Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


E Gba Mi O, Aje Ni Iya Mi, Oogun Lo Fi Pe Mi Wa Lati Eko To Fi Fi Mi Loko
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Abayomi Akanni, Ogbomoso

E Gba Mi O, Aje Ni Iya Mi, Oogun Lo Fi Pe Mi Wa Lati Eko To Fi Fi Mi Loko

Bii eni wo sinima agbelewo lo ri loju gbogbo awon tisele naa soju won, topo si yanu sile nigba ti won gbo tiyawo ile kan to ti bimo meji, Arabinrin Victoria Ojetunde, so pe aje ni iya oun, o ni oogun lo fi fa oun wale lati ilu Eko, to si fi oun fun Arakunrin Job toun fe, sugbon ti ki i se oun lo lawon omo toun bi.
Ninu oro Victoria nigba to n ba Iwe Iroyin Yoruba soro, o ni latigba toun ti wa nileewe girama loun ati Arakunrin Idowu ti n fe ara awon, o ni ile ti okunrin yii n gbe loun ti mo Job to je alaga odo ni soosi awon nigba naa.Obinrin naa lodo iya kan toun gbe tele ni iya oun ti koko fidan han oun nipa bo se koyin oun ati iya naa si ara won, ti mama ohun si dojuti oun ni gbangba pe arungun omo loun, idi to si se so bee ni nitori aisan to maa n se oun ni gbogbo igba. Nibi gan-an lo loun ti pinnu pe oun yoo loo da gbale. Job lo lo ba oun rile, oun kowo fun un sugbon ko gba a, leyin eyi lo ba oun soro ife sugbon oun ko fun un, o si so pe bi oun ko ba gba lero, oun yoo gba ni tipatipa.
Sugbon nipa ifowo-sowo-po Job ati mama oun, oun pada fe e laimo. Iyaale ile yii ni ilu Eko ni oun n gbe tele, ti oun ko si mo igba ti oun ba ara oun l’Ogbomoso lai mu eru kankan dani taisan taisan. Boun se de lo si fa oun le okunrin naa lowo. Ninu osu kewaa, odun 2009, lo loun loyun fun Idowu niluu Eko, ko too di pe won segbeyawo apapandodo foun pelu Job ninu osu kin-in-ni, odun 2010.

Victoria so pe nigba ti iya oun ka lo so pe toun ba loogun ibile ti ko ba tete sise toun fe, nise loun yoo bo ara oun sihooho omoluabi fun odidi ojo meje. O ni bi ara oun ba ti tun ya ti oun n gbiyanju lati pada s’Ekoo ni Job yoo ba tun gba odo iya oun lo, toun ko si ni i ranti Eko mo titi toun fi bi akobi oun to n je Timileyin.

Obinrin yii te siwaju pe nigba toun setan lati bimo keji loun gba Eko lo, toun loun fee loo ki awon egbon oun, leyin toun loyun tan loun pada si Ogbomoso, ti Idowu si so pe koun ma gbagbe oruko toun so pe koun somo naa, iyen Paul ati Olamide, nnkan toun si so o niyen. O ni gilaasi, atike funfun pelu ororo alawo buluu ati ose dudu ni oko oun maa n lo to ba ti fee ba oun lajosepo koju oun too la. Sugbon ni kete toju oun la tan loun ti n ko o fun un.

Laaaro Ojoru, ojo kejo, osu karun-un, yii ti akoroyin lo si adugbo Osupa ti Iya Victoria to n je Iyabo Olariike n gbe, abileko naa so pe oun loun bi Victoria, o loun to ba wu oun loun le se fun un. O loun loun ran an lekoo, o si wu oun loun fa a wale, sugbon ki i se oogun loun fi fa a, oun lo sori oke ti i ni. O ni Job loun fi omo oun fun gege bii oko re, oun ko mo eni to n je Idowu ri, gbogbo eeyan oun lo si fowo sigbeyawo toun se fun un.

Ninu oro Arakunrin Job, o loun fe Victoria nisu loka ni, oun loun ran an nileewe girama, leyin to pari loun da a lokoowo, pelu atileyin iya re loun si fi ri i fe. O lawon ni idaduro die ki awon too bimo akobi awon, bakan naa ni pe banki kan loun ti maa n yawo fun un koja re ma baa run laimo pe odo Idowu lo maa n kowo oogun oju oun lo l’Ekoo. Ojo akoko to lowo palaba re segi loun ka a mo ile awon okunrin naa, toun si fo o leti karakara, ki iya iyawo oun too loo kilo fun Idowu ati iya re pe komo re o so ara re ko ma le omo oun kuro nidii eru re.

Nipa ti gilaasi, atike, to fi mo ororo ati ose dudu tiyawo oun pate fun akoroyin wa, okunrin yii ni oun ko mo nnkan kan nipa re.

Ninu oro Ogbeni Idowu, o loun le fi gbogbo enu so o pe oun loun lomo meji ti Victoria bi nitori pe oruko oun lo wa lori iwe igbebi ati ti itoju oyun, ati pe oruko toun fi ranse si iya won lo somo eleekeji (Paul Olamide).

Ose to n bo ni won yoo loo se ayewo eje lati le fidi eni to lomo mule ninu Job ati Idowu.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 08 @ 17:21:45 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"E Gba Mi O, Aje Ni Iya Mi, Oogun Lo Fi Pe Mi Wa Lati Eko To Fi Fi Mi Loko" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: