Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Wahala Wa O: Gomina Fowo Awon Araalu Ra Eronpileeni
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Ademola Adejare

Wahala Wa O: Gomina Fowo Awon Araalu Ra Eronpileeni

Bii ere ni oro naa bere, sugbon ni bayii, oro ti di rannto. Eni ti yoo gba Gomina ipinle Rivers, Rotimi Amaechi, lowo Aare Goodluck Jonathan ni awon araalu ko ti i mo o, nitori bi nnkan ti wa yii, o jo pe okunrin Gomina naa ti bo sowo aye. O tojo meta ti ija won ti bere, latigba tawon kan ti le iwe alemogiri (posita) kaakiri Abuja, ti won ni Lamido fee dupo aare lodun 2015, ati pe Rotimi Amaechi ni igbakeji re ni wahala gidi ti bere fun okunrin Gomina naa. Se oun ni olori egbe awon Gomina, enu re si tole daadaa laarin won, nibi ti agbara re wa paapaa niyen, oun naa si ti mura lati lo agbara naa.

Sugbon nigba ti Jonathan atawon omoleyin re ti ri ibi ti Amaechi fee ba yo ni won ti dena de e, latigba naa ni ija to si ti n rugbo bo laarin oun ati okunrin olori Naijira naa ti feju, ti ina ija naa si bere si i jo titi di asiko yii ti awon omoose Aare ribi ko sekeseke si Rotimi Amaechi lowo.

Ko si tabi sugbon kan nibe, Rotimi Amaechi ko fi taratara gba ti Jonathan, o si jo pe o pe die ti aarin won ti n daru bo, eyi to ba oro naa je ni ti ese to n gbe pelu awon kan lati gba ise mo Jonathan lowo, Jonathan ko mu oro naa ni kekere o, loju-ese lo ti ri Gomina Rivers naa bii ota re, to si n so fawon omoose re pe eni to ba fee gba ise lowo eni, ota eni ni o. Igba yen ni alaga egbe PDP, Bamanga Tukur ti bere si i pariwo pe awon Gomina yii ti n koja aaye ara won o, ila won ti fee maa ga ju onire lo, ko si ki owo ma kan igi ila naa.


Nigba naa ni won sare so pe asiko ti to ki awon Gomina yii se ipade gbogbo ti won maa n se, ki won si yan eni ti yoo je alaga igbimo awon Gomina naa. Ohun ti won se se bee ni pe asiko ti to fun awon Gomina naa lati dibo, bi won ba fe Rotimi Amaechi, won yoo yan an leekan si i, bi won ko ba si fe e mo, won yoo yan elomiiran. Sugbon awon Gomina to ku kaakiri si feran Rotimi, oun ni won si fee mu lojo idibo won.
Bee Aare ati awon omoleyin re ti seto, ati alaga egbe won pelu awon ti won pe Amaechi yii ko gbodo wole leekeji, nitori bo ba wole, yoo ba ti Jonathan je ni, nitori awon Gomina ni yoo maa de si awon.

Nipa bee, awon naa ti sare gbe enikan dide ninu awon Gomina, won ni ko dupo naa pelu Rotimi. Sugbon bi eto ibo ti fee bere, bee lo han sawon asaaju PDP pe Amaechi yoo fi ibo ti won fee di naa kaa Jonathan labuku, nitori o jo pe gbogbo awon Gomina ti won wa nibe pata, tire ni won n se. Kia ni alaga egbe naa atawon asaaju won to ku ti pase pe ibo naa ko le waye mo, ki won sun un siwaju nikan lo ye nitori awon ni awon eto ti awon fee se ki won too le di iru ibo bee. N lawon Gomina ibe ba n yinmu, won n fi awon oga won naa se faari, won ni obe ti ba idi won. Awon alaga egbe naa ko duro sibe, lojo naa ni won gbe egbe mi-in dide, won pe e ni egbe awon Gomina ti won je omo egbe PDP, won si fi Godswill Akpabio, Gomina Akwa Ibom, se olori iyen.

Ohun ti eyi tumo si ni pe aarin awon Gomina naa daru, nitori egbe won ko le raaye ipade mo, se ohun ti won fee se ni lati yo awon Gomina PDP to ku kuro leyin Amaechi, nitori pe awon omo egbe naa lo po ju nibe.

Pelu gbogbo bi won se se yii o, Amaechi ko tori e fori bale, bee ni ko jawo ninu ohun to n se, ohun to si n so fawon ti won sun mo oun naa ni pe Jonathan n roko ete, oun yoo si fi abuku kan an daradara. O ni oro ko ti i too so, sugbon nigba to ba jade pe oun fee gbe apoti loun yoo jewo bi agbara toun ni ati ipo oun ni adugbo awon se to fun un. Nibi ti awon mejeeji ti n ba ara won fa a yii ni nnkan mi-in ti sele, nibe loro naa ti fo loju wa. Asiko ti won n sinku Igbakeji Gomina ipinle Ekiti tele, Funmilayo Olayinka, lojo kerindinlogbon, osu Kerin, to koja yii ni, ilu Akure ni ija Amaechi ati oga re niluu Abuja ti ba ona mi-in yo.

Amaechi wa gege bii awon Gomina to ku ni, sugbon nigba ti oun n bo, eronpileeni lo gbe wa, eronpileeni lo fi sese rin debe, o si wa nibe ti won jo se ayeye yen fobinrin naa ni. Igba to fee maa lo ni wahala sele, nitori bi won ti de idi eronpileeni won ni won gbo pe ofin ti de eronpileeni ohun, ko gbodo kuro niluu Akure to wa naa mo. Nje ki lo de Ki lo sele Awon ti wo n seto igboke-gbodo oko-ofurufu nile yii so pe ko si wahala, won ni iwe eronpileeni Amaechi ko pe, won ni ona aibofin-mu lo fi n gbe eronpileeni naa kiri nitori gbogbo iwe to ye ko gba ni ko gba, eyi to si je iwe to ni lowo ti le;jo;, o ti espaya bii oro awon oloyinbo, ohun ti ko le je ki won gbe e kuro niluu Akure niyen. Gomina naa fapa-janu, awon omo eyin re naa fese hale, won n soko oro buruku si won niluu Abuja. Won ni awon to mu eronpileeni naa ni ko sise won bii ise, won ni bi won ba sise won bii ise, won yoo ri i pe ko sohun to se iwe oko-ofurufu awon, ati pe gbogbo ofin lawon pamo.

Fun bii ojo meji si ojo meta ni awon osise ati ijoba ipinle Rivers fi n tu bii ejo, ti won n so pe ko sohun ti awon se. Sugbon lojo keta, awon ileese to n ri si irina oko-ofurufu gbe iwe jade loooto. Iwe ti won koko gbe jade ni pe eronpileeni naa, nomba ti ile Amerika lo wa lara re, iyen ni pe ki i se nomba ile Naijiria, bee ni eronpileeni naa ki i se tipinle Rivers, banki kan ni won so pe o ni in l’Amerika, oruko banki naa ni yoo si wa lara iwe naa titi di odun meta, leyin naa ni won yoo sese ko oruko eni to ni in si i. Ati pe ninu iwe adehun ti won se lohun-un, ko tie si oruko Rivers nibe, ti Gomina lo wa nibe, iyen ni pe bi odun meta ba pe, eronpileeni naa yoo pada di ti Gomina ni, ko si ni i bo sowo ipinle Rivers mo. Awon omoose Amaechi tun fese-hale, won sare gbe iwe mi-in jade pe bi won se se e l’Amerika niyen, ati pe ki eronpileeni naa le maa rin daadaa lawon se gba iwe Amerika si i, opo omo Naijiria lo si n se bee.

Eleyii ni won n se lowo nigba ti Minisita eto igboke-gbodo oko-ofurufu yii funra re, Stella Oduah jade, o ni ko si ki won ma ba ijoba ile Rivers sejo, nitori gbogbo iwe ti won n ko kiri ti won so pe awon fee fi gba iwease, ati eyi ti won fi n fo loju ofurufu lati ojo yii, ayederu ni. Obinrin naa ni ileese oloko-ofurufu kan ti won so pe o fun awon lase lati maa lo oruko won fi gba iwe-ase ti won ba fee fo lofurufu so pe awon ko mo won ri, koda awon ko gbo oruko won ri, won ko si mo pe won ni eronpileeni kankan, bee ni ko si adehun eyo kan bayii laarin awon. Iyen ni pe gbogbo iwe ti ijoba Rivers n ko jade, ti won fi n gbe eronpileeni yii kiri, aronda-ronda gbaa ni. Nigba toro naa jade sita wayi, won ko ri Komisanna tabi Gomina funra re, tabi amugbalegbee kan ti yoo soro jade mo, nise ni kaluku won wo sin, o si han gbangba pe afaimo ki Gomina won, Rotimi Amaechi, ma ti ha sowo Jonathan loooto loooto.

Iyen ni won n ro lowo nigba ti EFCC ba won da si i. EFCC ni awon ti tan oro naa de oju koko, iwe to wa lowo awon bayii ti fi han pe milionu metadinlaaadota owo dola (…47m) ni won fi ra eronpileeni naa, sugbon owo ti won yo kuro ninu apo ijoba Rivers, milionu metadinlogota owo dola (…57m) ni. Ohun ti eyi tumo si ni pe milionu mewaa dola ti poora, awon EFCC si so pe afi ki awon mo ibi towo naa wole si, ki awon si hu u jade. Esun ti EFCC n pale re mo fun okunrin Gomina yii ni pe o ra eronpileeni loruko ara re, o si pe e ni tijoba, ati pe to ba je tijoba, eelo lo ra a gan-an, won ni o fi oro eronpileeni naa ji owo ko lo si oke okun ni, iyen milionu mewaa owo dola. Nibi yii ni oro de duro, latigba ti awon asiri yii si ti jade, ko senikan to gbo kinni kan lati apa odo awon ijoba ati awon alase ipinle Rivers mo, awon ti won si ri ibi ti ina oro naa n jo lo so pe seesi ni Rotimi Amaechi ko ti ko tie lese-o-gbeji, afaimo ki won ma foju e ri mabo.
 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 03:05:43 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Wahala Wa O: Gomina Fowo Awon Araalu Ra Eronpileeni" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: