Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Madojutimi Ti Dojuti Awon Molebi E: Awon Omo Keekeekee Meji Lo Fipa Ba Lo Po Nil
 
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Madojutimi Ti Dojuti Awon Molebi E: Awon Omo Keekeekee Meji Lo Fipa Ba Lo Po Niluu Saki

Yoruba bo won ni oruko omo ni ijanu omo. Won a tun ni oruko ni i ro omo. Boya nitori iwonyi ni eni to pile oruko daradara kan, “Madojutimi≈ ti idile kan n je ni ilu Saki, nipinle Oyo, se se bee, sugbon okan ninu awon omo ti won bi sinu idile naa ti ko idoti ba oruko naa laipe yii, afaimo ni Madojutimi yii ko ti dojuti awon ebi e gidigidi.
Awon omodebinrin meji otooto ta a fi ojulowo oruko won bo won lasiiri lokunrin naa, Kazeem Madojutimi, ki mole, to fipa ba sun lona aibofin-mu.Eyi ti ko ju omo odun marun-un lo, Olabisi ni Kazeem koko ki mole lojo Abameta, Satide, ojo Kerin, osu karun-un, odun yii. Ije ana dun mo ehoro lenu, n ni jagunlabi ba tun ki omo mi-in, Bimbo, ti iyen je omoodun mefa mole lojo keji, iyen, ojo Aiku, Sannde, ojo Karunun, osu yii, o si fipa ba a lo po titi to fi fi kinni nla re da apa si omode naa labe.
Isu la gbo pe okunrin mekaniiki naa fi tan awon omo naa wo inu yara e, to si n ba won se ohun to lodi si ofin yii. Gege bi Iwe Iroyin Yoruba se gbo, bo tile je pe ko si eni to ka Kazeem mo ibi to ti n se awon omo olomo bi ose se e soju, sibe ojo naa lasiiri e tu nigba ti Iya Olabisi n we e, to si ri apa loju ara re kitikiti. Nigba ti iya yii bi omo e leere ohun to se e, o ni Booda Kasiimu ni.

Iya Bisi ati Kazeem n pariwo le ara won lori lowo, won ko ti i yanju e ti iya Bimbo tun fi da kun oran Kazeem, o lo se iru erekere to se pelu Olabisi pelu omo oun naa lanaa. O ni nise lokunrin naa ran omo oun ni omi mimu, nigba ti o si ra a de lo wo o mora, to si ba a sun. N ni won ba mu okunrin naa lo si aago olopaa tesan Saki.

Leyin iwadii pajawiri ti SP Sulaiman Baba ti i se oga olopaa tesan Saki atawon emewa e se lori isele naa ni won gbe ise to ku lori e le eka to n gbogun ti isele odaran laarin awon omode lowo fun iwadii siwaju si i. Lati ibe ni won si ti tun gbe oro naa lo si eka to n se iwadii esun odaran (SCID), ibe si lokunrin afurasi odaran naa wa titi di asiko ti a n ko iroyin yii jo.

Inu ile kan naa la gbo pe Kazeem atawon omode naa n gbe laduugbo Oke Aje, niluu Saki.

Won lo pe to ti maa n se bee, ti yoo tan awon omodebinrin adugbo wo yara ba sun. Iru iwa egbin yii naa la si gbo pe o hu nibi to n gbe tele ti won fi le e kuro laduugbo naa.

Kazeem funra e fidi e mule, o ni, “Lojo yen, mo pe omo yen pe ko waa lo ba mi ra omi wa, nigba to de, nibi ti mo ti fee maa ba a sun lo ti n ke, mo si fi i sile. Emi naa ko mo idi ti mo se feran lati maa ba awon omo kekere sun. Adua ti mo n gba ni pe ki Olorun dariji mi.’’ Lori isele to so o dero atimole yii, Kazeem to pera e leni odun mokandinlogbon so pe loooto loun jebi esun ti awon agbofinro tori e mu oun ti mole, o ni bo tile je pe Olabisi nikan loun ba sere egele, oun ko mo nipa oun ti Bimbo ati iya e n so rara.

Gege bo se so, ‘Mo n jeun lowo ni Olabisi de. Mo ni ko waa je iyooku. Nigba to wole, mo ni ko bo pata re, o si se bee. Mo waa fi ipara pa itan re mo ibi oju ara re. Ki i se pe mo fi tulaasi ki kinni bo o labe nitori mo mo pe omo yen kere, mo kan rora fi i ra a ni itan ni. Ki n kan saa fi to ato jade lasan naa ni mo se se e, mi o wole si i lara rara.’ Iya Olabisi, Abileko Rofiat Sefiu, salaye bi isele ohun se ya a lenu to, o ni inu ile loun wa nigba ti isele ohun waye. O ni oun gbo ti Kazeem pe Bisi to ran omo naa pe ko ba oun mu omi inu ora wa ti omo si mu un fun un, oun si ri i pe o fi isu to n je lowo le omo oun lowo, sugbon oun ko mo pe okunrin naa le dan iru iwa palapala bee wo pelu iru omo kekere bee.

Abileko Sefiu salaye pe leyin ti Bisi kuro lodo okunrin agbaaya naa lo se igbonse. O ni nibi ti oun ti n san idi fun un loun ti sakiyesi pe gbogbo abe re n yo boro fun ipara, eyi lo je ki oun ye abe re wo, ti oun si ri i bi gbogbo itan re se daranje, to si pon fun eje.

Obinrin naa te siwaju pe nigba ti oun bi omo oun leere lo salaye itu ti Kazeem fi i pa ninu yara e. O ni iyen lo mu ki awon sare gbe e lo sileewosan ko too di pe awon fi isele naa to awon olopaa leti.

Nigba to n fidi isele naa mule, alukoro fun ileese olopaa ipinle Oyo, DSP Olabisi Okuwobi-Ilobanafor, so pe ileese olopaa ti gbe Kazeem lo sile-ejo majisireeti ni Iyaganku, n’Ibadan, fun esun ifipa-ba-omode-lo-po, eyi to lodi si ofin orile-ede yii.

Ahamo awon olopaa la gbo pe ile-ejo pase pe ki won da okunrin afurasi odaran naa pada si nigba ti igbejo si n te siwaju.

DSP Ilobanafor waa gba awon obi nimoran lati maa mojuto awon omo won daadaa, paapaa awon omodebinrin won, nitori ki won ma baa ko sowo awon abani-laye-je okunrin.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 08 @ 17:16:05 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Madojutimi Ti Dojuti Awon Molebi E: Awon Omo Keekeekee Meji Lo Fipa Ba Lo Po Nil" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: