Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
[ Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere ]

·Ijoba Ipinle Osun Ti Ki Oselu Bo Eto-eko O - Awon Eeyan Iwo-Oorun Osun Ke Gbajar
·Awon Aare Agbaye N Se Idaro Iku Robert Mugabe, E Gbo Nnkan Ti Obasanjo So
·Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
·Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
·O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
·Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
·Nitori Bi Won Ko Se Rowo Osu Gba, Awon Osise Di Onibaara Nipinle Oyo
·Nitori Owo Osu, , Edet Be Ori Omo Oga e N'Ijebu Ife
·Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Awon Adigunjale Di Eru Jeje Siluu Ondo, Bi Won Ti N Fo Soobu Ni Won N Ja Okada G
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Taofeek Surdiq, Ondo

Awon Adigunjale Di Eru Jeje Siluu Ondo, Bi Won Ti N Fo Soobu Ni Won N Ja Okada Gba

Inu iberu-bojo lawon eeyan ilu Ondo wa bayii nitori bi awon ole se n ja alupupu gba lowo awon olokada ni gbogbo igba, bee ni won n ja soobu, ti won si tun n ka awon araadugbo mole loru lati gba gbogbo owo atawon nnkan ini olowo iyebiye lowo won.
Okada tawon adigunjale naa ti ja gba laarin ose meji seyin lowo awon eeyan to fi n sise se tabi awon ti won n lo o gege bii ohun irinse ti to mejo tabi ju bee lo. Igba mi-in wa tawon alo-kolohun-kigbe yii maa n se ose ninu adugbo, ti won yoo si ja soobu ko eru ibe sa lo, bee naa ni won maa n ji okada gbe nibi ti won ba gbe e si.Nitori idaamu tawon ole yii ko ba awon eeyan wonyi laarin ose meji seyin lo fa a ti adugbo kookan niluu naa fi n gbadura, ti won si n dana sun taya moto loru.
Gege bi iwadii oniroyin wa, l«Ojoru, Wesde, ose to koja yii ni awon odomokunrin meji kan tojo ori won ko ju odun metadinlogun lo pe olokada kan lagbegbe Oke-Odunwo, pe ko gbe awon lo sagbegbe kan ti won n pe ni Ajagbale, laduugbo Oka, niluu Ondo, pelu ileri pe awon yoo sanwo fun un to ba ti gbe awon debe, lai mo pe ogboju ole lawon odomokunrin meji ohun.

Sugbon oro naa ba eyin yo nigba ti olokada yii gbe won debi ti won n lo laarin igbo kekere kan, ti won si fa ibon agbelero yo si i, ti won si ni ko ko gbogbo owo to wa lapo re jade.

Leyin igba ti won gba owo naa tan ni won tun ni ko da oju bole, bi olokada yii si ti doju dele lawon omokunrin meji naa ti gbe okada ohun sa lo.

Iru isele to fara pe e leyii to tun sele lojo Isegun, Tusde, ose to koja yii, iyen lakooko tawon igaara-olosa fogbon tan odomokunrin kan toruko re n je Adewale Lamidi, to je okan lara awon olokada to wa laduugbo Yaba, niluu Ondo, ti won si fun un legberun kan naira pe ko loo se e wa nile-epo kan to wa nibe, ki omokunrin olokada naa too se owo de lawon ole ohun ti gbe alupupu e sa lo, niyen ba kawo leri.

Ninu ose to koja yii kan naa lawon atilaawi yii sose bii wakati merin gbako ninu adugbo kan ti won n pe ni Irewumi, lagbegbe Oke-Odunwo, eyi ti won se lojule-sojule. Awon nnkan asaraloge, owo ati dukia olowo iyebiye ni won gba lowo awon aladuugbo naa. Bakan naa lojo Aje, Monde, ose to koja, ni deede aago mefa irole niluu Ondo, niwaju ile-ejo giga to wa laduugbo Oka lawon odomokunrin meji kan ti pe olokada pe ko gbe awon lo saduugbo kan lagbegbe naa. Ka too seju peu, awon eni yii ti fa ibon ilewo yo, ni won ba yin in lu olokada naa lori. Loju-ese si ni olokada naa ti subu lule to ku, ki won too gbe okada e naa lo.

Lona mi-in ewe, ninu ose to koja yii naa lawon ole tun ji okada kan to je ti alaga egbe awon onimoto (RTEAN), Ogbeni Babatunde Soledayo, eyi ti won ni ki eni to n wa okada naa gbe awon lo saduugbo kan ti won n pe ni Velentino, nigba to ja awon arakunrin ohun sile lomokunrin kan jade si i pelu ibon to mu lowo pe ko fun oun ni kokoro alupupu naa. Logan ni olokada ti jowo kokoro yii sile, ti omokunrin ohun si gbe alupupu naa sa lo.

Nigba ti Iwe Iroyin Yoruba de ago olopaa meteeta to wa niluu Ondo lati fi oro wa awon oga ibe lenu wo lori awon isele wonyi, awon oga kookan to ba wa soro sugbon ti won ko fe ki won daruko won juwe isele ifipa gba okada lowo eni ati isele idigunjale to gbile ninu ilu naa lati bii ose meji seyin gege bii ohun to buru jai.

Lara awon olopaa yii seleri lati tubo sa ipa won lati mu awon to wa nidii isele naa. Bee ni won ni die lara awon ti won ja okada won gba ti waa fi to awon leti, won ni awon ti bere itopinpin lori awon isele naa.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 08 @ 16:43:58 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Awon Adigunjale Di Eru Jeje Siluu Ondo, Bi Won Ti N Fo Soobu Ni Won N Ja Okada G" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: