Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Awon Odaran Lo Ku Ti Yoo Maa Sejoba: Atiku, Iru Oro Wo Niyen?
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Ademola Adejare

Awon Odaran Lo Ku Ti Yoo Maa Sejoba: Atiku, Iru Oro Wo Niyen?

Kirikiri lo wa bayii Nibi ti oro ilu yii n lo yii, o jo pe apa awon oloselu atawon ti won wa nile ijoba ko ka ijoba mo, awon odaran, awon janduku, awon omoota ti obi ko to, awon ti ijoba ko fun nise se, awon ti won ti di idakuda siluu, awon yii ni yoo ku ti yoo maa sejoba wa.

Awon eeeyan ko beru olopaa nile yii mo, awon olowo ko beru won, awon oloselu ko beru won, won ti so awon olopaa wa nile yii di yeye pata, bee ilu ti olopaa ba ti di yeye, awon odaran naa ni won yoo maa sejoba.

Sugbon gbogbo olowo bayii lo beru awon gbomogbomo, won beru adigunjale, won si beru awon agbanipa.


Tabi olowo, oloselu abi eeyan pataki wo lo wa niluu bayii ti ko beru awon ajinigbe ti won n gbowo lowo won yii ju awon olopaa lo. E wo eyi ti won tun se lose to koja, adajo ile-ejo to ga julo nile wa, won gbe iyawo e, won gbe omo e, won si gbe dereba mo on. Ko si kinni kan ti won yoo fi eyi se ju ki won fi gba owo lowo won lo.

Nigba ti won ba n ko awon eeyan adajo lo bayii, ona wo ni mekunnu yoo gba, kin ni mekunnu yoo se. Ise ajinigbe ti di ise to de ile Yoruba bayii, ki i se pe awon kan lo n se e mo, Ibo nikan ko lo wa nidii e bayii, awon omode Yoruba naa ti ri i pe ona owo ni. E

yi to buru nibe ni pe yato si awon mekunnu, to ba je awon oloselu ni won gbe lonii, ariwo ti won yoo jade waa maa pa fun awa ni pe won ko gba kobo kan lowo awon, won kan fi awon sile nitori ise rere ti awon n se ni.

E wo alaga ijoba ibile Ejigbo ti won gbe lo laipe yii, nigba to de, ohun to so fun gbogbo ilu ni pe awon eeyan naa beere owo lowo oun, oun ko ri i fun won, igba ti won si waa wo ofiisi oun, ti won gbo bi awon eeyan ti n soro oun daadaa ni won fi oun sile, oga olopaa Eko lo sese n je ka mo pe owo nla lokunrin naa san fun awon ajinigbe naa ki won too le fi i sile, ati pe awon so fun un ko ma fun won lowo, sugbon awon ebi re ko da awon lohun.

A ko le ba awon ebi alaga yii wi pe won se sanwo, won kuku mo pe apa awon olopaa ko ka awon eeyan naa, won ko si fe ki won pa eni won danu lai pe ojo, eyi ti ko kan dara nibe ni iro ti awon oloselu wa maa n pa fun wa. Se bi won ba so ooto idi oro gbogbo fun wa, awa naa yoo mo bi a o se tun ara wa mu ati irin ti a o maa rin ti a ko fi ni i bo sowo awon ajinigbe.

O kuku ti han bayii pe apa awon ijoba Naijiria ko ka kinni ohun, ohun ti a o se, afi ki Olorun fi ona han ni.

Iru Oro Wo Niyen?

Abubakar Atiku so laipe yii pe ko si kinni kan laye yii to le mu oun fi egbe PDP sile, gbogbo ohun ti oun ba fee je laye, inu egbe naa loun yoo ti maa je e. Iru oro wo niyen. Iru oro rirun wo niyen. Se nigba ti Atiku yoo kuro ninu egbe PDP nijosi ti won yoo jo bere ACN, se enikan lo ni ko lo ni abi enikan lo le e kuro ninu PDP.

Sebi funra e lo lo, sebi funra e lo ni oun ko se mo, nigba to si su u funra re naa lo tun pada sinu egbe won.

Ewo waa ni ariwo bayii pe oun ko le se egbe oselu mi-in, oun ko si le kuro ninu PDP. Ko si eni ti ko mo ogbon ka feran senu ka wa a ti o jare, ko seni ti ko mo ohun to n sele, ko si seni ti oro oselu Naijiria ko ye.

Eni to ba fee se oselu, to je ko maa fi jeun lasan ni, tabi to je ko wa nipo ti won yoo fi jo maa ri nnkan ini Naijiria pin ni, ti won yoo si maa kowo min, ko si inu egbe oselu tiyen le wo ju egbe PDP lo, egbe to je ko sohun ti aaye ko gba nibe, egbe to je eni to ba wa nile ijoba lalagbara.

Tabi apa ibo, ona ibo ni Atiku yoo gba ti yoo fi tun raaye wole gege bii aare, yato si bi egbe PDP ba fa a kale. Oun naa mo pe bi egbe PDP ba ti le fa oun kale, o pari niyen, lagbara ojooro, lagbara owo ijoba, lagbara tipa-tikuuku, won yoo gbe oun debe dandan. Sugbon kin ni egbe yii se fun Naijiria, oore kin ni won se fun wa latojo ti won ti n wa nile ijoba, kaka ki nnkan tile waa san, nise lo n le si i. Oosa bi o ko ba le gbe mi, se mi bo se ba mi ni oro wi, PDP ko se Naijiria bo se ba Naijiria, won tubo n lu u fo si i ni.

Eyi ti a ko gbo ri lo ku ti a n gbo bayii, ogun iku loni-in, bombu lola, won yinbon pa enikan lotunla, won ji won gbe lojo merin, Boko Haraamu nijo karun-un, won kowo nla je lojo kefa, awon adigunjale payaan ki won too ji owo gbe lojo keje, ijamba moto run ogoji eeyan leekan lona Ibadan, sebi ohun ta a n fi ojoojumo gbo niyen. Bi Atiku ba si nitiju ni, bo ba tie pada sinu egbe won, yoo jokoo tie jee nitori ibi po ninu egbe naa ju u daadaa lo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 03:09:18 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Awon Odaran Lo Ku Ti Yoo Maa Sejoba: Atiku, Iru Oro Wo Niyen?" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: