Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
[ Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose ]

·Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi
·Eyi Ni Bi Pasito Se Gbe Majele Je Ni Ipinle-Ogun
·Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
·Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
·Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
·Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
·Orekunrin Bukola Fee Fi i Soogun Owo N'Ibadan
·Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo
·Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


O Ti D'oju E Bayii O! Orebinrin Ayo Gun Un Pa N’Ibadan, Omobinrin Naa Lo Fe
 
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

O Ti D'oju E Bayii O! Orebinrin Ayo Gun Un Pa N’Ibadan, Omobinrin Naa Lo Fee Fipa Ba Oun Lo Po Ni

Manigbagbe lojo Aiku, Sannde, ojo karun-un, osu karun-un, ta a wa yii je fun omodebinrin omo Ibo kan to n je Orakwuelum Onyinyechi to fi adugbo Ologuneru, n’Ibadan, sebugbe. Lona kin-in-ni, ojo naa lo pe eni odun mejidinlogun laye. Sugbon idunnu ayajo ojoobi ohun ko lo titi nitori nigba ti ile ojo yii kan naa yoo fi su, isele nla ti ko le gbagbe titi ojo aye e ti fi ibanuje ropo ayo ohun lowo ale, nitori ahamo awon olopaa lo pada sun lojo naa nitori bo se gun omo olomo lobe pa.

Onyinchechi la gbo pe o tele ore re okunrin ti won jo lo sileewe girama kan naa lo sile lati se awejewemu fun ayajo ojo-ibi e lale ojo naa, sugbon lojiji lesu ko si won laarin to bee to di ohun ti won n gun ara won lobe pa.


Gege bi Iwe Iroyin Yoruba se gbo, omokunrin ohun to n je Akinwale Ayobami lo koko pe Onyinchechi lori ero ibanisoro sugbon foonu ko si ni arowoto omobinrin yii nigba naa. Eyi lo mu ko pe omokunrin eni odun mokandinlogun ohun pada. Nibi ti won si ti n soro lo ti so fun un pe ojo naa ni ojoobi oun. N ni Ayo ba ni ko wa sile oun ki oun we e fun un.

Ko seni to mogba ti omobinrin eni odun mejidinlogun naa loo pade Ayo ni ikorita Ologuneru, ti iyen si mu un lo sile won laduugbo naa. Afi ni nnkan bii wakati kan sigba naa ti Onyinchechi sare gbon pepe loo ba iya e nile, to ni oun ti gun eeyan lobe.

Iya omo Ibo yii la gbo pe o mu imoran wa pe ko je ki awon tete loo fi isele naa to awon olopaa leti. Loju-ese lawon agbofinro ti ba a de ile awon Ayo, ti won si ba omokunrin naa ninu agbara eje ninu yara ijokoo won nibe. Nje ki won gbe e nile, ki won le sare loo toju e nileewosan ni won ri i pe omokunrin ti lo.

Nigba naa ni won mu Onyinchechi ti mole ni ahamo won ni Ologuneru, won lo ni lati salaye idi to fi gun omo olomo lobe pa. Ko si pe rara ti won fi gbe e lo si eka ileese olopaa ipinle Oyo to n ri si iwadii esun odaran, iyen CSID, Iyaganku, n’Ibadan. Nigba to n salaye isele naa fun akoroyin wa, obinrin eni odun mejidinlogun naa so pe loooto loun gun Ayo lobe nigbaaya, nitori to fee fipa ba oun lo po sugbon oun ko se e pelu ipinnu lati pa a.

Gege bo se so, “Ileewe Girama St Gabriel to wa ni Mokola, n’Ibadan, ni mo ti jade iwe girama. Akegbe mi ni Ayobami je nileewe wa, kilaasi kan naa la wa sugbon a ko sun mo ara wa nitori ki i se eka eko kan naa la wa. Eka eko imo nipa kara-kata loun wa, emi wa ni eka eko imo nipa isesi eeyan ati awujo. Sugbon oun ko pari nileewe wa to fi kuro to gba ileewe mi-in lo.

“Awon obi mi sese ko lo sile wa tuntun ni Ologuneru ni. Eyi lo je ki n jinna si opolopo awon ore mi nitori a ko lanfaani lati maa rira mo nigba ta a ti ko lo sile tuntun. Lojo kan ni mama mi de, won ni awon ri ore mi kan to n je Funmbi. Won lo so pe awon naa ti ko de Ologuneru bayii. Inu mi dun, a si wa ara wa kan. Ba a se bere si i se ore wa pada niyen.

Nigba to ya lo lanfaani lati wo ileewe giga fasiti. Nigba to wa sile ninu osu kerin, odun yii, lo so fun mi pe se mo ranti ore wa kan ti a n pe ni Ewizzy. O ni awon jo soro lori ayelujara, o si so pe Ologuneru loun naa n gbe. O lo ti so fun oun pe ki oun (Funmbi) waa pade oun (Ayobami) ni orita kan ki oun le mu un lo sile awon. Mo so fun Funmbi pe mi o le tele e lo nitori emi ko mo eni to n je Ewizzy. Nitori mi o ranti eni to n je Ewizzy yen loun nikan se da lo.

Lojo to tun fee lo sibe, o ni ki n je ka jo lo, mi o koko fee lo nitori mi o ranti eni to n so yen, mo si so fun un pe mi o le lo. O waa be mi pe ki n je ka jo lo. Nigba ta a debe, a ba a nile, orebinrin re naa wa pelu e to sun sori aga nla. A bere si i ranti awon egbe wa kookan ta a jo jade ileewe, a soro won lokookan ati gbogbo ba a se jo maa n se nigba yen. A ko pe nibe ta a fi kuro. O beere nomba mi, mo si fun un nigba to je pe adugbo kan naa la jo n gbe.

Ko pe ta a dele lo pe mi. O ni oun fee beere boya mo ti dele ni, mo ni mo ti dele. Latigba yen lo ti maa n pe mi lojoojumo sugbon emi ki i pe e nitori ko sowo lori foonu mi.” Nigba to n salaye bi isele to so o dero ahamo awon olopaa ohun se waye, Onyinyechi so pe, “Lojo Sannde to koja (ojo karun-un, osu karun-un, odun yii) ti mo sami ojoobi mi, mo loo ba anti kan sise nitosi ile wa.

Nigba ti mo ye ero ibanisoro mi wo ni mo ri i pe Ayo ati aburo mi ti pe mi. Mo si pe awon mejeeji pada.

“Ayo binu pe ki lo de ti oun n pe mi ti mi o gbe e. Mo ni ko ma binu, mi o si nile ni. Nibi ta a ti n soro ni mo ti so fun un pe oni ni ojoobi mi. O ni haa, o ye ka se ajoyo e o. Mo ni mi o we e, mo kan rora sami re lasan ni. O ni rara, a gbodo we e saa ni. O ni nibo ni mo wa, mo ni Ologuneru naa ni sugbon ki i se inu ile wa ni mo wa. O ni oun naa ko si nile sugbon ki n waa pade oun lorita Ologuneru, ki oun mu mi loo se faaji. Mo de orita yen ni nnkan bii aago meje ale. Mo ri i (Ayo) to jade lati ile oti kan nibe, emi ko si mo pe o ti muti yo.

“Nigba ta a de ile won, titi ni ilekun abawole wa. O waa mu mi gba ona enu ona eyinkule, mo ni sebi oju ile la gba wole lojo ti emi ati Funmbi jo wa. O ni ilekun abawole ti baje, leyin ti awon ba gba eyinkule wole la won sese maa n loo silekun iwaju lati inu ile. O silekun, o ni ki n wole, mo ni ita ti mo wa yii ti daa, ko je ki n jokoo sori simenti ti mo wa yen, nitori gbogbo inu ile lo sookun, ina toosi lo tan ta a fi n riran.

“O ni bawo ni mo se maa wa sile awon ti ma a waa jokoo sita. N ni mo ba wole. Mo jokoo sori aga, oun naa jokoo, o n se nnkan kan lori ero komputa alagbeeletan re. Nigba to ya lo pe iya e lori foonu. Nibe lo ti wo ile idana lo, o gbe ketu omi kan wa, o bu u fun mi, mo ni ko ma seyonu.

“Leyin yen lo tun dide to loo tilekun iwaju ile pa. Mo ni ki lo de to tilekun, ko da mi lohun, o kan jokoo si egbe mi ni. O ni o o mo nnkan to sele, mo fee fe e ni. Mo ro pe o fi n sere ni, mo ni se nnkan ta a waa se nile yin niyen. O ni oun ko ma fi sere. Bo se sun mo mi niyen, bee ni mo n gbo oorun oti lenu e. O ni oun ko ma fi sere o. Mo ni abi o muti yo ni? O ni oun ko muti, nnkan ti oun fe loun so yen. Mo ni o daa, emi ko fe o o. Ba mi silekun ki n maa ba temi lo. O ba ni mi o le lo sibi kankan, afi ti oun ba ba mi lasepo.≈ Omobinrin to pera e lomo bibi ilu Nkwele Ogidi, nipinle Anambra, yii te siwaju pe, “Mo be e titi sugbon gbogbo ebe mi ko wo o leti. Ka too wi ka too fo, o ti bo sokoto idi e sile. O ni se o ri mi bayii, se o mo pe ara mi ti wa lona. Mo ri i pe nnkan omokunrin re ti dide loooto, nigba yen ni mo ti mo pe mo ti wo wahala. Bi mo se sare dide niyen, o ba dide ti mi.

“Bi mo se sare lo sibi oju ferese niyen ti mo na orun sita ti mo pariwo pe e gba mi o. Bo se gba mi leti lati eyin niyen. O fa mi laso seyin. Bi mo se sa lo si apa ogiri lohun-un niyen, o tun waa ba mi, bi mo se n sa lo lo n le mi kiri inu ile.

“Nigba to ya lo loo mu obe nile idana. O ni ki n tete bo ara mi sile wooro ki oun too ka ookan de ori eewaa, bi bee ko, oun ko ni i fi obe owo oun won mi wo. Mo ba kunle, mo ba n be e. Mo ranti pe o ti so pe oun feran iya oun pupo, oun ki i si i fi oro re sere, n ni mo ba fi iya e be e. O ni wo o fi iyen sile jare.

“Mo tun fi Olorun be e, o ni haa, Olorun ke, emi ma ti fi Olorun sile tipe. Ogun ni mo gbagbo bayii. Wo o, aworan eye ta a gbe ko si ara ogiri yen, nnkan ti emi n sin bayii ni temi niyen. Nigba ti mo fi iya e be e ti ko gba, ti mo tun fi Olorun be e to saa fariga, mo so fun un pe mo n se nnkan osu lowo, o niyen ko se nnkan kan. O ni ki n je ki oun tete se nnkan ti oun fee se kiakia nitori ti awon ore oun ba de ba mi nibe, gbogbo won ni won maa ba mi sun lokookan karikari.

“Gbogbo bi mo se n be e yen, nise lo duro to saa n wo mi. Nigba to ya lo sa ina si siga. Nigba to fa a ku kekere lo ni, Wo o, ti siga to wa lowo mi yii ba fi jo tan ti o ko da mi lohun, nnkan ti ma a fi oju e ri ko ni i daa o. N lo ba tun bere si i ka ookan, eeji lo sori eewaa. Nigba to ka a de ori eejo ni mo tun kigbe, e gba mi o. Bo se di mi mu niyen to fee bo aso lorun mi. Sokoto penpe bii pata lasan ni mo wo lojo yen, mo wo ewu gbooro bii jalabia le e lori. O fi obe owo e sile ko le raaye bo aso mi, bi mo se mu un niyen ti mo bere si i fi i deruba a.

“Inu ookun la wa nigba yen nitori o ti fi toosi owo e naa sile nigba to fee bo aso lorun mi. Nibi ti mo ti n fi obe yen kaakiri bayii pe fi mi sile, fi mi sile ni mo gbo to so pe yee, o ti gun mi. Mo dide nile, mo bere si i gbon. Mo fi owo ra ile ki n fi le ri foonu mi. Mi o le pariwo pe awon eeyan lati waa gba mi sile mo nitori gbogbo ariwo ti mo n pa lataaro, ko seni to da mi lohun. Yeye ni Ayo n fi mi se, o ni se mi o mo pe oju oba ni won fi maa n wo awon laduugbo ni, o ni bi mo ba pariwo ju bee lo, ko seni to maa wo inu ile awon waa ba oun nitori ko seni to maa n fee gbena wo oju awon laduugbo yen. Iyen ni ko je ki n mo eni ti ma a pe.

“Mo sare loo so fun iya mi nile pe mo ti gun eeyan lobe. Awon naa pariwo pe haa, o jee je ka tete maa lo si ago olopaa. Ba a se loo so fun won ni tesan Ologuneru niyen. Awon olopaa tele mi de ile awon Ayo sugbon o ti ku ka too debe. Emi gan-an ko mo bi obe yen se gun un to, aaro ojo keji ni mo too ri i pe igba aya re ni obe gun.” Iwe Iroyin Yoruba gbo pe awon obi Ayo ti ko ara won sile, iya re ti n se abiyamo nile oko mi-in. Omokunrin eni odun mokandinlogun naa ko si gbe pelu eyikeyii ninu won. Inu ile okan ninu awon to je bii egbon fun un laduugbo lo n gbe bo tile je pe won ko tan rara.

Nigba to n fidi isele yii mule, okan ninu awon igbakeji oga agba awon olopaa nipinle Oyo, Ogbeni Dasuki Galadanchi, ti i se alamojuto eka iwadii labe ileese olopaa ipinle naa so pe awon agbofinro ti tese bo iwadii oro naa.

Gege bo se so, “Se e mo pe oku orun ki i ba araaye wijo. Awijare omobinrin yen nikan la gbo, ko si elerii kankan to le so boya loooto lomokunrin yen fee fipa ba a lo po tabi bee ko. Nitori naa, ko si nnkan ta a le se ju ka se iwadii ijinle lori isele yen lo. Mo si n fi i da gbogbo aye loju pe iwadii ododo la maa se lori isele yen pelu akoyawo gege bi oga agba awon olopaa lorile-ede yii, Muhammad Abubakar, se la a kale fun wa.” ACP Galadanchi fi kun un pe iwadii ti won ba se lo maa je kawon mo boya omobinrin to wa lahaamo olopaa n’Iyaganku, naa yoo foju bale-ejo tabi bee ko.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 13 @ 03:12:55 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"O Ti D'oju E Bayii O! Orebinrin Ayo Gun Un Pa N’Ibadan, Omobinrin Naa Lo Fe" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: