Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun
[ Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun ]

·Gbigba Kadara Gbo - Al-Imaan Bi-l-Qadar (Ayanma Tabi Akosile)
·Umaru Gbe Oogun Wo Kootu, Ladajo Ba Da Igbejo Duro Kia
·Fasasi Ko Iyawo e Sile N'Ibadan, O Ni Ko Ro Amala Fun Baba Oun
·Adajo Ni Ki Won Fi Emmanuel, Ayederu Looya, Sogba Ewon Kirikiri
·Alake To Fee Ko Oko Dero Ewon N'Ilorin
·Yekeen Fee Ko Munira n'Ilorin, O Ni Latigba Tawon Ti Fera Loun Ti n Ru, Tou
·Adajo Ni Kawon Ebi Oko Medinat Da Ogun Oko Re Pada Fun un
·Igbeyawo Ogun Odun Daru L'Osogbo
·Lori Oro Ti Ko To Nnkan, Awon Olopaa Fibon Fa Femi Lorun Ya, Ni Won Ba Sa Lo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Eni Kan Ko Le Da Yan Asaaju Fun Yoruba O
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Ademola Adejare

Eni Kan Ko Le Da Yan Asaaju Fun Yoruba O

Bi e ko ba gbagbe, mo so fun yin lose to koja bi mo ti ba aburo wa to n te iwe Iwe Iroyin Yoruba yii, nitori mo ri i pe eni ti oro Yoruba je logun ati akikanju eeyan to le se alaga igbimo ti a fee gbe dide ti yoo ba wa kiri ile Yoruba ti yoo si seto bi a se le yan asaaju wa ni. Aburo wa yii loun ko se, nigba to si salaye idi ti ko fi se fun mi, ko si ohun ti mo le se ju pe ki n fi i sile lo.

Sugbon mo ba a soro ko je ki n so iriri oun fun gbogbo omo Yoruba ki a le fi oro re se arikogbon, ko si le ran wa lowo lati yan asaaju wa. O waa salaye bi ileese oun se ko awon agbaagba Yoruba jo leemeta laarin odun 2002 si 2006, ati bi gbogbo apero yii se ja si pabo, ti awon si pinnu lati jawo ninu e, ki awon wa nnkan mi-in se fun gbogbo omo Yoruba lodun 2007.Iwe Iroyin Yoruba so fun mi pe ohun ti awon fee se naa ni odun asa ati ise fun gbogbo omo Yoruba, awon fee fi odun naa ko gbogbo omo Yoruba jo ni, ki won si fi ayeye naa pile eto idagbasoke fun iran omo Oodua. O ni nigba ti eto yii bere, oun tun rin sun mo awon agbaagba Yoruba lati fi to won leti, opolopo won si so pe ko si bi oun se le se eto naa bi ko ba ni owo ijoba awon ile Yoruba ninu. O ni Wole Soyinka ni oun koko ri, oun si so fun un ko ti oun leyin, ko je asoju awon kaakiri agbaye nidii odun naa. O ni Wole gba, iyen lawon se mura lati se ayeye iwuye fun un bii Asoju Agbaye (Global Ambasaador), ti Wole funra re si so pe Abeokuta loun fe ki ayeye naa ti waye nitori ese oun kan ti n wa l’Abeokuta.

Iwe Iroyin Yoruba ni nigba to je Abeokuta lawon ti fee sewuye fun Wole, o di dandan ki oun so fun Gomina, oun si loo ri Gbenga Daniel funra oun, inu Gomina naa si dun. Bee lawon pe oba ati ijoye, ati ijoba gbogbo wa si Abeokuta lati fi Wole se Asoju Odun Asa Yoruba naa.

O ni bo tile je pe awon ara Eko wa sibe, ti ijoba Eko si ni asoju ninu igbimo awon, bi awon ti se ayeye naa tan ni orisiirisii oro bere si i jade, won ni awon fee so Gbenga di asaaju Yoruba lawon se loo seto naa l’Abeokuta. Aburo wa yii ni nigba ti oro naa fee da eto awon ru ni eni kan ninu komiti awon, Adeniji Adele to je komisanna l’Ekoo ba so pe bi awon ko ba fe ki kinni naa daru, ki awon tete fi Bola Tinubu naa joye kan o, ki eto naa le fese mule.

Aburo wa yii ni oun funra oun loun gbera ti oun loo ba Bola nile, nigba ti oun si salaye fun un, inu re dun gan-an. O ni o gba pe ki awon se ayeye iwuye foun naa, nitori oye ti awon fi je ni Asoju Apapo, iyen National Ambassador fun ayeye naa. Iwe Iroyin Yoruba ni oun salaye fun Bola pe bi awon ba fee se iru nnkan bayii, gbogbo Yoruba ni yoo se e o, awon ko le se e ni ipinle kan, tabi ko je egbe oselu kan ni yoo se e. O ni Bola so pe oun mo, o si salaye pe ko si bi eniyan se le se iru nnkan nla bee ti ko ni i je gbogbo omo Yoruba ni yoo se e, o lo so foun pe iru eto bee ko gbodo je tawon oloselu rara, ti gbogbo omo Yoruba ni. Iwe Iroyin Yoruba ni nibi ti inu oun ti dun niyen, ti oun si mo pe kinni naa yoo se e se. O ni sugbon nigba ti Gbenga gbo pe oun loo ba Bola, Gbenga binu, o si pe ki oun too le salaye oro fun un.

Nibi ti won ti fee se ayeye ifinijoye ti Bola ni wahala ti bere. O ni awon ti dajo, awon si ti jo so pe gbogbo oba lawon yoo ko wa si Eko, awon si jo bere eto naa ni. Iwe Iroyin Yoruba ni oun lo sodo Ooni, Alaafin, Alake, ati awon oba nla nla mi-in, nitori oun fe ki won le lo eto naa lati pade ara won, ki won si pari ija nigba to se pe Oba Eko ni yoo gba gbogbo won lalejo. O ni Alaafin so foun pe oun yoo wa. Ooni ni eto nla kan niluu Kano lojo naa, nitori ojo naa ni Bayero University n se ayeye ikekoojade won, bee Ooni ni Baba Isale Yunifasiti naa, bi Oba naa ba si ti lo si Kano bee, ose kan lo maa n lo lodo ore re, Ado Bayero, sugbon nitori eto naa, ati lati fi ife han si Bola ati oun Iwe Iroyin Yoruba, bi eto ba ti pari ni Kano, o loun yoo de Eko lojo naa.

Bi gbogbo eto yii se n lo, Iwe Iroyin Yoruba so fun mi pe bee loun n fi to Bola leti, ti awon si jo n wo bi ayeye naa yoo se dun daadaa, afi bi awon kan se dide ti won n yo Bola lenu pe awon ko fe ki Ooni wa sibi ayeye naa.

Omokunrin yii ni nise loun pariwo nigba ti Bola so foun. Abi, Baba to fee pa eto nla pataki bee ti lati waa ye awon si, ti yoo si ti Kano sare wa si Eko, awon wo ni yoo waa duro sibi kan ti yoo so pe awon ko fe Ooni, nigba to se pe ijokoo Oba yii yoo tubo mu aponle ati iyi nla waa ba ayeye naa ni. Nje kin ni Ooni se, won ni won so pe won ko fe ki Ooni wa sibe wa maa se bii eni pe oun ni Baba gbogbo aye. Iwe Iroyin Yoruba ni nigba ti oun ati Bola jo ye oro naa wo daadaa, Bola so pe oun yoo ba awon eeyan naa soro, ko si wahala, ki oun loo fokan bale ni toun.

O ni lojo Satide ti ayeye naa ku ola, nitori Sannde, ojo keji, osu keta, odun 2008 lawon se e, akowe Alaafin pe oun, o si salaye foun pe Alaafin ni ki oun so foun pe awon oba meeedogbon ni won n ba oun bo lati Oyo o, ko seto ibi ti awon yoo wa pelu awon olopaa ati awon iranse gbogbo, iyen ni pe ki oun seto yara bii ogoji sile fun won, nitori irole layeye naa, enikeni to ba ti idale wa ko le pada lojo naa. Sugbon awon ti won n yo Bola lenu l’Ekoo daamu e titi debii pe laaaro ojo ayeye naa ti Ooni ti wa l’Ekoo, funra e lo pe Ooni to dupe lowo e, to so pe ayeye naa ki i se nnkan nla to ye ki won wa, nnkan kekere ni, ki won ran awon oba die wa, ki awon maa sinmi ni tiwon, ki won ma yo ara won lenu pe won n bo rara. Iwe Iroyin Yoruba ni oro naa da oun lokan ru debii pe nise lo da bii ki oun wole, nitori Ooni ko wa mo, bee nitori ayeye naa lo se wa l’Ekoo.

Ase nnkan mi-in tun n bo. Alaafin to ni pe oun atawon oba meeedogbon lawon n bo, pelu awon olopaa, ki won gba yara sile, Alaafin ko wa mo, bee ni ko si ran-an-yan, Oloun nikan lo mo awon to tun so fun oun naa pe ko ma yoju. Iwe Iroyin Yoruba ko mo, bee ni ko so fun won ni Airport Hotel to ti gba yara bii aadota si pe awon alejo oun ko wa mo, bee ni gbogbo owo to san sile jona pata!

Se e n fokan ba oro yii lo? Oro ti aburo wa yii so fun mi ko i tan o, nitori e ni n ko se le soro rara nigba to ni oun ko ni nnkan kan i se lori oro asaaju Yoruba, pe gbogbo ohun ti a ba fe, iwe iroyin Iwe Iroyin Yoruba yoo maa gbe e jade, yoo si maa so fawon omo Yoruba gbogbo. Bo ba dose to n bo, n o salaye ohun to so fun mi pe o sele leyin ayeye naa ati bi awon oloselu se fori eto naa sogi, ki gbogbo wa le ri nnkan fi kogbon ka too yan asaaju wa ni o.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 03:10:05 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Eni Kan Ko Le Da Yan Asaaju Fun Yoruba O" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: