eni to to ati eni to ye lati fi sori ite gege bii oba won.

Oro naa si ti di wahala nla laarin igbimo lobaloba to wa l’Akure.Te o ba gbagbe, lodun to koja ni Oba Adebiyi Adesida ro awon oba meji kan, Iralepo Isikan-Akure ati Osolo ti Isolo loye, oro naa si wa nile-ejo bayii. Eyi to tun waa sele bayii ni bi Deji se tun ro awon oba meji kan to wa lagbegbe Akure loye. Awon oloye naa ni Olu tilu Agunla, Omooba Sunday Salami ati Olu Alayere, Omooba Adeniran Aladetoyinbo. Awon mejeeji yii ni Alayede Ogbese Oba Iseoluwa Oluyede yan gege bii baale lawon ilu mejeeji yii, sugbon nise ni Deji to tun je alaga awon lobaloba nipinle Ondo yari pe oun loun letoo lati yan eeyan sawon ilu naa, ki i se Alayede. Eyi lo si mu un yan awon eeyan tire siluu mejeeji ohun, n loba ba di meji laafin.

Sugbon Alayede so pe niwon igba to je pe ki i se ijoba ibile kan naa ni awon wa pelu Akure, o ni Deji ko lase lati yan awon baale ati ijoye lawon ilu naa. O salaye pe ijoba ibile meji ni won pin Akure si, onikaluku lo si ni aala tire, nitori naa, Oba Adebiyi Adesida ko letoo lati wa sijoba ibile Ariwa Akure lati waa yan oloye tabi baale bi ko se awon oba to wa nijoba ibile naa.

O waa ro Deji lati tele ofin ati ilana tijoba la kale nitori pe ijoba ibile Guusu Akure nikan lo je tie.

Sugbon ninu oro ti Oba Adebiyi Adesida, o so pe lati ayebaye lo ti wa pe Akure lo je olu ilu fun gbogbo awon agbegbe to ku, bee lo je pe Deji nikan lo lase lati yan enikeni sipo niwon igba to je pe agbegbe Akure kan naa ni gbogbo awon ilu keekeekee ohun wa. Bee lo ni oro pe won pin Akure sijoba ibile meji latodo ijoba ki i se lati maa da nnkan se bi ko se kaye le derun fawon olugbe ibe ni.

O te siwaju pe ninu itan ati iwe ofin oro ile odun 1997, Deji Akure ni agbara lori oro ile ati iselu lawon ijoba ibile Ariwa ati Guusu Akure, to fi mo ijoba ibile Ifedore. Iwe ofin naa ni Deji fi gbe igbese pe Alayede Ogbese ko waa gba ase lodo Deji ko too yan awon baale naa lese.

Sugbon pelu gbogbo eyi, nise lawon oba alaye to wa nijoba ibile Ariwa Akure yari kanle pe Deji ko ni ase kankan lori awon ilu to wa nijoba ibile naa nitori ki i se alaga kan naa lo n dari awon, bee lawon ni igbimo lobaloba nijoba ibile naa.

Nigba ti okan ninu awon ti Deji ro loye to je Olu ti Alayere, Omooba Adeniran Aladetoyinbo, n ba awon oniroyin soro, o so pe Deji ko lase lati le awon kuro lori ite baba nla awon nitori ki i se oun lo fi awon sibe.

O ni eni kan soso to letoo lati yo awon kuro lori ipo naa ni eni to fi awon sipo ohun.

O fi kun un pe awon oba alaye to wa nijoba ibile Ariwa Akure lo pawo-po yan awon sipo naa, bee loro yii ko kan Deji rara.

Awon oba alaye naa ni; Alayede Ogbese, Oloba ti Oba Ile, Okiti ti Iju ati Ogbolu ti Itaogbolu. Won waa so pe awon ko nibi tawon yoo lo rara.

Sugbon Deji ni niwon igba to je pe awon oba to wa lagbegbe Akure ti di oba, won ko lase ju inu ilu won lo.

O ni oun nikan loun lase gege bo se wa ninu iwe itan ati iwe ofin ijoba ipinle Ondo lati yan ijoye kan tabi oloye sipo ni gbogbo ile Akure pata .

Awon ti won ro loye naa so pe pelu oro to n jade latenu Deji bayii, a je pe Ooni Ile-Ife, Oba Okunade Sijuade lo nile Akure, nitori latibe ni gbogbo awon ti wa, ati pe Ile-Ife lo ni gbogbo ile Yoruba.

Nibi toro de duro bayii, afaimo ki wahala ma be sile laarin awon oba to wa lagbegbe Akure lori isele to n sele naa.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 02:57:10 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Ipo Oba Di Wahala L’Akure, Deji Atawon Oba Fee Gbena Woju Ara Won" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: